Quantcast
Channel: The Yoruba Blog
Viewing all articles
Browse latest Browse all 9856

Ijẹbu lo ni Ìfọ́kọrẹ́/Ìkọ́kọrẹ́ gbogbo Yorùbá ló ni Ọ̀jọ̀jọ̀ – Water Yam Pottage is exclusive to Ijebu, fried water yam fritters belongs to all Yoruba.Originally Posted on October 6, 2015, last updated on October 6, 2015 and reposted on September 8, 2019

$
0
0

Ẹ ṣe àyẹ̀wò bi a ti ńṣe Ọ̀jọ̀jọ̀ lójú iwé yi.

Fọ Iṣu Ewùrà kan
Bẹ ewùrà yi
Rin iṣu yi (pẹ̀lú pãnu ti a dálu lati fi rin gãri, ilá tàbi ewùrà)
Po iyọ̀ àti iyọ̀ igbàlódé, ata gigún tàbi rẹ́ atarodo tútù, rin tàbi rẹ àlùbọ́sà si ewùrà rí-rin yi
Ti ó ba ki, fi omi diẹ si lati po gbogbo ẹ pọ
Gbe epo tàbi òróró kaná,
Bi ó bá ti gbóná, a lè fi ṣibi tàbi ọwọ́ da ewùrà ri-rin ti a ti pò pẹ̀lú èlò́ yi si inú epo to gbóná lati din
Wa kuro bi o ba ti jina.

ENGLISH TRANSLATION

Check out how to prepare Fried Water Yam Fritters on this page.

Wash the water yam,
Peel it,
Grate the water yam (with aluminium grater that can also
be used to grate Cassava, okra or water yam),
Mix with salt and seasoning, dry pepper or cut habanero,
grate or cut onions into the grated water yam,
If the grated water yam is too thick, add a little water to mix all together
Heat oil,
Cut with spoon or hand the mixed grated yam in small balls into the heated oil to fry
Remove the fried water yam fritters when cooked.

Originally posted 2015-10-06 19:27:40. Republished by Blog Post Promoter


Viewing all articles
Browse latest Browse all 9856

Trending Articles