Quantcast
Channel: The Yoruba Blog
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live

“Orúkọ ti òbi Yorùbá nsọ Àbíkú” – “Yoruba parental names associated...

(Olóògbé Ọ̀jọ̀gbọ́n Olikoye Ransome Kuti – Oníṣègùn-Ọmọdé ti gbogbo àgbáyé mọ̀, Òjíṣẹ́-Òṣèlú Nigeria ni ọdún keji-din-lọ́gbọ̀n si ọdún keji-lé-lógún sẹhin, ṣe irànlọ́wọ́ gidigidi...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ìtàn àròsọ bi obinrin ti sọ Àmọ̀tékùn di alábàwọ́n: The Folklore on...

Ni igba kan ri, Àmọ̀tékùn ni àwọ̀ dúdú ti ó jọ̀lọ̀, ṣùgbọ́n ni ọjọ́ kan, Àmọ̀tékùn wá oúnjẹ õjọ́ rẹ lọ.  Ó dé ahéré kan, ó ṣe akiyesi pe obinrin kan ńwẹ̀, inú rẹ dùn púpọ̀ pé...

View Article


Bi Irọ́ bá lọ fún Ogún Ọdún, Òtítọ á ba Lọ́jọ́ Kan – Ìbò Ọjọ́ Kejilá...

Lẹhin ọdún mẹẹdọgbọn ti Ijoba Ologun Ibrahim Babangida fagilé ìbò ti gbogbo ilú dì lai si ìjà tàbi asọ̀ tó gbé Olóògbé Olóyè Moshood Káṣìmáawòó Ọláwálé Abíọ́lá wọlé, Ìjọba...

View Article

“Ọ̀rẹ́ dani kò tó pọ́n, abínibí/ẹbi a má dani” –“It is not worth dwelling...

Kò si ibi ti ẹ̀tàn  tàbi ká dani kò ti lè wá.  Ẹni ti ó bá ni iwà burúkú bi: ojúkòkòrò, ìlara àti ìmọ-tara-ẹni nikan, lè dani tàbi tan-nijẹ. Ọmọ lè tan bàbá tàbi ìyá, ìyá tàbi...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Wọn mbẹ Oníṣègùn, wọn ò bẹ Aláìsàn” – “Pleading with the Doctor without...

Yorùbá ma nlo òwe yi nigbati èniyàn bá ṣẹ̀ tàbi ṣe nkan burúkú si ẹni keji, ti wọn bẹ̀rẹ̀ si bẹ ẹni ti wọn ṣẹ̀ lai mọ bóyá ẹni ti ó ṣẹ̀ ni àyipadà ọkàn kúrò ni iwà ìbàjẹ́ tàbi iṣẹ́...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“A kì í fi Oníjà sílẹ̀ ká gbájúmọ́ alápepe – Pí pa Àjòjì ni Gúsù...

Pí pa Àjòjì ni Gúsù ilẹ̀ Aláwọ̀-dúdú – South Africa’s xenophobic attacks Òwe Yorùbá kan sọ pé “Amúkun, ẹrù ẹ́ wọ́, ó ni ẹ̃ wò ìsàlẹ̀”.  Òwe yi ṣe é lò lati ṣe àyẹ̀wò ìṣẹ̀lẹ̀ pí pa...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Owó orí ìyàwó –“Bíbí ire kò ṣe fi owó ra”: Bride Price – “Good pedigree...

OWO NAIRA Bi ọkọ ìyàwó bà ti lówó tó ni ó ti lè fi owó si inú àpò ìwé fún owó orí àti àwọn owó ẹbi yókù.  Ni ayé òde òní, owó fún àpò ìwé méjìlá wọnyi lè bẹ̀rẹ̀ lati...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ìmọ́tótó borí àrùn mọ́lẹ̀, bi ọyẹ́ ti ḿborí ooru” –“Cleanliness...

http://www.theyorubablog.com/wp-content/uploads/2014/07/Imototo.wav Ìmọ́tótó borí àrùn mọlẹ̀, bọ́yẹ́ ti ḿborí ooru Àrùn ìwọ̀sí tinú ẹ̀gbin là wá Iná ni ḿborí aṣọ ẹlẹ́gbin Ni ayé àtijọ́...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ẹni tó Lórí kò ní Fìlà, Ẹni tó ní Fìlà kò Lórí”: “The one who has a...

Fìlà Aṣọ Òfì – Traditional Yoruba CapCourtesy: @theyorubablog.com Ọ̀rọ̀ Yorùbá ní “Ẹni tó Lórí kò ní Fìlà, Ẹni tó ní Fìlà kò Lórí”. Tani eni “Ẹni tó Lórí ti kò ní Fila”?  Enití gbogbo...

View Article


“Bibi ire kò ṣe fi owó rà – Yoruba names” – “Good pedigree cannot be...

