Quantcast
Channel: The Yoruba Blog
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live

Àwòrán àti pi pè orúkọ ẹ̀yà ara lati ori dé ọrùn – Pictures and...

Download: Parts of the body in Yoruba – head to neck You can also download the Parts of the body in Yoruba by right clicking this link: Parts of the body in Yoruba – head to neck (mp3) ORÍ DÉ ỌRÙN...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ẹni tó ni Ẹrú ló ni Ẹrù – Ìtàn Bàbá tó kó gbogbo ogún fun Ẹrú...

Àwọn Alágbàṣe ni Oko -Labourers in the farm Ni ayé igbà kan ri ki ṣe oye ọkọ, ilé gogoro, aṣọ àti owó ni ilé-ìfowó-pamọ́ ni a fi nmọ Ọlọ́rọ̀ bi kò ṣe pé oye Ẹrú, Ìyàwó, Ọmọ, Ẹran ọsin àti...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ìfura loògùn àgbà, àgbà ti kò sọnú, á sọnù”: “Suspicion is the medicine of...

Ẹ̀kọ́ kíkọ́ ni ó lè fún àgbà ni ọgbọ́n àti òye lati lè sọnú.  Oriṣiriṣi ọ̀nà ni a lè fi gbà kọ́ ẹ̀kọ́, ṣugbọn ni ayé òde òni, ohun gbogbo ni a lè ri kọ́ ni orí ayélujára. Bi ayélujára ti sọ ayé di...

View Article

ÀWÒRÁN ÀTI PÍPÈ ORÚKỌ ẸRANKO, APA KEJI – Names of Wild/Domestic...

Originally posted 2018-03-22 01:59:26. Republished by Blog Post Promoter

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Bi a bá pẹ́ láyé, a ó jẹ ẹran ti o ́tó Erin” – “If one lives long...

Erin – Elephant Erin jẹ ẹran ti ó tóbi ju gbogbo ẹranko ti a mọ̀ si ẹran inú igbó àti ẹran-àmúsìn, ti a mọ̀ ni ayé òde òni.  Bi a bá ṣe àyẹ̀wò bi Yorùbá ti ńgé ẹran ọbẹ̀, ó ṣòro lati...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Àìnítìjú lọba gbogbo Àlébù: Shamelessness is the king of all Vices

Ìjàpá ọkọ Yáníbo – Tortoise the husband of Yanibo Gbogbo Ẹranko – Group of Animals Gbogbo Ẹranko (Ajá, Àmọ̀tẹ́kùn, Ẹkùn, Kìnìún, Ọ̀bọ, Akátá, Ológbò, Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, Ìjàpá/Àjàpá àti bẹ̃bẹ lọ) kó ara jọ...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ìtàn iyàwó ti ó fi ẹ̀mi òkùnkùn pa iyá-ọkọ: Ẹni a fẹ́ la mọ̀, a ò...

Ìtàn ti ó wọ́pọ̀ ni, bi iyá-ọkọ ti burú lai ri ìtàn iyá-ọkọ ti ó dára sọ.  Eyi dákún àṣà burúkú ti ó gbòde láyé òde òni, nipa àwọn ọmọge ti ó ti tó wọ ilé-ọkọ tàbi obinrin...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

ÀṢÀ ÌDÁBẸ́: A Culture of Female Genital Mutilation #IWD

Ìdábẹ́ jẹ ìkan nínú àṣà Yorùbá tí ólòdì si ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin.  Gẹ́gẹ́bí ìtàn ìdábẹ́, Yorùbá ndabẹ fún ob̀nrin ní àti ìkókó títí dé ọmọ ọdún kan,  nwọn ní ìgbàgbọ́ wipe yio da ìṣekúṣe dúró lára...

View Article


“Ọmọdé ò jobì, àgbà ò jẹ oyè” Èrè Òbí tó kọ ọmọ sílẹ̀: The...

Yorùbá ni “Ọmọdé ò jobì, àgbà ò jẹ oye”, òwe yi bá àwọn òbí ti ó kọ ọmọ sílẹ̀, ìyá ti ó ta ọmọ, bàbá ti ó sá fi ọmọ sílẹ̀ àti àwọn ti o fi ìyà jẹ ọmọ, irú ọ̀pọ̀lọpọ̀ òbí bayi ni...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

A ki sọ pé ki wèrè ṣe òkú ìyá rẹ̀ bi ó bá ṣe ri, bi ó bá ni òhun...

Oriṣiriṣi wèrè ló wà, nitori pé ki ṣe wèrè ti ó wọ àkísà ni ìgboro tàbi já sita nikan ni wèrè.  Ẹnikẹni ti o nhu ìwà burúkú tàbi ṣe ìpinnu burúkú ni Yorùbá npè ni “wèrè”....

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Àpọ́nlé kò si fún Ọba ti kò ni Olorì” – “There is no respect for a King...

