Orukọ́ Ẹranko àti Àwòrán – Yoruba Names of Animals and pictures
Originally posted 2013-06-21 22:30:27. Republished by Blog Post Promoter
View Article“Ori ló mọ iṣẹ́ àṣe là”: Ògbójú-ọdẹ di Adẹmu fún Ará-Ọ̀run –“Destiny...
Ọkunrin kan wa láyé àtijọ́, Ògbójú-ọdẹ ni, ṣùgbọ́n bi ó ti pa ẹran tó, kò fi dá nkan ṣe. Ọ̀pọ̀ igbà, ki ri ẹran ti ó bá pa tà, o ma ńpin fún ará ilú ni. Nigbati kò ri ẹran pa mọ́,...
View Article“Ni Ayé òde òni, njẹ́ ó yẹ ki a pọ́n Àṣà fi fẹ́ Iyàwó púpọ̀ lé ni...
Ni igbà àtijọ́, oníyàwó kan kò wọ́pọ̀ nitori iṣẹ́ Àgbẹ̀. Àṣà fi fẹ́ iyàwó púpọ̀ ṣe kókó nitori bibi ọmọ púpọ̀ pàtàki ọmọ ọkùnrin fún irànlọ́wọ́ iṣẹ́-oko. Fi fẹ̀ iyàwó púpọ̀ kò...
View Article“Ẹ̀gẹ́ ò lẹ́wà; lásán ló fara wé Iṣu” – “Cassava has no attraction, it...
Ẹ̀gẹ́/Gbaguda/Pákí fi ara jọ Iṣu nitori àwọn mejeeji jẹ oúnjẹ ti ó wọ́pọ̀ ni ilẹ̀ Yorùbá ti wọn ńkọ ebè fún lati gbin. Wọn ma nwa wọn lati inú ebè ti wọn bá ti gbó, wọn ni eèpo ti wọn ma...
View ArticleOunjẹ Yorùbá: Yoruba Food
Ẹ GBA OUNJẸ YORÙBÁ LÀ: SAVE YORÙBÁ: SAVE YORUBA FOOD Ọpọlọpọ oriṣiriṣi ounjẹ Yorùbá nparẹ lọ, nípàtàkì larin awọn to ngbe ìlú nla. Òwe Yorùbá ni “Ki àgbàdo to de ilẹ aye, adíyẹ njẹ, adíyẹ nmu”....
View Article“À ì sí Iná Mọ̀nà-mọ́ná àti Epo Ọkọ̀ bá Onílé pẹ̀lú Àlejò”: –...
Ki gbogbo Nigeria tó gba ominira ni àwọn Òṣèlú lábẹ́ olùdari Olóyè Ọbáfẹ́mi Awolọwọ ti fi owó kòkó àti iṣẹ́-àgbẹ̀ dá nkan ṣe fún gbogbo ilẹ̀ Yorùbá. Yorùbá jẹ èrè àwọn ohun...
View ArticleÌJÀPÁ JẸ ÈRÈ AIGBỌRAN ÀTI ÌWÀ Ọ̀KANJÚÀ: The Tortoise is Punished for not...
ÌJÀPÁ/Àjàpá JẸ ÈRÈ AIGBỌRAN ÀTI ÌWÀ Ọ̀KANJÚÀ: THE RESULT OF DISOBEDIENCE AND GREED The tragic Tortoise — having eaten food made for his wife by the Herbalist — there really should have been a warning...
View Article“BÍ ỌMỌDÉ BÁ ṢUBÚ Á WO IWÁJÚ…”: “IF A CHILD FALLS HE/SHE LOOKS FORWARD…”
BÍ ỌMỌDÉ BÁ ṢUBÚ Á WO IWÁJÚ, BÍ ÀGBÀ BÁ ṢUBÚ Á WO Ẹ̀HÌN Òwe Yorùbá yi wúlò lati juwe òye àgbàlagbà lati wo ẹ̀hìn fún ẹ̀kọ́ nínú ìrírí tó ti kọjá lati yanjú ọ̀ràn tó ṣòro nígbàtí ọmọdé tí kò rí irú...
View Article“BÍ A TI NṢE NI ILÉ WA…”: MICHELLE OBAMA’S DRESSING AT OSCAR 2013
Image is from MSNBC (http://tv.msnbc.com/2013/02/25/a-cover-up-by-the-iranian-press-michelle-obama-has-no-right-to-bare-arms/) They covered the story on the Iranian Press Agency that found Michelle...
View ArticleÌránti Aadọta Ọdún ti Ọ̀gágun Adékúnlé Fájuyi fi ara rẹ ji fún...
Yorùbá fẹ́ràn àlejò púpọ̀. Ìwà ti ọmọ ilú lè hù ti yio fa ibinú, bi àlejò bá hu irú ìwà bẹ́ ẹ̀, wọn yio ni àlejò ni, ki wọn fori ji i. Òwe Yorùbá ti ó sọ wi pé “Ojú àlejò...
