Quantcast
Channel: The Yoruba Blog
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live

Ẹ káàbọ̀ si ọdún Ẹgbàálémẹ́tàdínlógún – Welcome to 2017

Originally posted 2016-12-31 23:30:32. Republished by Blog Post Promoter

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Iṣẹ́ loògùn ìṣẹ́” – “Work is the antidote for destitution/poverty”

http://www.theyorubablog.com/wp-content/uploads/2014/12/Iṣẹ́-Àgbẹ̀-ni-iṣẹ́-ilẹ̀-wa-Song-to-encourage-Farming.wav Orin fun Àgbẹ̀:                            Yoruba song encouraging farming: Iṣẹ́...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Bi o kò bá lágbára ohun ti o fẹ́, ni ìfẹ́ ohun ti o ni”: “If you cannot...

Ẹ kú ipalẹ̀mọ́ ọdún o.  Bi ọdún bá sún mọ́ etílé, oúnjẹ àti ohun èlò gbogbo maa nwọn nitori àwọn ọlọ́jà yio ti fi owó kún ọjà nitori èrò ti ó fẹ́ ra ọjà maa n pọ̀ si ni àsikò yi....

View Article

ORÚKỌ ỌJỌ́: Days of the Week in Yoruba

Below are the Yoruba days of the week. Of course it is worth noting that very few native Yoruba speakers use these words in conversation.   SUNDAY                               ÀÌKÚ MONDAY...

View Article

“Orin ẹ̀kọ́ lati bọ̀wọ̀ fún òbí ni ilé-ìwé alakọbẹrẹ”: Primary School...

Orin yi ni Olùkọ́ ma fi ńkọ́ àwọn ọmọ ilé-ìwé alakọbẹrẹ nigbà “ilé-ìwé ọ̀fẹ́” ti àwọn Òṣèlú ilẹ̀ Yorùbá ti Olóyè Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ ṣe olórí rẹ.  Ni ayé ìgbà wọnyi, ọ̀pọ̀lọpọ̀ òbí...

View Article


Wi wé Gèlè Ìgbàlódé – How to tie Modern Head Scarfs

Originally posted 2015-07-07 19:41:40. Republished by Blog Post Promoter

View Article

Bi Irọ́ bá lọ fún Ogún Ọdún, Òtítọ á ba Lọ́jọ́ Kan – Ìbò Ọjọ́ Kejilá...

Lẹhin ọdún mẹẹdọgbọn ti Ijoba Ologun Ibrahim Babangida fagilé ìbò ti gbogbo ilú dì lai si ìjà tàbi asọ̀ tó gbé Olóògbé Olóyè Moshood Káṣìmáawòó Ọláwálé Abíọ́lá wọlé, Ìjọba...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ìfura loògùn àgbà, àgbà ti kò sọnú, á sọnù”: “Suspicion is the medicine of...

Ẹ̀kọ́ kíkọ́ ni ó lè fún àgbà ni ọgbọ́n àti òye lati lè sọnú.  Oriṣiriṣi ọ̀nà ni a lè fi gbà kọ́ ẹ̀kọ́, ṣugbọn ni ayé òde òni, ohun gbogbo ni a lè ri kọ́ ni orí ayélujára. Bi ayélujára ti sọ ayé di...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Àjàpá rẹ Erin sílẹ̀ – “Ìjàlọ ò lè jà, ó lè bọ́ ṣòkòtò ni idi...

Erin jẹ ẹranko ti Ọlọrun da lọ́lá pẹlu titobi rẹ ninu igbo.  Yorùbá ni “Koríko ti Erin bá ti tẹ̀, àtẹ̀gbé ni láyé”, oko ti Erin bá wọ̀, olóko bẹ wọ igbèsè tori ibajẹ ti o ma ṣẹlẹ̀ si irú...

View Article


Ẹ̀YÀ ARA – ÈJÌKÁ DÉ ẸSẸ̀: PARTS OF THE BODY – SHOULDERS TO TOES

Download: Parts of the body in Yoruba – shoulders to toes You can also download the mp3 by right clicking here: Parts of the body in Yoruba – shoulders to toes (mp3) Ẹ̀YÀ ARA PARTS   OF THE BODY...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

ẸRÙ FÚN ÌDÍLÉ ÌYÀWÓ – LIST FOR BRIDE’S FAMILY – Apá Kẹta – Part Three

Gifts at a modern Yoruba Traditional wedding — courtesy of @theYorubablog Ìyàtọ̀ diẹ̀ ló wà lãrin awọn ẹru igbéyàwó ti a kọ́ si ojú iwé yi lati idile si idile. Fún àpẹre: idile miran fẹ...

