Quantcast
Channel: The Yoruba Blog
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ọwọ́ Ọmọdé Kòtó Pẹpẹ, Tagbalagba Ò Wọ Kèrègbè: The Child’s Hand Cannot...

Only a child’s hand can reach into this type of calabash. The image is from Wikipedia. Ọ̀rọ̀ Yorùbá sọ wípé “ọwọ́ ọmọde ko to pẹpẹ, tagbalagba ko wọ̀ kèrègbè”, èyí tí a lè túmọ̀ sí wípé,...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ibi ti à ńgbé là ńṣe…” – Ìfi ìdí kalẹ̀ ni Ìlú-Ọba – One should live...

 Ẹ̀kọ́ púpọ̀ ni enia lè ri kọ́ ni irin àjò.  A lè rin irin àjò fún ìgbà díẹ̀ tàbi pípẹ́ lati bẹ ilú nã wò tàbi lati lọ tẹ̀dó si àjò. wọ ọkọ̀ òfũrufu – Boarding Aeroplane. Courtesy:...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Àjọ̀dún Òmìnira Nigeria Kẹrindinlọgọta – Nigeria’s Fifty-six Independence...

Àjọ̀dún Òmìnira Nigeria Kẹrindinlaadọta – Nigeria’s Fifty-six Independence Celebration. Courtesy: @theyorubablog Originally posted 2016-10-01 00:37:30. Republished by Blog Post Promoter

View Article

Àwòrán ati pi pe Orúkọ Ẹranko ni Èdè Yorùbá Apá Kini àti Apá Keji...

Bi ó ti ẹ̀ jẹ́ pé a ti kọ nipa orúkọ àti àwòrán ẹranko ni àwọn ìwé ti a ti kọ sẹhin, ṣùgbọ́n Yorùbá ni “Ọgbọ́n ki i tán”, nitori eyi, a ṣe àtúnṣe gẹ́gẹ́ bi “Ọ̀jọ̀gbọ́n Èdè Yorùbá” ti...

View Article

Orúkọ Ẹranko a fàyà fà tabi jomijòkè ni èdè Yorùbá: Names of...

Gẹgẹbi àpè júwe, ẹranko a fàyà fà jẹ ẹranko ti ó ni àwọ̀, omiran ni oro, omiran ni ikarawun, wọn si ńyé ẹyin.  Bi Ejò, àti Ákẽke ti ni oró bẹ̃ ni Àjàpá  àti Ìgbín ni ikarawun. Fún...

View Article


YORÙBÁ alphabets – A B DOriginally Posted on May 31, 2016, last updated on...

A B D E Ẹ F G GB H I J K L M N O Ọ P R S Ṣ T U W Y   You can also download the Yoruba alphabets by right clicking this link: A B D – audio file Yoruba alphabets recited (mp3) OHUN TÍ A LÈ FI PÈ...

View Article

Ẹ̀kọ́ àti Ọgbọ́n ni Ọ̀rọ̀ Àgbà lati Ẹnu Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọmọlolú Olunlọyọ lórí...

Bi a ba fi eti si ọ̀rọ̀ ti àgbà Yorùbá Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọmọlolú Olunlọyọ  ni ori ẹ̀rọ “Amóhùnmáwòrán Òpómúléró”, ni ori ayélujára, a o ṣe àkíyèsí àwọn nkan wọnyi:...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Iwé-àkọ-ránṣẹ́ ni èdè Yorùbá – Letter writing in Yoruba...

Ni àtijọ́, àwọn ọmọ ilé-iwé ló ńran àgbàlagbà ti kò lọ ilé-iwé lọ́wọ́ lati kọ iwé, pataki ni èdè abínibí.  Ẹ ṣe àyẹ̀wò àwọn iwé-àkọ-ránṣẹ́ wọnyi ni ojú iwé yi: Ìwé ti Ìyá kọ...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ìgbéyàwó Ìbílẹ́ Yorùbá: “Ọ̀gá Méji Kò Lè Gbé inú Ọkọ̀” – Yoruba...

Adarí Ètò Ijoko àti “Adarí Ètò Ìdúró – Traditional Master of Ceremony. Courtesy: @theyorubablog A ṣe àkíyèsí pé wọn ti sọ iṣẹ́ ìyàwó-ilé di òwò nibi ìgbéyàwó ìbíl̀̀̀̀̀̀ẹ̀, pàtàki ni àwọn ilú nlá,...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Bi eyi ò ṣe, omiran yio ṣe – bi Ọlọrun o pani, ẹnikan ò lè pani”: If this...

Ìtàn yi dá lori Bàbá ti aládũgbò mọ si “Bàbá Beyioṣe”.  Bàbá yi jẹ onígbàgbọ́, ti ki ja tabi ṣe ãpọn.  O bi ọmọ mẹta ti wọn jọ ngbe nitori iyawo rẹ ti kú. Ni ilé ti o ngbe, ó fi ifẹ...

