Quantcast
Channel: The Yoruba Blog
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live

“Ọmọdé ò jobì, àgbà ò jẹ oyè” Èrè Òbí tó kọ ọmọ sílẹ̀: The...

Yorùbá ni “Ọmọdé ò jobì, àgbà ò jẹ oye”, òwe yi bá àwọn òbí ti ó kọ ọmọ sílẹ̀, ìyá ti ó ta ọmọ, bàbá ti ó sá fi ọmọ sílẹ̀ àti àwọn ti o fi ìyà jẹ ọmọ, irú ọ̀pọ̀lọpọ̀ òbí bayi ni...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ẹni bá wá iwa-kuwa, ojú rẹ á ri irikuri” – Ìtàn bi imú Erin ti di...

Ni igbà kan ri, imú Erin dàbi ti àwọn ẹranko tó kù ni, ṣùgbọ́n Erin fi aigbọ tara ẹni, di o ni imú gigùn.  Gbogbo nkan tó nlọ ni ayé àwọn ẹranko yoku ni Erin fẹ tọpinpin rẹ. Yorùbá ni...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ẹ̀gẹ́ ò lẹ́wà; lásán ló fara wé Iṣu” – “Cassava has no attraction, it...

Ẹ̀gẹ́/Gbaguda/Pákí fi ara jọ Iṣu nitori àwọn mejeeji jẹ oúnjẹ ti ó wọ́pọ̀ ni ilẹ̀ Yorùbá ti wọn ńkọ ebè fún lati gbin.  Wọn ma nwa wọn lati inú ebè ti wọn bá ti gbó, wọn ni eèpo ti wọn ma...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ẹ Kú Ọwọ́ Lómi Là Nki Ọlọ́mọ Tuntun – Ìtọ́jú Ọmọ Tuntun ni Àtijọ́”:...

Ni ayé àtijọ́, kò si itẹdi à lò sọnù bi ti ayé òde òni.   Bẹni wọn kò lo ìgò oúnjẹ lati fún ọmọ tuntun ni oúnjẹ. Ri rọ ọmọ – Yoruba Traditional baby feeding. Courtesy:@theyorubablog Ọwọ́...

View Article

“Ìkà gbàgbé Àjọbi, adánilóró̀ gbàgbé ọ̀la, ẹ̀san á ké lóri...

Yorùbá ni ètò àti òfin ti àwọn Àgbà, Ọba àti Ìjòyè fi nto ilú ki aláwọ̀-funfun tó dé.  Onirúurú ọ̀nà ni wọn ma fi nṣe idájọ́ ìkà laarin àwùjọ.  Wọn lè fi orin tú àṣiri...

View Article


“Orúkọ ti òbi Yorùbá nsọ Àbíkú” – “Yoruba parental names associated...

(Olóògbé Ọ̀jọ̀gbọ́n Olikoye Ransome Kuti – Oníṣègùn-Ọmọdé ti gbogbo àgbáyé mọ̀, Òjíṣẹ́-Òṣèlú Nigeria ni ọdún keji-din-lọ́gbọ̀n si ọdún keji-lé-lógún sẹhin, ṣe irànlọ́wọ́ gidigidi...

View Article

IMULO ÒWE YORUBA: APPLYING YORUBA PROVERBS

“A NGBA ÒRÒMỌDÌYẸ LỌWỌ IKÚ O NI WỌN O JẸ KI OHUN LỌ ATAN LỌJẸ”  A le lo òwe yi lati kilọ fun ẹni to fẹ lọ si Òkèokun (Ìlu Òyìnbó)  lọna kọna lai ni ase tabi iwe ìrìnà.  Bi ẹbi, ọrẹ tabi ojulumọ to mọ...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

‘Gómìnà Ìpínlẹ̀ Yorùbá, ẹ pèsè omi mi mun fún ará ilú ki wọ́n yé...

Ìjọba Ológun àkọ́kọ́ ni abẹ́ Olóògbé Ọ̀gágun Aguiyi Ironsi, da gbogbo ipinlẹ̀ pọ si abẹ́ Ìjọba àpapọ̀.  Ki wọ́n tó dá àwọn ipinlẹ̀ pọ̀, àwọn ipinlẹ̀ ndàgbà sókè gẹ́gẹ́ bi ohun ti ó ṣe...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ìfura loògùn àgbà, àgbà ti kò sọnú, á sọnù”: “Suspicion is the medicine of...

Ẹ̀kọ́ kíkọ́ ni ó lè fún àgbà ni ọgbọ́n àti òye lati lè sọnú.  Oriṣiriṣi ọ̀nà ni a lè fi gbà kọ́ ẹ̀kọ́, ṣugbọn ni ayé òde òni, ohun gbogbo ni a lè ri kọ́ ni orí ayélujára. Bi ayélujára ti sọ ayé di...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Bi a bá tori ẹni burúkú fọ́jú, a kò ni ri ojú ri ẹni rere” – “If one...

