“Ilé là ńwò ká tó sọmọ lórúkọ” – Orúkọ ẹni ni ìfihàn ẹni: One...
Ọpọlọpọ ọmọ Yorùbá ti bẹ̀rẹ̀ si tijú lati jẹ orúkọ ti òbí fi èdè Yorùbá sọ wọn. Èyi tó bá tún gba lati jẹ orúkọ Yorùbá á tún bã jẹ ni kikọ tàbi ni pipè. Èwo ni ká kọ “Bayọ ni Bayor, Fẹmi...
View ArticleỌba titun, Ọọni Ifẹ̀ Kọkànlélaadọta gba Adé – The new Monarch, Ooni of Ife...
Ọọni Ifẹ̀ Kọkànlélaadọta gba Adé – Ooni of Ife Oba Enitan Ogunwusi after receiving the AARE Crown from the Olojudo of Ido land on Monday PHOTOS BY Dare Fasub Ilé-Ifẹ̀ tàbi Ifẹ̀ jẹ ilú àtijọ́ ti...
View ArticleWelcome to the Yoruba Blog…
The home of all things Yoruba… news, commentary, proverbs, food. Keeping the Yoruba culture alive. Originally posted 2013-01-24 21:03:41. Republished by Blog Post Promoter
View ArticleYí Yára bi Ojú-ọjọ́ ti nyí padà nitori Èérí Àyíká – Effect of...
Ẹlẹkọ-ìjìnlẹ̀ ṣe àkiyesi pe enia ndá kún yí yára bi ojú-ọjọ́ ti nyi padà nitori èérí-àyíká. Ojú-ọjọ́ ti nyí padà lati ìgbà ti aláyé ti dá ayé, ṣùgbọ́n àyípadà ojú-ọjọ́ ni ayé...
View Article“Olóri Ẹbi, Baba Bùkátà” – “Headship of a Family is the Father of...
Olóri Ẹbi – Head of the Family connotes responsibiliies. Courtesy: @theyorubablog Olóri Ẹbi jẹ àkọ́bi ọkùnrin ni idilé. Bi àkọ́bi bá kú, ọkùnrin ti ó bá tẹ̀le yio bọ si ipò. Iṣẹ́ olóri...
View ArticleÀwòrán àti pi pè orúkọ ẹ̀yà ara lati ori dé ọrùn – Pictures and...
Download: Parts of the body in Yoruba – head to neck You can also download the Parts of the body in Yoruba by right clicking this link: Parts of the body in Yoruba – head to neck (mp3) ORÍ DÉ ỌRÙN...
View Article“A kì í fi Oníjà sílẹ̀ ká gbájúmọ́ alápepe – Pí pa Àjòjì ni Gúsù...
Pí pa Àjòjì ni Gúsù ilẹ̀ Aláwọ̀-dúdú – South Africa’s xenophobic attacks Òwe Yorùbá kan sọ pé “Amúkun, ẹrù ẹ́ wọ́, ó ni ẹ̃ wò ìsàlẹ̀”. Òwe yi ṣe é lò lati ṣe àyẹ̀wò ìṣẹ̀lẹ̀ pí pa...
View Article“Ẹsẹ̀ yá ju mọ́tọ̀ (ọkọ̀) ara ló nfàbò sí” – ohun ìrìn-àjò ni èdè Yorùbá:...
Ni ayé àtijọ́ ẹsẹ̀ ni gbogbo èrò ma nlo lati rin lati ìlú kan si keji nigbati ọkọ̀ ìgbà̀lódé kò ti wọpọ. Ilé Ọba àti Ìjòyè ni a ti le ri ẹṣin nitori ẹṣin kò lè rin ninu igbó kìjikìji ti o yi ilẹ̀...
View ArticleBÍBẸ̀ ÈKÓ WÒ FÚN Ọ̀SẸ̀ KAN (ỌJỌ́ KEJÌ) – Visiting Lagos for a Week (Day 2)
Download: A conversation in Yoruba (Day 2) You can also download the Yoruba alphabets by right clicking this link: A conversation in Yoruba – Day 2(mp3) ỌJỌ́ KEJÌ – DAY TWO ONÍLÉ (HOST OR HOSTESS)...
View ArticleORÚKỌ ỌJỌ́: Days of the Week in Yoruba
Below are the Yoruba days of the week. Of course it is worth noting that very few native Yoruba speakers use these words in conversation. SUNDAY ÀÌKÚ MONDAY...
View Article“A ki mọ́ ọkọ ọmọ, ki a tún mọ àlè rẹ” –“One does not acknowledge one’s...
