“Orúkọ ẹni ló njẹri ẹni lókèèrè: Yorùbá tó wà ni òkè-òkun...
Yorùbá ki dá gbé, nitori eyi, ẹbi àti ará á pa pọ̀ lati sọ ọmọ lórúkọ. Ni ọjọ́ ìsọmọ-lórúkọ, ki ṣe iyá àti bàbá ọmọ nikan ni ó nmú orúkọ silẹ̀, iyá àti bàbá àgbà àti ẹ̀gbọ́n...
View Article“Bi o kò bá lágbára ohun ti o fẹ́, ni ìfẹ́ ohun ti o ni”: “If you cannot...
Ẹ kú ipalẹ̀mọ́ ọdún o. Bi ọdún bá sún mọ́ etílé, oúnjẹ àti ohun èlò gbogbo maa nwọn nitori àwọn ọlọ́jà yio ti fi owó kún ọjà nitori èrò ti ó fẹ́ ra ọjà maa n pọ̀ si ni àsikò yi....
View ArticleIṣẹ́ ni oògùn ìṣẹ́ – Hard-work is a cure for poverty
Ẹ ṣe àyẹ̀wò ìwé akéwì-orin ni èdè Yorùbá ti àwọn ọmọ ilé-ìwé n kọ́ sórí ni ilé-ìwé ilẹ̀ Yorùbá ni ayé àtijọ: Iṣẹ́ ni oògùn ìṣẹ́, múra si iṣẹ́ rẹ ọ̀rẹ́ mi, iṣẹ́ ni a fi i di ẹni...
View Article“Ìmọ́tótó borí àrùn mọ́lẹ̀, bi ọyẹ́ ti ḿborí ooru” –“Cleanliness...
http://www.theyorubablog.com/wp-content/uploads/2014/07/Imototo.wav Ìmọ́tótó borí àrùn mọlẹ̀, bọ́yẹ́ ti ḿborí ooru Àrùn ìwọ̀sí tinú ẹ̀gbin là wá Iná ni ḿborí aṣọ ẹlẹ́gbin Ni ayé àtijọ́...
View Article“Ai jẹun Ológbò kọ́ ni kò jẹ́ kó tó Ajá, bẹni ki ṣe ai jẹun Ajá ni kò...
Àsè “Ọjọ́ Ọpẹ́” – Thanksgiving buffet table Fún àwọn ti ó wà ni òkè-òkun – America, wọn ni ọjọ́ ti wọn ya si ọ̀tọ̀ gẹ́gẹ́ bi “Ọjọ́ Ọpẹ́”. Oúnjẹ pọ rẹpẹtẹ ni àsikò yi pàtàki ni “Ọjọ́...
View Article“Ṣe bi o ti mọ ki i tẹ́ – Ọdún wọlé dé”: “One who acts moderately will not...
Ọdún Kérésì jẹ́ ọdún Onigbàgbọ́ lati ṣe iránti ọjọ́ ibi Jésù Olùgbàlà. Ọjọ́ kẹjọ lẹhin ọdún Kérésìmesì ni ọdún tuntun. Fún ayẹyẹ ọdún, kò si iyàtọ̀ laarin Ìgbàgbọ́ àti...
View Article“Gbogbo ohun tó ndán kọ́ ni Wúrà” – “Not all that glitters is Gold”
Wúrà jẹ ikan ninú ohun àlùmọ́ni iyebiye, pàtàki fún ohun ẹ̀ṣọ́. Ẹwà Wúrà ki hàn, titi di ìgbà ti wọn bá yọ gbogbo ẹ̀gbin rẹ̀ kúrò pẹ̀lú iná tó gbóná rara. Àwòrán ti ó wà...
View Article“Àbíkú sọ Olóògùn di èké” – “Child mortality mis-portray the...
Ìgbàgbọ́ Yorùbá yàtọ̀ si ohun ti àwọn Ẹlẹko-Ijinlẹ fi hàn ni ayé òde òni. Ni igbà àtijọ́, bi obinrin/iyàwó bá bi ọmọ, ti ó kú ni ikókó tàbi ki ó tó gba àbúrò, ọmọ ti wọn bá...
View Article“Ẹ̀mí ti ò jata, ẹ̀mí yẹpẹrẹ”: “Life devoid of consumption of pepper is trifle”
Ata-ṣọmbọ, Ata-wẹ́wẹ́, Ata-Ijọsin, Ata gbigbẹ, Ata gígún àti awọn èlò ọbẹ̀ – Jalapeno, Serrano, Cayenne & various spices. Courtesy: @theyorubablog Ata ṣe pàtàki ninu àwọn èlò ọbẹ̀....
View ArticleA ki sọ pé ki wèrè ṣe òkú ìyá rẹ̀ bi ó bá ṣe ri, bi ó bá ni òhun...
Oriṣiriṣi wèrè ló wà, nitori pé ki ṣe wèrè ti ó wọ àkísà ni ìgboro tàbi já sita nikan ni wèrè. Ẹnikẹni ti o nhu ìwà burúkú tàbi ṣe ìpinnu burúkú ni Yorùbá npè ni “wèrè”....