View Article

Tọ́jú Ìwà Rẹ Ọ̀rẹ́ Mi – Ọ̀rọ̀-orin lati Ìwé Olóògbé Olóyè J.F....

Ọ̀rọ̀-orin yi jẹ ikan ninú àwọn àkọ́-sórí ni ilé-ìwé alakọbẹrẹ ni ilẹ̀ Yorùbá ni igbà ti ile-iwe àpapọ̀ yè koro.  Ṣùgbọ́n ni ayé òde òni, ti gbogbo ilé-ìwé ti kọ èdè abínibí silẹ̀,...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ewédú: Botanical Name Cochorus, Craincrain in Sierra LeoneOriginally Posted...

Ewédú jẹ ikan nínú ọbẹ̀ Yorùbá tó wọpọ ni agbègbè Ọ̀yó, Ọ̀sun, Ògùn gẹ́gẹ́bi ilá ti wọ́pọ̀ ni agbègbè Ondo àti Èkìti. Fún ẹni tó́ nkanju, ilá yára láti sè ju ewédú lọ, nítorí...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Òṣèlú Ẹ Gbé Èdè Yorùbá Lárugẹ: Politicians – Promote Yoruba...

Yoruba, other Nigerian languages on the verge of extinction, Prof Akinwunmi Isola warns Nínú ìwé ìròyìn “Vanguard”, ti ọjọ́ Àìkú, oṣù kẹta, ọjọ́ , ọdún kẹrinlélógún, Ẹgbaalémétàlá, Olùkọ́...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Gèlè ò dùn bi ká mọ̀ ọ́ wé, ká mọ̀ ọ́ wé, kò tó kó yẹni”: “Head tie is not...

Aṣọ Yorùbá, ìró àti bùbá kò pé lai si gèlè. Gèlè oriṣiriṣi ló wà̀, a lè lo gèlè aṣọ ìbílẹ̀ bi: aṣọ òfi/òkè, àdìrẹ, tàbi ki á yọ gèlè lára aṣọ.  Ọpọlọpọ gèle ìgbàlódé wá lati òkè òkun. Ìmúra obinrin...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ìgbésí Ayé Aláwọ̀-dúdú Ṣe pàtàki” pé Àwọ Lè Yàtọ̀, Ṣùgbọ́n...

B;ack Lives Matter protesters Ikú àwọn ọkùnrin Aláwọ̀-dúdú ni ọwọ́ Ọlọpa ni orilẹ̀ èdè Àméríkà pọ̀ ju pi pa àwọn aláwọ̀ funfun tàbi laarin àwọn ẹ̀yà kékeré miran.  Ọ̀sẹ̀ kini oṣù...

View Article


“Bibi ire kò ṣe fi owó rà – Yoruba names” – “Good pedigree cannot be...

Kò di igbà ti enia bá ni owó rẹpẹtẹ ki ó tó sọ ọmọ rẹ ni “Ọlá” nitori Yorùbá ka ipò giga, ọmọ, ilera, orúkọ rere si “Ọlá”.  Ibi ti “Ọlá” wà ninú orúkọ Yorùbá, a lè lo “Adé; Ibi;...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Awọ kò ká Ojú ìlù, Ọmọ Onílù ni òhun fẹ́ má a sun Awọ jẹ –...

Nigbati àwọn Òṣèlú gba Ìjọba ni igbà keji lọ́wọ́ Ìjọba Ológun, inú ará ilú dùn nitori wọn rò wi pé Ológun kò kọ iṣẹ́ Òṣèlú.  Ilú rò wi pé Ìjọba Alágbádá yio ni àánú ilú ju...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Àpọ́nlé kò si fún Ọba ti kò ni Olorì” – “There is no respect for a King...

Ọ̀rọ̀ Yorùbá ni “Bi ọmọdé bá tó ni ọkọ́, à fún lọ́kọ́”.  Ọkọ́ jẹ irinṣẹ́ pàtàki fún Àgbẹ̀.  Iṣẹ́-àgbẹ̀ ni ó wọ́pọ̀ ni ayé àtijọ́. Nitori eyi, bi bàbá ti nkọ́ ọmọ rẹ ọkùnrin ni...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Wọn mbẹ Oníṣègùn, wọn ò bẹ Aláìsàn” – “Pleading with the Doctor without...

Yorùbá ma nlo òwe yi nigbati èniyàn bá ṣẹ̀ tàbi ṣe nkan burúkú si ẹni keji, ti wọn bẹ̀rẹ̀ si bẹ ẹni ti wọn ṣẹ̀ lai mọ bóyá ẹni ti ó ṣẹ̀ ni àyipadà ọkàn kúrò ni iwà ìbàjẹ́ tàbi iṣẹ́...

View Article

“Ìwé àti kọ Yorùba lọfẹ lọwọ Àjàyí Crowther Fún Ra Rẹ”: Learn Yoruba for Free...

Ise Alagba Yoruba, Ajayi Crowther fun ra re. A Yoruba dictionary to look up basic vocabulary     Originally posted 2013-05-23 05:38:56. Republished by Blog Post Promoter

View Article
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live