“Odò ti ó bá gbàgbé orisun gbi gbẹ ló ngbẹ” – “A river that forgets its...
Orúkọ idile Yorùbá ti ó nparẹ́ nitori èsìn. Àwọn orúkọ ìdílé wọnyi kò di ẹlẹ́sìn lọ́wọ́ lati ṣe iṣẹ́ rere tàbi dé ọ̀run, ENGLISH TRANSLATION Yoruba family names that are disappearing....
View Article“A kì í fi Oníjà sílẹ̀ ká gbájúmọ́ alápepe – Pí pa Àjòjì ni Gúsù...
Pí pa Àjòjì ni Gúsù ilẹ̀ Aláwọ̀-dúdú – South Africa’s xenophobic attacks Òwe Yorùbá kan sọ pé “Amúkun, ẹrù ẹ́ wọ́, ó ni ẹ̃ wò ìsàlẹ̀”. Òwe yi ṣe é lò lati ṣe àyẹ̀wò ìṣẹ̀lẹ̀ pí pa...
View Article“Iwájú lèrò mbá èrò – Kò si ohun téni kan ṣe, téni kò ṣe ri” –...
Ọ̀rọ̀ ijinlẹ àti Òwe Yorùbá wà lati fi kọ́ ọgbọ́n àti imò bi èniyàn ti lè gbé igbésí ayé rere. Ọ̀gá àgbà ninú Olórin ilẹ̀ aláwọ̀-dúdú (Olóyè, Olùdarí Ebenezer Obey) kọ ninú...
View Article“Ọ̀rẹ́ dani kò tó pọ́n, abínibí/ẹbi a má dani” –“It is not worth dwelling...
Kò si ibi ti ẹ̀tàn tàbi ká dani kò ti lè wá. Ẹni ti ó bá ni iwà burúkú bi: ojúkòkòrò, ìlara àti ìmọ-tara-ẹni nikan, lè dani tàbi tan-nijẹ. Ọmọ lè tan bàbá tàbi ìyá, ìyá tàbi...
View ArticleIMULO ÒWE YORUBA: APPLYING YORUBA PROVERBS
“A NGBA ÒRÒMỌDÌYẸ LỌWỌ IKÚ O NI WỌN O JẸ KI OHUN LỌ ATAN LỌJẸ” A le lo òwe yi lati kilọ fun ẹni to fẹ lọ si Òkèokun (Ìlu Òyìnbó) lọna kọna lai ni ase tabi iwe ìrìnà. Bi ẹbi, ọrẹ tabi ojulumọ to mọ...
View Article“Òjò tó rọ̀ ló mú pẹ̀tẹ̀pẹ́tẹ̀ wá”: Ìgbà Òjò dé – “It is the rain...
Pẹ̀tẹ̀pẹ́tẹ̀ Òjò – Much Mud “Òjò ibùkún lọ́dọ̀ ẹni kan, ni òjò ìbànújẹ́ lọ́dọ̀ ẹlòmíràn”. Lai si òjò, ọ̀gbẹlẹ̀ á wà, ọ̀gbẹlẹ̀ pi pẹ́ ló nfa iyàn. Inú àgbẹ̀ ma ndun ni àsikò...
View ArticleỌwọ́ Ọmọdé Kòtó Pẹpẹ, Tagbalagba Ò Wọ Kèrègbè: The Child’s Hand Cannot...
Only a child’s hand can reach into this type of calabash. The image is from Wikipedia. Ọ̀rọ̀ Yorùbá sọ wípé “ọwọ́ ọmọde ko to pẹpẹ, tagbalagba ko wọ̀ kèrègbè”, èyí tí a lè túmọ̀ sí wípé,...
View ArticleIjẹbu lo ni Ìfọ́kọrẹ́/Ìkọ́kọrẹ́ gbogbo Yorùbá ló ni Ọ̀jọ̀jọ̀ – Water Yam...
Ẹ ṣe àyẹ̀wò bi a ti ńṣe Ọ̀jọ̀jọ̀ lójú iwé yi. Fọ Iṣu Ewùrà kan Bẹ ewùrà yi Rin iṣu yi (pẹ̀lú pãnu ti a dálu lati fi rin gãri, ilá tàbi ewùrà) Po iyọ̀ àti iyọ̀ igbàlódé, ata gigún...
View Article“Kò si ohun a nfi ọ̀gẹ̀dẹ̀ ṣe ni Ijeṣa, ẹiyẹ ló njẹ́” – Oú́njẹ ti a lè fi...
Iyán ni oúnjẹ gidi fún Ijẹṣa, nitori wọn ni iṣu ju ọ̀gẹ̀dẹ̀ lọ. Òwe àtijọ́ ni pé “Kò si ohun a nfi ọ̀gẹ̀dẹ̀ ṣe ni Ijeṣa, ẹiyẹ ló njẹ́” nitori ọ̀pọ̀ ohun ni a lè fi ọ̀gẹ̀dẹ̀ ṣe, ni ayé òde...
View Article“Ọba Aládélúsi Ògúnladé-Aládétóyìnbó gun Ori Oyè ilu Àkúrẹ́” –...
