ÌJÀPÁ JẸ ÈRÈ AIGBỌRAN ÀTI ÌWÀ Ọ̀KANJÚÀ: The Tortoise is Punished for not...
ÌJÀPÁ/Àjàpá JẸ ÈRÈ AIGBỌRAN ÀTI ÌWÀ Ọ̀KANJÚÀ: THE RESULT OF DISOBEDIENCE AND GREED The tragic Tortoise — having eaten food made for his wife by the Herbalist — there really should have been a warning...
View ArticleẸ̀rù ló sọ ọmọ Ẹkùn di Ológbò/Ológìní tó fi di ”Ẹran-àmúsìn –Ọdẹ...
Ni igbà àtijọ́, ẹranko ti wọn pè ni Ẹkùn jẹ alágbára ẹranko, bẹni Kìnìún si jẹ́ alágbára ẹranko. Bi Kìnìún ti lágbára tó ninú igbó, bi ó bá bú ramúramù, ohun gbogbo ninú igbó á...
View Article“Ọ̀run nyabọ̀, ki ṣé ọ̀rọ̀ ẹnìkan – Ayé Móoru” –“Heaven is collapsing, is...
Ọ̀run nyabọ̀ – Nature’s fury Ìbẹ̀rù tó gbòde ayé òde òni ni pé “Ayé Móoru”, nitori iṣẹ̀lẹ̀ ti o nṣẹlẹ̀ ni àgbáyé bi òjò àrọ̀ irọ̀ dá ni ilú kan, ilẹ̀-riru ni òmìràn, ọ̀gbẹlẹ̀,...
View ArticleÌgbéyàwó Ìbílẹ́ Yorùbá: “Ọ̀gá Méji Kò Lè Gbé inú Ọkọ̀” – Yoruba...
Adarí Ètò Ijoko àti “Adarí Ètò Ìdúró – Traditional Master of Ceremony. Courtesy: @theyorubablog A ṣe àkíyèsí pé wọn ti sọ iṣẹ́ ìyàwó-ilé di òwò nibi ìgbéyàwó ìbíl̀̀̀̀̀̀ẹ̀, pàtàki ni àwọn ilú nlá,...
View Article“Ẹ̀mí ti ò jata, ẹ̀mí yẹpẹrẹ”: “Life devoid of consumption of pepper is trifle”
Ata-ṣọmbọ, Ata-wẹ́wẹ́, Ata-Ijọsin, Ata gbigbẹ, Ata gígún àti awọn èlò ọbẹ̀ – Jalapeno, Serrano, Cayenne & various spices. Courtesy: @theyorubablog Ata ṣe pàtàki ninu àwọn èlò ọbẹ̀....
View Article“Ọ̀rẹ́ dani kò tó pọ́n, abínibí/ẹbi a má dani” –“It is not worth dwelling...
Kò si ibi ti ẹ̀tàn tàbi ká dani kò ti lè wá. Ẹni ti ó bá ni iwà burúkú bi: ojúkòkòrò, ìlara àti ìmọ-tara-ẹni nikan, lè dani tàbi tan-nijẹ. Ọmọ lè tan bàbá tàbi ìyá, ìyá tàbi...
View Article“Òjò tó rọ̀ ló mú pẹ̀tẹ̀pẹ́tẹ̀ wá”: Ìgbà Òjò dé – “It is the rain...
Pẹ̀tẹ̀pẹ́tẹ̀ Òjò – Much Mud “Òjò ibùkún lọ́dọ̀ ẹni kan, ni òjò ìbànújẹ́ lọ́dọ̀ ẹlòmíràn”. Lai si òjò, ọ̀gbẹlẹ̀ á wà, ọ̀gbẹlẹ̀ pi pẹ́ ló nfa iyàn. Inú àgbẹ̀ ma ndun ni àsikò...
View Article“Tani alãikàwé/alãimọ̀wé? Ẹnití ó lè kọ, tó lè kà Yorùbá kúrò ní...
Oriṣiriṣi ènìyàn miran tiki sọmọ Yorùbá pọ ni ìlú nla bi ti Èkó tàbí àwọn olú ìlù nla miran ni agbègbè ilẹ Yorùbá (fun àpẹrẹ: Abéòkúta, Adó-Èkìtì, Akurẹ, Ibadan, Oṣogbo, àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ). Gẹ́gẹ́bí...
View Article“Odò ti ó bá gbàgbé orisun gbi gbẹ ló ngbẹ” – “A river that forgets its...
Orúkọ idile Yorùbá ti ó nparẹ́ nitori èsìn. Àwọn orúkọ ìdílé wọnyi kò di ẹlẹ́sìn lọ́wọ́ lati ṣe iṣẹ́ rere tàbi dé ọ̀run, ENGLISH TRANSLATION Yoruba family names that are disappearing....
View ArticleẸGBẸ́́ YORÙBÁ NÍ ÌLÚỌBA: Finding Yoruba Food in the UK (Dalston Kingsland)
Yorùbá ní “Bí ewé bá pẹ́ lára ọṣẹ, á dọṣẹ”,ọ̀rọ̀ yí bá ẹgbẹ́ Yorùbá ni Ìlúọba mu pàtàkì àwọn ti o ngbe ni Olú Ìlúọba. Títí di bi ọgbọ̀n ọdún sẹhin, àti rí oúnjẹ Yorùbá rà...
