“A ò mọ èyi ti Ọlọrun yio ṣe, kò jẹ́ ki á binú kú” – “We know not what...
Àṣà Yorùbá ma ńri ọpẹ́ ninú ohun gbogbo, nitori eyi ni àjọyọ̀ àti ayẹyẹ ṣe pọ ni ilẹ̀ Yorùbá. Bi kò bá ṣe ayẹyẹ igbéyàwó; á jẹ́ idúpẹ́ fun ikómọ/isọmọlórúkọ; ìsìnku arúgbó;...
View Article“Ṣòkòtò àgbàwọ̀, bi kò ṣoni lẹsẹ á fúnni nítan”: “A borrowed trouser/pant, if...
Ìwà àti ìṣe ọ̀dọ́ ìgbàlódé, kò fi àṣà àti èdè Yorùbá hàn rárá. Aṣọ àlòkù ti gbòde, dipò aṣọ ìbílẹ̀. Ọpọlọpọ aṣọ àgbàwọ̀ yi kò wà fún ara àti lilò ni ilẹ̀ aláwọ̀-dúdú. Ọ̀dọ́ miran a wọ asọ àti bàtà...
View ArticleWi wé Gèlè Ìgbàlódé – How to tie Modern Head Scarfs
Originally posted 2015-07-07 19:41:40. Republished by Blog Post Promoter
View ArticleTọ́jú Ìwà Rẹ Ọ̀rẹ́ Mi – Ọ̀rọ̀-orin lati Ìwé Olóògbé Olóyè J.F....
Ọ̀rọ̀-orin yi jẹ ikan ninú àwọn àkọ́-sórí ni ilé-ìwé alakọbẹrẹ ni ilẹ̀ Yorùbá ni igbà ti ile-iwe àpapọ̀ yè koro. Ṣùgbọ́n ni ayé òde òni, ti gbogbo ilé-ìwé ti kọ èdè abínibí silẹ̀,...
View ArticleATỌ́NÀ LÉDÈ YORÙBÁ – Cardinal Directions in Yoruba
A compass showing the poles in Yoruba language. The image is courtesy of @theyorubablog Originally posted 2013-04-16 19:01:07. Republished by Blog Post Promoter
View ArticleWelcome to the Yoruba Blog…
The home of all things Yoruba… news, commentary, proverbs, food. Keeping the Yoruba culture alive. Originally posted 2013-01-24 21:03:41. Republished by Blog Post Promoter
View Article“Ọ̀rẹ́ dani kò tó pọ́n, abínibí/ẹbi a má dani” –“It is not worth dwelling...
Kò si ibi ti ẹ̀tàn tàbi ká dani kò ti lè wá. Ẹni ti ó bá ni iwà burúkú bi: ojúkòkòrò, ìlara àti ìmọ-tara-ẹni nikan, lè dani tàbi tan-nijẹ. Ọmọ lè tan bàbá tàbi ìyá, ìyá tàbi...
View ArticleẸNITÍ ỌLỌRU KÒ DÙN NÍNÚ TÓ NLA ṢÚGÀ, JẸ̀DÍJẸ̀DÍ LÓ MA PÁ: WHOEVER GOD HAS NOT...
Yorùbá ní “Ẹnití Ọlọrun kò dùn nínú, tó nla ṣúgà (iyọ̀ ìrèké), jẹ̀díjẹdí ló ma pá”. Ọ̀rọ̀ Yorùbá yi ṣ̀e àtìlẹhìn fún iwadi tó fihàn wípé ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ti ìrẹ̀wẹ̀sì mbaja ma mu ọtí àti jẹ oúnje...
View Article“Ránti Ọmọ Ẹni ti Iwọ Nṣe: Olè ki ṣe Orúkọ Rere lati fi Jogún” –...
Oriṣiriṣi òwe ni Yorùbá ni lati fihàn pé iwà rere ló ni ayé. Iwà ni Yorùbá kàsí ni ayé àtijọ́ ju owó ti gbogbo ilú bẹ̀rẹ̀ si bọ ni ayé òde òni. Fún àpẹrẹ, Yorùbá ni “Ẹni bá...
View Article“Ìsọ̀rọ̀ ni igbèsi: Ibere ti ó wọ́pọ́ ni èdè Yorùba” – “Questions calls...
Ọpọlọpọ ibere ni èdè Yorùbá bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lu “ọfọ̀ – K”. Yàtọ̀ fún li lò ọfọ̀ yi ninú ọ̀rọ̀, orúkọ enia tàbi ẹranko, ọfọ̀ yi wọ́pọ̀ fún li lò fún ibere. Fún àpẹrẹ, orúkọ enia ti ó bẹ̀rẹ̀...