Déjì Àkúrẹ́ Ọba Aládélúsi Ògúnladé-Aládétóyìnbó pari gbogbo ètùtù ibilẹ ti Ọba Àkúrẹ́ ma nṣe lati gori oyè ni Ọjọ́rú, ọjọ́ kẹjọ, oṣù keje, ọdún Ẹgbãlemẹ̃dógún, lati di Ọba...
View Article“Bi a bá tori ẹni burúkú fọ́jú, a kò ni ri ojú ri ẹni rere” – “If one...
Kò si ilú, ẹ̀yà tàbi àwọ̀ ti kò ni ẹni burúkú tàbi ẹni rere. Àti ẹni burúkú àti ẹni rere ló wà ninú ẹbi, ilú, àti gbogbo ẹ̀yà àgbáyé ninú èniyàn dúdú àti funfun, ọkùnrin,...
View ArticleÀgbo Ibà – Malaria Herbal Decoction
Àgbo Ibà – Malaria Herbal Decoction Ibà jẹ ikan ninú àwọn àrùn tó pa àwọn èniyàn jù ni àwọn orilẹ̀-èdè Ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ Aláwọ̀dúdú. Yorùbá ti ńlo ewé àti egbò igi ti ó wà...
View Article“Bi ojú bá mọ́, Agbe á yalé Aláró, Àlùkò á yalé Olósùn,...
Bi a bá wo òwe yi, a o ri pe Agbe pọn bi aró, Àlùkò pupa bi osùn nigbati Lékeléke funfun bi ẹfun. Nitori eyi, bi wọn kò ti ẹ̀ lọ si ilé Aláró, Olósùn àti Ẹlẹ́fun, àwọ̀ wọn á si wa...
View ArticleOrúkọ Ẹranko a fàyà fà tabi jomijòkè ni èdè Yorùbá: Names of...
Gẹgẹbi àpè júwe, ẹranko a fàyà fà jẹ ẹranko ti ó ni àwọ̀, omiran ni oro, omiran ni ikarawun, wọn si ńyé ẹyin. Bi Ejò, àti Ákẽke ti ni oró bẹ̃ ni Àjàpá àti Ìgbín ni ikarawun. Fún...
View ArticleATỌ́NÀ LÉDÈ YORÙBÁ – Cardinal Directions in Yoruba
A compass showing the poles in Yoruba language. The image is courtesy of @theyorubablog Originally posted 2013-04-16 19:01:07. Republished by Blog Post Promoter
View ArticleÀjàpá àti Ọmọdé Mẹta – “Ẹnu àìmẹ́nu, ètè àìmétè, ló́ nmú ọ̀ràn bá ẹ̀rẹ̀kẹ́” –...
Ni abúlé Yorùbá nigbati ko ti si ẹ̀rọ asọ̀rọ̀-mágbèsì tabi ẹ̀rọ amú-òhùn-máwòrán àti ẹ̀rọ ayélujára, àwọn ọmọdé má nkó ara jọ lati ṣe eré lẹhin iṣẹ́ oojọ Bàbá àti Ìyá wọn. Pataki, ni igba ọ̀gbẹlẹ̀...
View ArticleỌ̀tún wẹ Òsì, Òsì wẹ Ọ̀tún, Lọwọ́ fi Nmọ: Right Washing The Left & The...
There is a Yoruba saying that, the right hand washes the left, and the left washes the right for clean hands. Image is courtesy of Microsoft Free Images. Àṣà àtọwọ́dọ́wọ́, ọwọ́ ni a fi njẹ...
View ArticleJọ mi, Jọ mi, Òkúrorò/Ìkanra ló ndà – Insisting on people doing things...
Yorùbá ni “Bi Ọmọdé ba ṣubú á wo iwájú, bi àgbà ba ṣubú á wo ẹ̀hìn”. Bi enia bá dé ipò àgbà, pàtàki gẹ́gẹ́ bi òbí, àgbà ìdílé tàbi ọ̀gá ilé iṣẹ́, ẹni ti ó bá ni ìfẹ́ kò ni...
View Article“Bàbá Ìtàn Ìkọ̀lé-Èkìtì, Olóògbé Ọj̀ọ̀gbọ́n-Àgbáyé Adé Àjàyí...
http://www.theyorubablog.com/wp-content/uploads/2014/09/Baba-rele-Burial-of-an-elders-song.wav Babá re lé ò, Ilé ló lọ́ tarà-rà Bàbá re lé ò, Ilé ló lọ́ tarà-rà Ilé ò, ilé, Ilé ò,...
View ArticleẸ̀kọ́ àti Ọgbọ́n ni Ọ̀rọ̀ Àgbà lati Ẹnu Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọmọlolú Olunlọyọ lórí...
Bi a ba fi eti si ọ̀rọ̀ ti àgbà Yorùbá Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọmọlolú Olunlọyọ ni ori ẹ̀rọ “Amóhùnmáwòrán Òpómúléró”, ni ori ayélujára, a o ṣe àkíyèsí àwọn nkan wọnyi:...
View Article