“Iṣẹ́ ajé, sọ ọmọ nù bí òkò” –“Working for survival throws away the child...
Ọjọ́ ti pẹ́ ti Yorùbá ti ńkúrò ni ilú kan si ilú keji, yálà fún ọrọ̀ ajé tàbi fún ẹ̀kọ-kikọ́. Ni ayé àtijọ́, ọjọ́ pípẹ́ ni wọn fi ńrin irin-àjò nitori irin ti ọkọ̀ òfúrufú lè...
View Article“Ìkà gbàgbé Àjọbi, adánilóró̀ gbàgbé ọ̀la, ẹ̀san á ké lóri...
Yorùbá ni ètò àti òfin ti àwọn Àgbà, Ọba àti Ìjòyè fi nto ilú ki aláwọ̀-funfun tó dé. Onirúurú ọ̀nà ni wọn ma fi nṣe idájọ́ ìkà laarin àwùjọ. Wọn lè fi orin tú àṣiri...
View ArticleÀròkàn ló n fa ẹkún à sun à i dákẹ́: Anguish of mind is the root...
Ohun ti Yorùbá mọ̀ si àròkàn n irònú igbà gbogbo. Kò si ẹni ti ki ronú, ṣùgbọ́n àròkàn léwu. Inú rirò yàtọ si àròkàn. Inu rirò ni àwọn Onimọ-ijinlẹ̀ lò lati ṣe ọkọ̀ òfúrufú...
View ArticleBi ọmọ ò jọ ṣòkòtò á jọ kíjìpá: Ibáṣe pọ Idilé Yorùbá – If a child...
Bàbá, iyá àti ọmọ ni wọn mọ si Idilé ni Òkè-òkun ṣùgbọ́n ni ilẹ̀ Yorùbá kò ri bẹ́ ẹ̀, nitori ẹbi Eg bàbá, ẹ̀gbọ́n àti àbúrò ẹni, ọmọ, ọkọ àti aya wọn ni a mọ̀ si Idilé. Yorùbá...
View ArticleABD YORÙBÁ – Yoruba Alphabet
“ABD”, ìbẹ̀rẹ̀ iwé kikà ni èdè Yorùbá – Yoruba Alphabets “ABD” is the beginning of Yoruba education. Bi ọmọdé bá bẹrẹ ilé-iwé alakọbẹrẹ, èdè Yorùbá ni wọn fi nkọ ọmọ ni ilé-iwé lati...
View Article“Olúróhunbí jẹ́ ẹ̀jẹ́ ohun ti kò lè san”: “Olurohunbi made a vow/covenant she...
Yorùbá ka ọmọ bibi si ohun pàtàki fún ìdílé, nitori èyi, tijó tayọ̀ ni Yorùbá ma fi nki ọmọ titun káàbọ̀ si ayé. Gẹ́gẹ́bí Ọ̀gá ninu Olórin ilẹ̀-aláwọ̀ dúdú, Olóyè Ebenezer Obey ti kọ́ “Ẹ̀bùn pàtàki ni...
View ArticleBíbẹ Èkó wo fún Ọ̀sẹ̀ kan – Ọjọ́ kẹta: Visiting Lagos for one week – Day 3...
Apá Kinni – Part One Download: A conversation in Yoruba (Day 3) You can also download the conversation by right clicking this link: A conversation in Yoruba – Day 3(mp3) ONÍLÉ – HOST/HOSTESS &...
View ArticleỌdún tuntun káàbọ̀ –Ẹgbà-lé-mẹ́rìnlà – Welcoming the New Year – 2014
Ẹ kú ọdún o – Season Greetings. Courtesy: @theyorubablog Ẹ kú ọdún Festive Greetings Ẹ kú ìyè dún Greetings on the return of the year Ọdún á ya abo Prosperous New Year À ṣèyí ṣe àmọ́dún...
View ArticleKò si ọgbọ́n to lè dá, kò si ìwà ti o lè hù, ti o lè fi tẹ́ aiyé...
Oni – kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ – The Horseman & his son Ni aiyé àtijọ́, ẹsin àti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ló dàbi ọkọ̀ igbàlódé ti wọn ńpè ni mọ́tò. Ẹni ti ó jẹ́ ọlọ́rọ̀, ló lè ni ẹsin tàbi kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́....
View Article“Gbogbo ohun tó ndán kọ́ ni Wúrà” – “Not all that glitters is Gold”
Wúrà jẹ ikan ninú ohun àlùmọ́ni iyebiye, pàtàki fún ohun ẹ̀ṣọ́. Ẹwà Wúrà ki hàn, titi di ìgbà ti wọn bá yọ gbogbo ẹ̀gbin rẹ̀ kúrò pẹ̀lú iná tó gbóná rara. Àwòrán ti ó wà...