Ọ̀rọ̀ Yorùbá ni “Bi ọmọdé bá tó ni ọkọ́, à fún lọ́kọ́”.  Ọkọ́ jẹ irinṣẹ́ pàtàki fún Àgbẹ̀.  Iṣẹ́-àgbẹ̀ ni ó wọ́pọ̀ ni ayé àtijọ́. Nitori eyi, bi bàbá ti nkọ́ ọmọ rẹ ọkùnrin ni...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ìwà bi Ọlọrun pẹ̀lú Ìtẹ́lọ́rùn, Èrè nla ni” – “Godliness with...

Ìtẹ́lọ́rùn – Contentment. Courtesy: @theyorubablog Bi kò bá si ìtẹ́lọ́rùn, kò si ohun ti èniyàn ni ti ó tó.  À i ni ìtẹ́lọ́rùn ló nfa iwà burúkú bi, olè̀ jijà, àgbèrè,...

View Article

ỌRỌ ÌYÀNJÙ (WORD OF ADVICE): Ẹni tólèdè lóni ayé ibi ti wọn ti nsọ

ỌRỌ ÌYÀNJÙ (WORD OF ADVICE) Ẹyin ọmọ Odùduwà ẹjẹ ki a ran rawa létí wípé “Ẹni tólèdè lóni ayé ibi ti wọn ti nsọ”.  Mo bẹ yin  ẹ maṣe jẹki  a tara wa  lọpọ nitorina ẹ maṣe jẹki èdè Yorùbà parẹ. Èdè ti a...

View Article


“Orúkọ Yorùbá ti o ti inu Ẹsin Ìgbàgbọ jade” – “Yoruba names that...

Yorùbá jẹ èrè àti ka Ìwé Mímọ́ ti a mọ̀ si “Bibeli Mímọ́” nitori iṣẹ́ ribiribi ti Olõgbe Olóri àwọn Àlùfáà Samuel Ajayi-Crowther ṣe lati túmọ Bibeli Mímọ́ si èdè Yorùbá ni Àádóje...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Tani alãikàwé/alãimọ̀wé? Ẹnití ó lè kọ, tó lè kà Yorùbá kúrò ní...

Oriṣiriṣi ènìyàn miran tiki sọmọ Yorùbá pọ ni ìlú nla bi ti Èkó tàbí àwọn olú ìlù nla miran ni agbègbè ilẹ Yorùbá (fun àpẹrẹ:  Abéòkúta, Adó-Èkìtì, Akurẹ, Ibadan, Oṣogbo, àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ). Gẹ́gẹ́bí...

View Article


Àpẹrẹ Ìsìnkú Ìbílẹ̀ fún Arúgbó ni Ilẹ́ Yorùbá – Example of Yoruba...

Ìnáwó rẹpẹtẹ ni ìsìnkú arúgbó jẹ́ ni ilé Yorùbá.  Bi arúgbó bá kú ni ilé Yorùbá ki ṣe òkú ọ̀fọ̀ ṣùgbọ́n òkú ijọ àti ji jẹ, mi mu ni pàtàki bi irú arúgbó bá bi àwọn ọmọ ti...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ọ̀dájú ló bi owó, ìtìjú ló bi igbèsè”: “Shrewdness gives birth to money...

Gẹ́gẹ́bí ọ̀rọ̀ Yorùbá ti ó ni “Iṣẹ́ ni oogun ìṣẹ́”, jẹ́ òtítọ́, bi òṣìṣẹ́ bá ri owó gbà ni àsìkò, tàbi gba ojú owó fún iṣẹ́ ti wọn ṣe.  Òṣìṣẹ́ ti ó ṣiṣẹ́ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ wákàtí/àkókò lórí owó kékeré, kò...

View Article


Orúkọ Gbogbo Ẹ̀yà Ara ni Èdè Yorùbá – Names of part of Human Body in...

Nitotọ àti ṣe ẹ̀yà orí tẹlẹ ṣugbọn a lérò wípé orúkọ gbogbo ẹ̀yà ara lati orí dé ẹsẹ á wúlò fún kíkà. Ẹ̀yà Ara ni Èdè Yorùbá and the English Translation of names of part of the body...

View Article

Obinrin kò ṣe e jánípò si ìdí Àdìrò nikan, Obinrin ló ni gbogbo Ilé –...

Ìtàn fi yé wa wi pé Yorùbá ka ọ̀rọ̀ obinrin si ni àṣà Yorùbá  bi ó ti ẹ jẹ wi pé obinrin ki jẹ Ọba nitori ni àṣà ilú, ọkunrin ló njẹ olóri.  Obinrin kò pọ̀ ni ipò agbára.  Àwọn...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Mọ̀ mí, nmọ̀ ẹ́, “Ẹni tó lọ si ilé àna, lọ sọ èdè oyinbo, ni yio túmọ̀...

Ni ayé àtijọ́, òbi ni o nfẹ iyàwó fún ọmọ ọkùnrin wọn.  Bi òbi bá ri ọmọ obinrin ti o dára ni idile ti o dára, wọn á lọ fi ara hàn lati tọrọ rẹ fún ọmọ wọn ọkunrin.  Àṣà yi ti yàtọ̀ ni...

View Article
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live