View Article

Àwòrán ati Orúkọ àwọn Ẹiyẹ ni èdè Yorùbá – Pictures and names of...

      Originally posted 2014-10-17 13:00:55. Republished by Blog Post Promoter

View Article

Àmì – Yoruba Accent

Àmì – ṣe pàtàkì ni èdè Yorùbá nitori lai si àmì, àṣìwí tàbi àṣìsọ á pọ̀.  Ọ̀rọ̀ kan ni èdè Yorùbá lè ni itumọ rẹpẹtẹ, lai si àmì yio ṣòro lati mọ ìyàtọ.  Àmì jẹ ki èdè Yorùbá...

View Article


“Igbà kan nlọ, igbà kan nbọ̀, igbà kan kò dúró titi” – “Time passes by...

Oriṣi mẹta ni Yorùbá ka igbà ẹ̀dá si.  Gẹ́gẹ́ bi àgbà ninú Olórin ilẹ̀ Aláwọ̀dúdú Olóyè Ebenezer Obey (Fabiyi) ti kọ́ pé “Igbà mẹta ni igbà ẹ̀dá láyé, igbà òwúrọ̀, igbà ọ̀sán,...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

ATỌ́NÀ LÉDÈ YORÙBÁ – Cardinal Directions in Yoruba

A compass showing the poles in Yoruba language. The image is courtesy of @theyorubablog   Originally posted 2013-04-16 19:01:07. Republished by Blog Post Promoter

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ni Ayé òde òni, njẹ́ ó yẹ ki a pọ́n Àṣà fi fẹ́ Iyàwó púpọ̀ lé ni...

Ni igbà àtijọ́, oníyàwó kan kò wọ́pọ̀ nitori iṣẹ́ Àgbẹ̀.  Àṣà fi fẹ́ iyàwó púpọ̀ ṣe kókó nitori bibi ọmọ púpọ̀ pàtàki ọmọ ọkùnrin fún irànlọ́wọ́ iṣẹ́-oko.  Fi fẹ̀ iyàwó púpọ̀ kò...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“ỌMỌ ÌYÁ́ MEJI KI RÉWÈLÈ”: 2 Siblings of the Same Mother Should not Die in...

Omo iya meeji okin ka abamo: Chechen legal permanent resident brothers terrorist suspects in Boston marathon bombing. Image is from the WHDH stream. “Ọmọ ìyá meji ki réwèlè, Yorùbá ma nlo ọ̀rọ̀ yi...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Òjò nrọ̀, Orò nké, atọ́kùn àlùgbè ti ò láṣọ méji a sùn ihòhò –...

Ìgbà tàbi àsikò mèji ló wà ni ọ̀pọ̀ ilẹ̀ aláwọ̀-dúdú, ìgbà òjò àti ẹ̀rùn.  Ni ayé àtijọ́, òjò ni ará ilú gbójúlé lati pọn omi silẹ̀ fún ọ̀gbẹlẹ̀.  Àsikò òjò ṣe pàtàki...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ọ̀run ńyabọ̀, ki ṣé ọ̀rọ̀ ẹnìkan”: “The sky is falling, is not a matter...

Ọ̀run ńyabọ̀ – the sky is falling. Courtesy: @theyroubablog Òwe Yorùbá yi ṣe gba àwọn ti o nbẹ̀rù nigba gbogbo níyànjú wípé ó yẹ ki èniyàn fara balẹ̀ lati ṣe iwadi ohun ti ó fẹ́ ṣẹlẹ̀ ki ó tó “kú sílẹ̀...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ọ̀dájú ló bi owó, ìtìjú ló bi igbèsè”: “Shrewdness gives birth to money...

Gẹ́gẹ́bí ọ̀rọ̀ Yorùbá ti ó ni “Iṣẹ́ ni oogun ìṣẹ́”, jẹ́ òtítọ́, bi òṣìṣẹ́ bá ri owó gbà ni àsìkò, tàbi gba ojú owó fún iṣẹ́ ti wọn ṣe.  Òṣìṣẹ́ ti ó ṣiṣẹ́ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ wákàtí/àkókò lórí owó kékeré, kò...

View Article
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live