View Article“Ọ̀rẹ́ dani kò tó pọ́n, abínibí/ẹbi a má dani” –“It is not worth dwelling...
Kò si ibi ti ẹ̀tàn tàbi ká dani kò ti lè wá. Ẹni ti ó bá ni iwà burúkú bi: ojúkòkòrò, ìlara àti ìmọ-tara-ẹni nikan, lè dani tàbi tan-nijẹ. Ọmọ lè tan bàbá tàbi ìyá, ìyá tàbi...
View ArticleÀìnítìjú lọba gbogbo Àlébù: Shamelessness is the king of all Vices
Ìjàpá ọkọ Yáníbo – Tortoise the husband of Yanibo Gbogbo Ẹranko – Group of Animals Gbogbo Ẹranko (Ajá, Àmọ̀tẹ́kùn, Ẹkùn, Kìnìún, Ọ̀bọ, Akátá, Ológbò, Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, Ìjàpá/Àjàpá àti bẹ̃bẹ lọ) kó ara jọ...
View Article“Gèlè ò dùn bi ká mọ̀ ọ́ wé, ká mọ̀ ọ́ wé, kò tó kó yẹni”: “Head tie is not...
Aṣọ Yorùbá, ìró àti bùbá kò pé lai si gèlè. Gèlè oriṣiriṣi ló wà̀, a lè lo gèlè aṣọ ìbílẹ̀ bi: aṣọ òfi/òkè, àdìrẹ, tàbi ki á yọ gèlè lára aṣọ. Ọpọlọpọ gèle ìgbàlódé wá lati òkè òkun. Ìmúra obinrin...
View ArticleATỌ́NÀ LÉDÈ YORÙBÁ – Cardinal Directions in Yoruba
A compass showing the poles in Yoruba language. The image is courtesy of @theyorubablog Originally posted 2013-04-16 19:01:07. Republished by Blog Post Promoter
View ArticleÌtàn Yorùbá bi Àdán ti di “Ko ṣeku, kò ṣẹyẹ” – Yoruba Folklore on how the Bat...
Àdán fò lọ bá ẹyẹ – Bat flew to join the birds @theyorubablog Ìtàn sọ wí pé eku ni àdán tẹ́lẹ̀ ki ìjà nla tó bẹ́ sílẹ̀ laarin eku àti ẹyẹ. Àdán rò wípé àwọn ẹyẹ fẹ́ bori, nitorina o fo lati lọ darapọ̀...
View ArticleBi ọmọ ò jọ ṣòkòtò á jọ kíjìpá: Ibáṣe pọ Idilé Yorùbá – If a child...
Bàbá, iyá àti ọmọ ni wọn mọ si Idilé ni Òkè-òkun ṣùgbọ́n ni ilẹ̀ Yorùbá kò ri bẹ́ ẹ̀, nitori ẹbi Eg bàbá, ẹ̀gbọ́n àti àbúrò ẹni, ọmọ, ọkọ àti aya wọn ni a mọ̀ si Idilé. Yorùbá...
View Article“Àbíkú sọ Olóògùn di èké” – “Child mortality mis-portray the...
Ìgbàgbọ́ Yorùbá yàtọ̀ si ohun ti àwọn Ẹlẹko-Ijinlẹ fi hàn ni ayé òde òni. Ni igbà àtijọ́, bi obinrin/iyàwó bá bi ọmọ, ti ó kú ni ikókó tàbi ki ó tó gba àbúrò, ọmọ ti wọn bá...
View Article“Bi a bà jẹ̀kọ à dári ji Ewé”: À-lò-tún-lò – “After eating the corn...
Ewé iran – Organic food wrapping leaves. Courtesy: @theyorubablog Ki ariwo à-lò-tún-lò tó gbòde ni aiyé òde òni nipa àti dáàbò bo àyíká ni Yorùbá ti ńlo à-lò-tún-lò pàtàki li...
View Article“Olóri Ẹbi, Baba Bùkátà” – “Headship of a Family is the Father of...
Olóri Ẹbi – Head of the Family connotes responsibiliies. Courtesy: @theyorubablog Olóri Ẹbi jẹ àkọ́bi ọkùnrin ni idilé. Bi àkọ́bi bá kú, ọkùnrin ti ó bá tẹ̀le yio bọ si ipò. Iṣẹ́ olóri...
View ArticleẸ̀kọ́-ìṣirò ni èdè Yorùbá – Simple Arithmetic in Yoruba Language
Yorùbá ni bi wọn ti ma nṣe ìṣirò ki wọn tó bẹ̀rẹ̀ si ka ni èdè Gẹ̀ẹ́sì. Akọ̀wé yi kọ ìṣirò ki ó tó bẹ̀rẹ̀ ilé-ìwé lọdọ ìyá rẹ̀ àgbà. Nígbàtí ìyá-àgbà bá nṣe iṣẹ́ òwú “Sányán”...
View Article