View ArticleIṣẹ́ ni oògùn ìṣẹ́ – Hard-work is a cure for poverty
Ẹ ṣe àyẹ̀wò ìwé akéwì-orin ni èdè Yorùbá ti àwọn ọmọ ilé-ìwé n kọ́ sórí ni ilé-ìwé ilẹ̀ Yorùbá ni ayé àtijọ: Iṣẹ́ ni oògùn ìṣẹ́, múra si iṣẹ́ rẹ ọ̀rẹ́ mi, iṣẹ́ ni a fi i di ẹni...
View Article“Gbogbo ohun tó ndán kọ́ ni Wúrà” – “Not all that glitters is Gold”
Wúrà jẹ ikan ninú ohun àlùmọ́ni iyebiye, pàtàki fún ohun ẹ̀ṣọ́. Ẹwà Wúrà ki hàn, titi di ìgbà ti wọn bá yọ gbogbo ẹ̀gbin rẹ̀ kúrò pẹ̀lú iná tó gbóná rara. Àwòrán ti ó wà...
View ArticleÀròkàn ló n fa ẹkún à sun à i dákẹ́: Anguish of mind is the root...
Ohun ti Yorùbá mọ̀ si àròkàn n irònú igbà gbogbo. Kò si ẹni ti ki ronú, ṣùgbọ́n àròkàn léwu. Inú rirò yàtọ si àròkàn. Inu rirò ni àwọn Onimọ-ijinlẹ̀ lò lati ṣe ọkọ̀ òfúrufú...
View Article“Iṣẹ́ ajé, sọ ọmọ nù bí òkò” –“Working for survival throws away the child...
Ọjọ́ ti pẹ́ ti Yorùbá ti ńkúrò ni ilú kan si ilú keji, yálà fún ọrọ̀ ajé tàbi fún ẹ̀kọ-kikọ́. Ni ayé àtijọ́, ọjọ́ pípẹ́ ni wọn fi ńrin irin-àjò nitori irin ti ọkọ̀ òfúrufú lè...
View Article“Ará Ilú Nigeria: “Fi Ẹ̀tẹ̀ silẹ̀ pa Làpálàpá” – Nigerians are:...
Ẹ̀tẹ̀ tó mbá ilú jà ni ‘iwà-ibàjẹ́’. Ìyà ti ará ilú njẹ lọ́wọ́lọ́wọ́, ki i ṣe èrè iwà-ibàjẹ́ ọdún kan, ṣùgbọ́n ti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún. Kò si ìfẹ́ ilú, nitori eyi, àwọn oniwà ibàjẹ́...
View ArticleỌ̀dọ́ Kọ̀yà Ọlọpa orílẹ̀-èdè Nigeria – Nigeria Youths protest Police...
Ọlọpa ti fi iyà jẹ ará ilú fún igbà pípẹ́, nitori iwà-ibàjẹ́ àti gbi gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ ni iṣẹ́ Ọlọpa àti ni orilẹ̀-èdè Nigeria. Ọlọpa ti tori àti gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ fi iyà jẹ ọlọ́jà, àgbẹ,...
View Article“Ọ̀run nyabọ̀, ki ṣé ọ̀rọ̀ ẹnìkan – Ayé Móoru” –“Heaven is collapsing, is...
Ọ̀run nyabọ̀ – Nature’s fury Ìbẹ̀rù tó gbòde ayé òde òni ni pé “Ayé Móoru”, nitori iṣẹ̀lẹ̀ ti o nṣẹlẹ̀ ni àgbáyé bi òjò àrọ̀ irọ̀ dá ni ilú kan, ilẹ̀-riru ni òmìràn, ọ̀gbẹlẹ̀,...
View Article“Ti ibi, ti ire la wá ilé ayé” –Ọ̀rọ̀ àti Ìṣe Ìgboro ni Èkó: “We came into...
Èkó jẹ́ olú ìlú Nigeria fún ọpọlọpọ ọdún, ki wọn tó sọ Abuja di olú ìlú Nigeria, ṣùgbọ́n Èkó ṣi jẹ́ olú ìlú fún iṣẹ ọrọ̀ gbogbo Nigeria. Nitori eyi, gbogbo ẹ̀yà Nigeria àti àwọn ará ìlú miran titi dé...
View ArticleORÚKỌ ỌJỌ́: Days of the Week in Yoruba
Below are the Yoruba days of the week. Of course it is worth noting that very few native Yoruba speakers use these words in conversation. SUNDAY ÀÌKÚ MONDAY...
View Article“Ai jẹun Ológbò kọ́ ni kò jẹ́ kó tó Ajá, bẹni ki ṣe ai jẹun Ajá ni kò...
Àsè “Ọjọ́ Ọpẹ́” – Thanksgiving buffet table Fún àwọn ti ó wà ni òkè-òkun – America, wọn ni ọjọ́ ti wọn ya si ọ̀tọ̀ gẹ́gẹ́ bi “Ọjọ́ Ọpẹ́”. Oúnjẹ pọ rẹpẹtẹ ni àsikò yi pàtàki ni “Ọjọ́...
View Article