Kò si ilú, ẹ̀yà tàbi àwọ̀ ti kò ni ẹni burúkú tàbi ẹni rere.  Àti ẹni burúkú àti ẹni rere ló wà ninú ẹbi, ilú, àti gbogbo ẹ̀yà àgbáyé ninú èniyàn dúdú àti funfun, ọkùnrin,...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Bi ikú ilé ò pani, tòde ò lè pani” – “If the death at home does not...

“Bi ikú ilé ò pani, tòde ò lè pani” – “If the death at home does not kill, the death outside will not” Òwe Yorùbá ti o ni “Bi ikú ilé ò pani, tòde ò lè pani” bá ọ̀pọ̀ iṣẹ̀lẹ̀ ti o...

View Article

“Orúkọ Yorùbá ti o ti inu Ẹsin Ìgbàgbọ jade” – “Yoruba names that...

Yorùbá jẹ èrè àti ka Ìwé Mímọ́ ti a mọ̀ si “Bibeli Mímọ́” nitori iṣẹ́ ribiribi ti Olõgbe Olóri àwọn Àlùfáà Samuel Ajayi-Crowther ṣe lati túmọ Bibeli Mímọ́ si èdè Yorùbá ni Àádóje...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ayẹyẹ ṣi ṣe ni Òkèrè – Àṣà ti ó mba Owó Ilú jẹ́”: “Destination...

Yorùbá fẹ́ràn ayẹyẹ ṣi ṣe púpọ̀ pàtàki fún igbéyàwó.  Ni ayé àtijọ́, ìnáwó igbéyàwó kò tó bi ó ti dà ni ayé òde òni.  Titi di bi ogoji ọdún sẹhin, ilé Bàbá Iyàwó tàbi...

View Article


Orúkọ Gbogbo Ẹ̀yà Ara ni Èdè Yorùbá – Names of part of Human Body in...

Nitotọ àti ṣe ẹ̀yà orí tẹlẹ ṣugbọn a lérò wípé orúkọ gbogbo ẹ̀yà ara lati orí dé ẹsẹ á wúlò fún kíkà. Ẹ̀yà Ara ni Èdè Yorùbá and the English Translation of names of part of the body...

View Article

Welcome to the Yoruba Blog…

The home of all things Yoruba… news, commentary, proverbs, food. Keeping the Yoruba culture alive. Originally posted 2013-01-24 21:03:41. Republished by Blog Post Promoter

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ààntéré ọmọ Òrìṣà-Omi – “Ọmọ o láyọ̀lé, ẹni ọmọ sin lo bimọ”: Aantere...

Yorùbá ka ọmọ si ọlá àti iyì ti yio tọ́jú ìyá àti bàbá lọ́jọ́ alẹ́.  Eyi han ni orúkọ ti Yorùbá nsọ ọmọ bi: Ọmọlọlá, Ọmọniyi, Ọmọlẹ̀yẹ, Ọmọ́yẹmi, Ọlọ́mọ́là, Ọlọ́mọlólayé, Ọmọdunni,...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ọdún Ẹgbã-lemẹ̃dogun wọlé, ọdún á yabo o – Year 2015 is here, may the...

Ọdún tuntun Ẹgbã-lemẹ̃dogun wọlé dé.  Ilú Èkó fi tijó tayọ̀ gba ọdún tuntun wọlé, gbogbo àgbáyé naa fi tijó tayọ̀ gba ọdún wọlé.  A gbàdúrà pé ki ọdún yi tura fún gbogbo wa o...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ìtàn Ìjà laarin Ọ̀kẹ́rẹ́ àti Asin – Ìgbẹ̀hìn Ìjà fún Asin àti...

Ni ayé igbà kan ri, àwọn ẹranko ni ọjà ti wọn.  Ni ọjọ́ ọjà, Kìnìún, Ajá, Ìgalà, Ikõkò, Kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀, Erin, Ẹkùn,  Ìjàpá, Ọ̀kẹ́rẹ́, Eku-Asin, àti àwọn ẹranko yoku gbé irè oko àti...

View Article

Àwòrán àti pípè orúkọ Èlò Ọbẹ̀ Yorùbá – Pictures and pronunciation...

Àwọn èlò ọbẹ̀ Yorùbá, ẹni ti ó bá mọ ọbẹ̀ se, yio mọ èlò ọbẹ̀ ti ohun yio ra àti bi yio ti se, ṣùgbọ́n ẹni ti kò mọ ọbẹ̀ se, lè lo owó ai mọye lati se ọbẹ̀, ki ọbẹ̀ rẹ má dùn.  Fún...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ìtàn iyàwó ti ó fi ẹ̀mi òkùnkùn pa iyá-ọkọ: Ẹni a fẹ́ la mọ̀, a ò...

Ìtàn ti ó wọ́pọ̀ ni, bi iyá-ọkọ ti burú lai ri ìtàn iyá-ọkọ ti ó dára sọ.  Eyi dákún àṣà burúkú ti ó gbòde láyé òde òni, nipa àwọn ọmọge ti ó ti tó wọ ilé-ọkọ tàbi obinrin...

View Article
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live