View ArticleKÍKÀ NÍ YORÙBÁ: COUNTING IN YORUBA – NUMBERS 1 TO 20
KÍKÀ ỌJÀ NIPARI Ọ̀SẸ̀ – END OF WEEK STOCK TAKING: LEARNING NUMBERS 1 TO 20 Download: counting in Yoruba/a> You can also download the Yoruba alphabets by right clicking this link: counting 1 -20 in...
View Article“Ṣòkòtò àgbàwọ̀, bi kò ṣoni lẹsẹ á fúnni nítan”: “A borrowed trouser/pant, if...
Ìwà àti ìṣe ọ̀dọ́ ìgbàlódé, kò fi àṣà àti èdè Yorùbá hàn rárá. Aṣọ àlòkù ti gbòde, dipò aṣọ ìbílẹ̀. Ọpọlọpọ aṣọ àgbàwọ̀ yi kò wà fún ara àti lilò ni ilẹ̀ aláwọ̀-dúdú. Ọ̀dọ́ miran a wọ asọ àti bàtà...
View Article“Ohun ti ajá mã jẹ, Èṣù á ṣẽ”: “What the dog will eat, the Devil will...
Yorùbá ma nṣe rúbọ Èṣù nigba gbogbo ki ẹ̀sìn ìgbàgbọ́ tó gbalẹ̀. Ounjẹ ni wọn ma fi ṣè rúbo ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà. Irú ounjẹ yi ni Yorùbá npè ni “ẹbọ”. Ìta gbangba ni wọn ma ngbe irú...
View Article“Orúkọ idile Yorùbá ti ó ńparẹ́” – “Yoruba family names that are...
Orúkọ ẹni ni ìfihàn ẹni, orúkọ Yorùbá fi àṣà, iṣẹ́ àti Òriṣà idile hàn tàbi àtẹsẹ̀bi ọmọ. Yorùbá gbàgbọ́ ninú Ọlọrun/Eledumare ki ẹ̀sin igbàgbọ́ àti imọ̀le tó dé. Ifá jẹ́ ẹ̀sin...
View ArticlePi pè àti Orin fún orúkọ ọjọ́ ni èdè Yorùbá – Yoruba Days of the week...
http://www.theyorubablog.com/wp-content/uploads/2014/07/Oruko-Ojo-ni-ede-Yoruba-Days-of-the-week.wav Orúkọ Ọjọ́ni èdè Yorùbá Days of the Week In English Àìkú/Ọjọ́ Ọ̀sẹ̀/Ìsimi...
View Article“Orin ẹ̀kọ́ lati bọ̀wọ̀ fún òbí ni ilé-ìwé alakọbẹrẹ”: Primary School...
Orin yi ni Olùkọ́ ma fi ńkọ́ àwọn ọmọ ilé-ìwé alakọbẹrẹ nigbà “ilé-ìwé ọ̀fẹ́” ti àwọn Òṣèlú ilẹ̀ Yorùbá ti Olóyè Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ ṣe olórí rẹ. Ni ayé ìgbà wọnyi, ọ̀pọ̀lọpọ̀ òbí...
View ArticleỌba titun, Ọọni Ifẹ̀ Kọkànlélaadọta gba Adé – The new Monarch, Ooni of Ife...
Ọọni Ifẹ̀ Kọkànlélaadọta gba Adé – Ooni of Ife Oba Enitan Ogunwusi after receiving the AARE Crown from the Olojudo of Ido land on Monday PHOTOS BY Dare Fasub Ilé-Ifẹ̀ tàbi Ifẹ̀ jẹ ilú àtijọ́ ti...
View Article“Ẹni tó Lórí kò ní Fìlà, Ẹni tó ní Fìlà kò Lórí”: “The one who has a...
Fìlà Aṣọ Òfì – Traditional Yoruba CapCourtesy: @theyorubablog.com Ọ̀rọ̀ Yorùbá ní “Ẹni tó Lórí kò ní Fìlà, Ẹni tó ní Fìlà kò Lórí”. Tani eni “Ẹni tó Lórí ti kò ní Fila”? Enití gbogbo...
View ArticleÀwòrán ati Orúkọ àwọn Ẹiyẹ ni èdè Yorùbá – Pictures and names of...
Originally posted 2014-10-17 13:00:55. Republished by Blog Post Promoter
View ArticleA Dúpẹ́ fún Ẹyin Àyànfẹ́ tó Bẹ̀rẹ̀ sí Tẹ̀léwa ní Twitter: Thank You to Our...
Twitter followers Ẹfi ojú sọ́na lọ́sọ̀sẹ̀ fún kíkọ nípa àwọn nkan wọnyi lédè Yorùbá àti ìtum̀ọ lédè Gẹ̀ẹ́sì: Ìmúlò Òwe, Kíkọ Èdè, Ìtàn àti Ìròyìn tí a lè fi kọ́gbọ́n, Ẹgbẹ́ àti Oúnjẹ Yorùbá ni ìlú...
View Article