Kò di igbà ti enia bá ni owó rẹpẹtẹ ki ó tó sọ ọmọ rẹ ni “Ọlá” nitori Yorùbá ka ipò giga, ọmọ, ilera, orúkọ rere si “Ọlá”.  Ibi ti “Ọlá” wà ninú orúkọ Yorùbá, a lè lo “Adé; Ibi;...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ìfẹ́ kò fọ́jú, ẹni ti ó wọnú ìfẹ́ ló fọ́jú: ‘Igbéyàwó ki ṣe ọjà...

Ni ayé àtijọ́, ki òbí tó gbà lati fi ọmọ fún ọkọ, wọn yio ṣe iwadi irú iwà àti àìsàn ti ó wọ́pọ̀ ni irú idile bẹ́ ẹ̀.  Nitori eyi, igbéyàwó ibilẹ̀ ayé  àtijọ́ ma npẹ́ ju ti ayé òde...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ìránti Aadọta Ọdún ti Ọ̀gágun Adékúnlé Fájuyi fi ara rẹ ji fún...

Yorùbá fẹ́ràn àlejò púpọ̀.  Ìwà ti ọmọ ilú lè hù ti yio fa ibinú, bi àlejò bá hu irú ìwà bẹ́ ẹ̀, wọn yio ni àlejò ni, ki wọn fori ji i.  Òwe Yorùbá ti ó sọ wi pé “Ojú àlejò...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ẹrù fún Ìgbéyàwó Ìbílẹ̀”–“Traditional Bridal List”

Apá Kini – Part One Gifts at a modern Yoruba Traditional wedding — courtesy of @theYorubablog  Ìnáwó nla ni ìgbéyàwó ìbílẹ̀, ṣùgbọ́n gẹ́gẹ́ bi òwe Yorùbá “Bi owó ti mọ ni oògùn nmọ”, bi agbára ọkọ...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ìtàn bi Ìjàpá ti fa Àkóbá fún Ọ̀bọ: Ẹ Ṣọ́ra fún Ọ̀rẹ́ Burúkú”–...

Ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ itàn Yorùbá, Ìjàpá jẹ ọ̀lẹ, òbùrẹ́wà, kò tóbi tó àwọn ẹranko yoku, ṣùgbọ́n ó ni ọgbọ́n àrékérekè ti ó fi ngbé ilé ayé. Ò̀we Yorùbá sọ wi pé, “Iwà jọ iwà, ni...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ààntéré ọmọ Òrìṣà-Omi – “Ọmọ o láyọ̀lé, ẹni ọmọ sin lo bimọ”: Aantere...

Yorùbá ka ọmọ si ọlá àti iyì ti yio tọ́jú ìyá àti bàbá lọ́jọ́ alẹ́.  Eyi han ni orúkọ ti Yorùbá nsọ ọmọ bi: Ọmọlọlá, Ọmọniyi, Ọmọlẹ̀yẹ, Ọmọ́yẹmi, Ọlọ́mọ́là, Ọlọ́mọlólayé, Ọmọdunni,...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Àjàpá fẹ́ kó bá Ajá – Kàkà ki eku májẹ sèsé, á fi ṣe àwàdànu” –...

Ajá dúró dèmί lọna, fẹrẹ kun fẹ 2ce Bί ὸ bá dúró dèmί lọna fẹrẹ kun fẹ Makékéké Olóko á gbọ fẹrẹ kun fẹ Á gbọ á gbéwa dè, fẹrẹ kun fẹ Á gbéwa dè, á gbàwá nίṣu fẹrẹ kun fẹ Ajá dúró dèmί lọna, fẹrẹ kun...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ọwọ́ Ọmọdé Kòtó Pẹpẹ, Tagbalagba Ò Wọ Kèrègbè: The Child’s Hand Cannot...

Only a child’s hand can reach into this type of calabash. The image is from Wikipedia. Ọ̀rọ̀ Yorùbá sọ wípé “ọwọ́ ọmọde ko to pẹpẹ, tagbalagba ko wọ̀ kèrègbè”, èyí tí a lè túmọ̀ sí wípé,...

View Article


Jọ mi, Jọ mi, Òkúrorò/Ìkanra ló ndà – Insisting on people doing things...

Yorùbá ni “Bi Ọmọdé ba ṣubú á wo iwájú, bi àgbà ba ṣubú á wo ẹ̀hìn”.  Bi enia bá dé ipò àgbà, pàtàki gẹ́gẹ́ bi òbí, àgbà ìdílé tàbi ọ̀gá ilé iṣẹ́, ẹni ti ó bá ni ìfẹ́ kò ni...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

ÀṢÀ ÌDÁBẸ́: A Culture of Female Genital Mutilation #IWD

Ìdábẹ́ jẹ ìkan nínú àṣà Yorùbá tí ólòdì si ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin.  Gẹ́gẹ́bí ìtàn ìdábẹ́, Yorùbá ndabẹ fún ob̀nrin ní àti ìkókó títí dé ọmọ ọdún kan,  nwọn ní ìgbàgbọ́ wipe yio da ìṣekúṣe dúró lára...

View Article

Wi wé Gèlè Ìgbàlódé – How to tie Modern Head Scarfs

Originally posted 2015-07-07 19:41:40. Republished by Blog Post Promoter

View Article
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live