Ohun ti mo fẹ́ràn nipa Ìsimi Iparí Ọ̀sẹ̀ – What I love about the Weekend Break
Ni ọjọ́ Ẹti, ọjọ́ karun ti a ti bẹ̀rẹ̀ ilé-iwé ni ọ̀sẹ̀, inú mi ma ń dùn nitori ilé-iwé ti pari ni agogo kan ọ̀sán, ti ìsimi bẹ̀rẹ̀. Mo fẹ́ràn ìsimi ipari ọ̀sẹ̀ nitori mo ma nri àwọn òbí mi....
View Article“BÍ ỌMỌDÉ BÁ ṢUBÚ Á WO IWÁJÚ…”: “IF A CHILD FALLS HE/SHE LOOKS FORWARD…”
BÍ ỌMỌDÉ BÁ ṢUBÚ Á WO IWÁJÚ, BÍ ÀGBÀ BÁ ṢUBÚ Á WO Ẹ̀HÌN Òwe Yorùbá yi wúlò lati juwe òye àgbàlagbà lati wo ẹ̀hìn fún ẹ̀kọ́ nínú ìrírí tó ti kọjá lati yanjú ọ̀ràn tó ṣòro nígbàtí ọmọdé tí kò rí irú...
View Article“Ohun ti ó ntán lọdún eégún”– Kérésìmesì ọdún Ẹgbã-lé-mẹ́rìnlà ti...
Bàbá-Kérésì – Father Christmas Ìwà alajẹtan ti bori iránti ohun ti Kérésìmesì wà fún. Ọ̀pọ̀ kò ti ẹ̀ ránti pé iránti ọjọ́ ibi Jesu ni Ìjọba ṣe fún ará ilú ni ọjọ́ ìsimi ni ọjọ́...
View ArticleÒrìṣà òkè jẹ́ ki npé meji obinrin kò dé inú – Àṣà Ìkó-binrin-jọ:...
Ọkùnrin kan pẹ̀lú iyàwó púpọ̀ wọ́pọ̀ ni ilẹ̀ Yorùbá. Àwọn obinrin ti ó bá́ fẹ́ ọkọ kan naa ni à ńpè ni “Orogún”. Ìwà oriṣiriṣi ni ó ma ńhàn ni ilé olórogún, àrù̀n iyàwó ti...
View ArticleABD YORÙBÁ – Yoruba Alphabet
“ABD”, ìbẹ̀rẹ̀ iwé kikà ni èdè Yorùbá – Yoruba Alphabets “ABD” is the beginning of Yoruba education. Bi ọmọdé bá bẹrẹ ilé-iwé alakọbẹrẹ, èdè Yorùbá ni wọn fi nkọ ọmọ ni ilé-iwé lati...
View ArticleÀròkọ ni Èdè Yorùbá – Essay in Yoruba Language
Idi ti a fi bẹ̀rẹ̀ si kọ iwé ni èdè Yorùbá lóri ayélujára ni lati jẹ́ ki ẹnikẹ́ni ti ó fẹ́ mọ̀ nipa èdè àti àṣà Yorùbá ri ìrànlọ́wọ́ lóri ayélujára. A ò bẹ̀rẹ̀ si kọ àwọn àròkọ ni...
View ArticleẸ̀rù ló sọ ọmọ Ẹkùn di Ológbò/Ológìní tó fi di ”Ẹran-àmúsìn –Ọdẹ...
Ni igbà àtijọ́, ẹranko ti wọn pè ni Ẹkùn jẹ alágbára ẹranko, bẹni Kìnìún si jẹ́ alágbára ẹranko. Bi Kìnìún ti lágbára tó ninú igbó, bi ó bá bú ramúramù, ohun gbogbo ninú igbó á...
View ArticleẸ̀YÀ ARA – ÈJÌKÁ DÉ ẸSẸ̀: PARTS OF THE BODY – SHOULDERS TO TOES
Download: Parts of the body in Yoruba – shoulders to toes You can also download the mp3 by right clicking here: Parts of the body in Yoruba – shoulders to toes (mp3) Ẹ̀YÀ ARA PARTS OF THE BODY...
View ArticleÒjò nrọ̀ si kòtò, gegele mbinú – The rain is filling up the gully to the...
Ójò rẹpẹtẹ – Heavy rain Bi inú ọpọ ti ndùn, ni inú ẹlòmíràn mbàjẹ́ ni àsikò òjò. Yorùbá ni orin fún igbà ti kò ba si òjò, igbà ti òjò bá ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ si rọ̀, tàbi ti ó bá...
View Article“Ohun ti ajá mã jẹ, Èṣù á ṣẽ”: “What the dog will eat, the Devil will...
Yorùbá ma nṣe rúbọ Èṣù nigba gbogbo ki ẹ̀sìn ìgbàgbọ́ tó gbalẹ̀. Ounjẹ ni wọn ma fi ṣè rúbo ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà. Irú ounjẹ yi ni Yorùbá npè ni “ẹbọ”. Ìta gbangba ni wọn ma ngbe irú...
View ArticleBi ọmọ ò jọ ṣòkòtò á jọ kíjìpá: Ibáṣe pọ Idilé Yorùbá – If a child...