Igbéyàwó ibilẹ̀ – Traditional marriage Ni ayé àtijọ́, wọn ma ńfi obinrin fún ọkọ ni, ṣùgbọ́n ni ayé òde òni, obinrin á mú̀ àfẹ́sọ́nà lati fi hàn òbi, nitori Yorùbá gba ọmọ obinrin ni...
View ArticleÀjùmòbí kò kan tãnu… Same parentage does not compel compassion…
Same parentage does not compel compassion. Òwe Yorùbá ní “Àjùmòbí kò kan tãnu, ẹni Olúwa bá rán síni ló nṣeni lõre”. Òwe yi wúlò lati gba àwọn ènìà tí o gbójúlé ẹbí níyànjú. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ rò wípé ẹ̀tọ́...
View ArticleNi Iránti Bàbá Ẹgbẹ́ Òṣèré Nigeria: Olóògbé Olóyè Hubert Adédèji...
Ẹbi, ará, iránṣẹ́ Ìjọba àti àwọn ọmọ Olóògbé Olóyè Hubert Adédèji Ogunde pé jọ ni ọjọ́ kẹrinlélógún oṣù kẹrin ọdún Ẹgbãlemẹ̃dógún, ni ilú Ìjẹ̀bú Ọ̀sọ̀sà ti ipinlẹ̀ Ògùn lati...
View Article“Iṣẹ́ ajé, sọ ọmọ nù bí òkò” –“Working for survival throws away the child...
Ọjọ́ ti pẹ́ ti Yorùbá ti ńkúrò ni ilú kan si ilú keji, yálà fún ọrọ̀ ajé tàbi fún ẹ̀kọ-kikọ́. Ni ayé àtijọ́, ọjọ́ pípẹ́ ni wọn fi ńrin irin-àjò nitori irin ti ọkọ̀ òfúrufú lè...
View Article“A ki i jẹ Igún, a ki i fi Ìyẹ́ Igún rinti: Ẹnu Ayé Lẹbọ” –“It is...
Ohun ti o jẹ èèwọ̀ tàbi òfin ni ilú kan le ma jẹ èèwọ̀/òfin ni ilú miran ṣùgbọ́n bi èniyàn bá dé ilú, ó yẹ ki ó bọ̀wọ̀ fún àṣà àti òfin ilú. Bi èniyàn bá ṣe nkan èèwọ̀, ó...
View Article“Ìtàn bi Ìjàpá ti fa Àkóbá fún Ọ̀bọ: Ẹ Ṣọ́ra fún Ọ̀rẹ́ Burúkú”–...
Ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ itàn Yorùbá, Ìjàpá jẹ ọ̀lẹ, òbùrẹ́wà, kò tóbi tó àwọn ẹranko yoku, ṣùgbọ́n ó ni ọgbọ́n àrékérekè ti ó fi ngbé ilé ayé. Ò̀we Yorùbá sọ wi pé, “Iwà jọ iwà, ni...
View Article“Ọ̀run ńyabọ̀, ki ṣé ọ̀rọ̀ ẹnìkan”: “The sky is falling, is not a matter...
Ọ̀run ńyabọ̀ – the sky is falling. Courtesy: @theyroubablog Òwe Yorùbá yi ṣe gba àwọn ti o nbẹ̀rù nigba gbogbo níyànjú wípé ó yẹ ki èniyàn fara balẹ̀ lati ṣe iwadi ohun ti ó fẹ́ ṣẹlẹ̀ ki ó tó “kú sílẹ̀...
View ArticleWi wé Gèlè Ìgbàlódé – How to tie Modern Head Scarfs
Originally posted 2015-07-07 19:41:40. Republished by Blog Post Promoter
View ArticleObinrin kò ṣe e jánípò si ìdí Àdìrò nikan, Obinrin ló ni gbogbo Ilé –...
Ìtàn fi yé wa wi pé Yorùbá ka ọ̀rọ̀ obinrin si ni àṣà Yorùbá bi ó ti ẹ jẹ wi pé obinrin ki jẹ Ọba nitori ni àṣà ilú, ọkunrin ló njẹ olóri. Obinrin kò pọ̀ ni ipò agbára. Àwọn...
View Article“Ìmọ́tótó borí àrùn mọ́lẹ̀, bi ọyẹ́ ti ḿborí ooru” –“Cleanliness...
http://www.theyorubablog.com/wp-content/uploads/2014/07/Imototo.wav Ìmọ́tótó borí àrùn mọlẹ̀, bọ́yẹ́ ti ḿborí ooru Àrùn ìwọ̀sí tinú ẹ̀gbin là wá Iná ni ḿborí aṣọ ẹlẹ́gbin Ni ayé àtijọ́...
View Article