View ArticleÀjàpá rẹ Erin sílẹ̀ – “Ìjàlọ ò lè jà, ó lè bọ́ ṣòkòtò ni idi...
Erin jẹ ẹranko ti Ọlọrun da lọ́lá pẹlu titobi rẹ ninu igbo. Yorùbá ni “Koríko ti Erin bá ti tẹ̀, àtẹ̀gbé ni láyé”, oko ti Erin bá wọ̀, olóko bẹ wọ igbèsè tori ibajẹ ti o ma ṣẹlẹ̀ si irú...
View ArticleÀgbo – Ewé àti Egbòigi fún ìtọ́jú – Yoruba Herbal remedies/Traditional...
Ki oògùn Òyinbó tó gbòde, ewé àti egbòigi ti ó wà ni oko tàbi àyíká ilé ni Yorùbá fi nki àgbo lati dí àisàn lọ́wọ́ tàbi wo àisàn. Àwọn gbajúmọ̀ àti ọ̀dọ́ ayé òde òni ti...
View ArticleOrukọ́ Ẹranko àti Àwòrán – Yoruba Names of Animals and pictures
Originally posted 2013-06-21 22:30:27. Republished by Blog Post Promoter
View Article“Bi a bá pẹ́ láyé, a ó jẹ ẹran ti o ́tó Erin” – “If one lives long...
Erin – Elephant Erin jẹ ẹran ti ó tóbi ju gbogbo ẹranko ti a mọ̀ si ẹran inú igbó àti ẹran-àmúsìn, ti a mọ̀ ni ayé òde òni. Bi a bá ṣe àyẹ̀wò bi Yorùbá ti ńgé ẹran ọbẹ̀, ó ṣòro lati...
View Article“Ilé là ńwò ká tó sọmọ lórúkọ” – Orúkọ ẹni ni ìfihàn ẹni: One...
Ọpọlọpọ ọmọ Yorùbá ti bẹ̀rẹ̀ si tijú lati jẹ orúkọ ti òbí fi èdè Yorùbá sọ wọn. Èyi tó bá tún gba lati jẹ orúkọ Yorùbá á tún bã jẹ ni kikọ tàbi ni pipè. Èwo ni ká kọ “Bayọ ni Bayor, Fẹmi...
View ArticleỌJỌ GBOGBO NI TI OLÈ – Everyday is for the thief … a warning to fraudsters
“ỌJỌ GBOGBO NI TI OLÈ, ỌJỌ KAN NI TOLÓHUN”: “EVERYDAY IS FOR THE THIEF, ONE DAY FOR THE OWNER”. Ní ọjọ Ẹti ọjọ keji lelogun oṣu keji ọdún yi, Ẹrọ amóhùn máwòrán Iluọba (BBC 1) tu asiri ọmọkunrin kan ti...
View Article“Iṣẹ́ loògùn ìṣẹ́” – “Work is the antidote for destitution/poverty”
http://www.theyorubablog.com/wp-content/uploads/2014/12/Iṣẹ́-Àgbẹ̀-ni-iṣẹ́-ilẹ̀-wa-Song-to-encourage-Farming.wav Orin fun Àgbẹ̀: Yoruba song encouraging farming: Iṣẹ́...
View ArticleOHUN TÍ́ A LÈRÍ NÍNÚ ÀTI ÀYÍKÁ ILÉ – BASIC YORUBA HOUSEHOLD ITEMS
YORÙBÁ ENGLISH YORÙBÁ ENGLISH Àwo pẹrẹsẹ Plates Ṣíbí Spoon Abọ́ Dish Ọ̀bẹ Knife Ago Cup Ìgò Omi Water Bottle Aago Clock Ìkòkò Omi Water Pot Aṣọ Clothes Omi Water Oúnjẹ Food Ibi Ìdáná Kitchen...
View ArticleJọ mi, Jọ mi, Òkúrorò/Ìkanra ló ndà – Insisting on people doing things...
Yorùbá ni “Bi Ọmọdé ba ṣubú á wo iwájú, bi àgbà ba ṣubú á wo ẹ̀hìn”. Bi enia bá dé ipò àgbà, pàtàki gẹ́gẹ́ bi òbí, àgbà ìdílé tàbi ọ̀gá ilé iṣẹ́, ẹni ti ó bá ni ìfẹ́ kò ni...
View Article“Ọgbọ́n ju agbára”: Ìjàpá mú Erin/Àjànàkú wọ ìlú – “Wisdom is greater than...
Ni ìlú Ayégbẹgẹ́, ìyàn mú gidigidi, eleyi mu Ọba ìlú bẹ̀rẹ̀ si sá pamọ́ fún àwọn ará ìlú nitori kò mọ ohun ti ohun lè ṣe. Òjò kò rọ̀ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún, oorun gbóná janjan, nitorina, kò si ohun...
View Article