View ArticleOunjẹ Yorùbá: Yoruba Food
Ẹ GBA OUNJẸ YORÙBÁ LÀ: SAVE YORÙBÁ: SAVE YORUBA FOOD Ọpọlọpọ oriṣiriṣi ounjẹ Yorùbá nparẹ lọ, nípàtàkì larin awọn to ngbe ìlú nla. Òwe Yorùbá ni “Ki àgbàdo to de ilẹ aye, adíyẹ njẹ, adíyẹ nmu”....
View Article“Ti ibi, ti ire la wá ilé ayé” –Ọ̀rọ̀ àti Ìṣe Ìgboro ni Èkó: “We came into...
Èkó jẹ́ olú ìlú Nigeria fún ọpọlọpọ ọdún, ki wọn tó sọ Abuja di olú ìlú Nigeria, ṣùgbọ́n Èkó ṣi jẹ́ olú ìlú fún iṣẹ ọrọ̀ gbogbo Nigeria. Nitori eyi, gbogbo ẹ̀yà Nigeria àti àwọn ará ìlú miran titi dé...
View ArticleÌtẹ́lọ́rùn ni Baba Ìwà – Contentment is the Father of Character
Àìní ìtẹ́lọ́rùn ló bí gbogbo ìwà burúkú bi: irọ́ pípa, olè jíjà, àgbèrè, ojúkòkòrò àti bẹ̃bẹ lọ. Àìní ìtẹ́lọ́rùn ló wà ni ìdí àwọn Oṣèlú àti Olórí Ìjọ ti o nlo owó ìlú tàbi owó ìjọ fún ara wọn dipò ki...
View ArticleÌtán ti a fẹ́ kà loni dá lóri Bàbá tó kó gbogbo Ẹrù fún Ẹrú – The...
Originally posted 2017-12-06 00:23:08. Republished by Blog Post Promoter
View Article“Orin ẹ̀kọ́ lati bọ̀wọ̀ fún òbí ni ilé-ìwé alakọbẹrẹ”: Primary School...
Orin yi ni Olùkọ́ ma fi ńkọ́ àwọn ọmọ ilé-ìwé alakọbẹrẹ nigbà “ilé-ìwé ọ̀fẹ́” ti àwọn Òṣèlú ilẹ̀ Yorùbá ti Olóyè Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ ṣe olórí rẹ. Ni ayé ìgbà wọnyi, ọ̀pọ̀lọpọ̀ òbí...
View Article“Ilé làbọ̀sinmi oko” – “Home is for rest after the farm or hard day’s work”.
Bi ènìà lówó tàbi bi kò ni, àwọn ohun kan ṣe pàtàki lati wà ni ílé ki a tó lè pẽ ibẹ̀ ni ilé. Fún àpẹrẹ: ilé ti ó ni òrùlé, ilẹ̀kùn àti fèrèsé; àdìrò àti àdògán; omi: Ki ba jẹ omi ẹ̀rọ, omi òjò tàbí...
View ArticleWelcome to the Yoruba Blog…
The home of all things Yoruba… news, commentary, proverbs, food. Keeping the Yoruba culture alive. Originally posted 2013-01-24 21:03:41. Republished by Blog Post Promoter
View ArticleGbẹ̀dẹ̀ bi Ogún Ìyá, Ogún Bàbá ló ni ni lára – Maternal Inheritance...
Ogún jẹ́ gbogbo ohun ìní ti bàbá tàbi ìyá bá fi silẹ́ ti wọn bá kú. Ni ìgbà àtijọ́, kò wọ́pọ̀ ki olóògbé ṣe ìwé-ìhágún, bi wọn ṣe má a pín ohun ini wọn lẹhin ikú. Ọ̀pọ̀lọpọ̀...
View Article“Ni ilú Afọ́jú, Olójú kan Lọba”: Ìjọba Òṣèlú tuntun gba Ìjọba ni...
Ọjọ́ itàn ni ọjọ́ kọkàndinlógún, oṣù karun, ọdún Ẹgbãlemẹ̃dógún jẹ fun orilẹ̀ èdè Nigeria àti gbogbo ilẹ̀ Aláwọ̀dúdú. Kò wọ́pọ̀ ki Ìjọba Ológun tàbi Ẹgbẹ́ Òṣèlú gbà lati gbé...
View ArticleA ki yin lati Ilé – Greetings from Home
Ni ai pẹ yi, Olùkọ̀wé yi bẹ ilé wò fún bi ọ̀sẹ̀ mẹta. A ṣe àwọn akiyesi wọnyi. Ilú Èkó n fẹ̀ si, ṣùgbọ́n ọ̀nà kò fẹ̀ tó bi èrò àti ọkọ̀ ti pọ̀ tó, nitori eyi, sún-kẹrẹ fà-kẹrẹ ọkọ̀...
View Article