Bàbá, iyá àti ọmọ ni wọn mọ si Idilé ni Òkè-òkun ṣùgbọ́n ni ilẹ̀ Yorùbá kò ri bẹ́ ẹ̀, nitori ẹbi Eg bàbá, ẹ̀gbọ́n àti àbúrò ẹni, ọmọ, ọkọ àti aya wọn ni a mọ̀ si Idilé. Yorùbá...
View ArticleỌjọ́ ayọ̀ lọjọ́ òni, America yan Kamala Harris Obinrin àkọ́kọ́ si ipò...
Ọjọ́ keje, oṣù kọkanla ọdún Ẹgbàá, ìròyìn kàn pé Joe Biden àti Igbakeji rẹ Kamala Harris ni wọ́n yàn si ipò Àrẹ kẹrindinlaadọta ti yio gun ori oyè lati Ogún ọjọ́, oṣù kini ọdún...
View ArticleÀmì – Yoruba Accent
Àmì – ṣe pàtàkì ni èdè Yorùbá nitori lai si àmì, àṣìwí tàbi àṣìsọ á pọ̀. Ọ̀rọ̀ kan ni èdè Yorùbá lè ni itumọ rẹpẹtẹ, lai si àmì yio ṣòro lati mọ ìyàtọ. Àmì jẹ ki èdè Yorùbá...
View ArticleGbígbé Ìṣe Yorùbá Jáde Lórí Ẹ̀rọ Ayélujára – Publishing Yoruba...
Àwọn ọ̀nà oríṣiríṣi ni a le fi gbé àṣà Yorùbá àti lílò iṣẹ́ ọ̀nà ni ilẹ̀ Yorùbá jáde lórí ẹ̀rọ-alántakùn. Onírúurú ìṣe ọ̀nà ni a le fi sí ẹ̀rọ-alántakùn bí i sinimá,...
View Article“Ẹrù fún Ìgbéyàwó Ìbílẹ̀”–“Traditional Bridal List”
Apá Kini – Part One Gifts at a modern Yoruba Traditional wedding — courtesy of @theYorubablog Ìnáwó nla ni ìgbéyàwó ìbílẹ̀, ṣùgbọ́n gẹ́gẹ́ bi òwe Yorùbá “Bi owó ti mọ ni oògùn nmọ”, bi agbára ọkọ...
View ArticleÌGBÉYÀWÓ ÌBÍLẸ̀ – TRADITIONAL MARRIAGE
Gifts at a modern Yoruba Traditional wedding — courtesy of @theYorubablog Ìgbéyàwó ìbíle ní Ilẹ̀ Yorùbá jẹ́ àsìkò ti ẹbí ọkọ àti ì̀yàwó ma nparapọ. Ìyàwó ṣíṣe ni ilẹ̀ Yorùbá kò pin sí ãrin ọkọ àti...
View Article“Bi a bá tori ẹni burúkú fọ́jú, a kò ni ri ojú ri ẹni rere” – “If one...
Kò si ilú, ẹ̀yà tàbi àwọ̀ ti kò ni ẹni burúkú tàbi ẹni rere. Àti ẹni burúkú àti ẹni rere ló wà ninú ẹbi, ilú, àti gbogbo ẹ̀yà àgbáyé ninú èniyàn dúdú àti funfun, ọkùnrin,...
View Article“Gèlè ò dùn bi ká mọ̀ ọ́ wé, ká mọ̀ ọ́ wé, kò tó kó yẹni”: “Head tie is not...
Aṣọ Yorùbá, ìró àti bùbá kò pé lai si gèlè. Gèlè oriṣiriṣi ló wà̀, a lè lo gèlè aṣọ ìbílẹ̀ bi: aṣọ òfi/òkè, àdìrẹ, tàbi ki á yọ gèlè lára aṣọ. Ọpọlọpọ gèle ìgbàlódé wá lati òkè òkun. Ìmúra obinrin...
View ArticleÌtàn iyàwó ti ó fi ẹ̀mi òkùnkùn pa iyá-ọkọ: Ẹni a fẹ́ la mọ̀, a ò...
Ìtàn ti ó wọ́pọ̀ ni, bi iyá-ọkọ ti burú lai ri ìtàn iyá-ọkọ ti ó dára sọ. Eyi dákún àṣà burúkú ti ó gbòde láyé òde òni, nipa àwọn ọmọge ti ó ti tó wọ ilé-ọkọ tàbi obinrin...
View ArticleÀàntéré ọmọ Òrìṣà-Omi – “Ọmọ o láyọ̀lé, ẹni ọmọ sin lo bimọ”: Aantere...
Yorùbá ka ọmọ si ọlá àti iyì ti yio tọ́jú ìyá àti bàbá lọ́jọ́ alẹ́. Eyi han ni orúkọ ti Yorùbá nsọ ọmọ bi: Ọmọlọlá, Ọmọniyi, Ọmọlẹ̀yẹ, Ọmọ́yẹmi, Ọlọ́mọ́là, Ọlọ́mọlólayé, Ọmọdunni,...
View Article