Quantcast
Channel: The Yoruba Blog
Viewing all articles
Browse latest Browse all 9856

Àwòrán àti pípè orúkọ Èlò Ọbẹ̀ Yorùbá – Pictures and pronunciation of ingredients for Yoruba Soup/Stew/SauceOriginally Posted on August 1, 2014, last updated on April 8, 2017 and reposted on April 26, 2019

$
0
0

Àwọn èlò ọbẹ̀ Yorùbá, ẹni ti ó bá mọ ọbẹ̀ se, yio mọ èlò ọbẹ̀ ti ohun yio ra àti bi yio ti se, ṣùgbọ́n ẹni ti kò mọ ọbẹ̀ se, lè lo owó ai mọye lati se ọbẹ̀, ki ọbẹ̀ rẹ má dùn.  Fún àwọn ti ó ńgbé ni Òkè-Òkun, ọ̀pọ̀lọpọ̀ èlò yi ni a lè ri rà ni àyiká.  Ẹṣe àyẹ̀wò èlòọbẹ̀ àti pípè rẹ ni ojú ewé yi.

ENGLISH TRANSLATION

Yoruba Soup/Stew/Sauce ingredients, for those who know how to prepare it, they know the type of ingredients to buy and combine for cooking, but for bad cooks, he/she can spend lots of amount to cook yet the soup/stew/sauce may be tasteless.  For those living abroad, many of these ingredients can be sourced locally.  Check out list and pronunciation of these ingredients on this page.

 

View more presentations or Upload your own.

Originally posted 2014-08-01 18:26:06. Republished by Blog Post Promoter


Viewing all articles
Browse latest Browse all 9856

Trending Articles