Òjò nrọ̀ si kòtò, gegele mbinú – The rain is filling up the gully to the...
Ójò rẹpẹtẹ – Heavy rain Bi inú ọpọ ti ndùn, ni inú ẹlòmíràn mbàjẹ́ ni àsikò òjò. Yorùbá ni orin fún igbà ti kò ba si òjò, igbà ti òjò bá ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ si rọ̀, tàbi ti ó bá...
View Article“Orin ẹ̀kọ́ lati bọ̀wọ̀ fún òbí ni ilé-ìwé alakọbẹrẹ”: Primary School...
Orin yi ni Olùkọ́ ma fi ńkọ́ àwọn ọmọ ilé-ìwé alakọbẹrẹ nigbà “ilé-ìwé ọ̀fẹ́” ti àwọn Òṣèlú ilẹ̀ Yorùbá ti Olóyè Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ ṣe olórí rẹ. Ni ayé ìgbà wọnyi, ọ̀pọ̀lọpọ̀ òbí...
View Article“Ojú ọ̀run tó ẹyẹ fò lai fi ara gbọ́n ra” – “The sky is wide enough for...
Ẹ̀sìn ti wa láyé, ki ẹ̀sìn Ìgbàgbọ́ àti Mùsùlùmi tó dé. Fún àpẹrẹ, Yorùbá gbàgbọ́ ninú “Ọlọrun” ti Yorùbá mọ̀ si “Òrìṣà-òkè” tàbi “Eledumare”. Bi Yorùbá ṣe ḿbá Ọlọrun...
View ArticleNi Iránti Bàbá Ẹgbẹ́ Òṣèré Nigeria: Olóògbé Olóyè Hubert Adédèji...
Ẹbi, ará, iránṣẹ́ Ìjọba àti àwọn ọmọ Olóògbé Olóyè Hubert Adédèji Ogunde pé jọ ni ọjọ́ kẹrinlélógún oṣù kẹrin ọdún Ẹgbãlemẹ̃dógún, ni ilú Ìjẹ̀bú Ọ̀sọ̀sà ti ipinlẹ̀ Ògùn lati...
View ArticleBi Ọdẹ bá ro ìṣẹ́ ro ìyà inú igbó, ti ó bá pa ẹran kòní fẹ́nì kan jẹ – If the...
Ọlọ́dẹ/Ọdẹ – Hunter Láyé àtijọ́, iṣẹ́ Ọdẹ jẹ ikan ninú iṣẹ gidi ni ile Yorùbá. Ògbójú Ọdẹ ló npa ẹranko bi Erin, Ẹkùn, Kìnìún àti Ẹfòn, Ìmàdò, Ikõkò, nígbàtí àwọn to nṣe Ọdẹ etílé npa ẹranko ìtòsí ilé...
View ArticleẸ̀̀ya orí ni èdè Yorùbá – Parts of Head in Yoruba Language
Orúkọ ẹ̀yà ara ṣe pàtàkì lati mọ nípa kíkọ́ èdè nítorí ó ma nwà nínú ọ̀rọ̀. Mí mọ awọn orúkọ wọnyi á́ tún jẹ ki èdè Yorùbá yé àwọn ti ó ni ìfẹ́ lati kọ èdè. A lérò wípé àwòrán àti pípè tí ó wà ni...
View Article“Iṣẹ́ loògùn ìṣẹ́” – “Work is the antidote for destitution/poverty”
http://www.theyorubablog.com/wp-content/uploads/2014/12/Iṣẹ́-Àgbẹ̀-ni-iṣẹ́-ilẹ̀-wa-Song-to-encourage-Farming.wav Orin fun Àgbẹ̀: Yoruba song encouraging farming: Iṣẹ́...
View Article“Àpẹrẹ Ẹrú ati Owó Àna fún Ìtọrọ Iyàwó ni Idilé Arinmájàgbẹ̀” –...
Gẹ́gẹ́ bi a ti kọ tẹ́lẹ̀, ẹrù àti owó àna yàtọ̀ lati idilé kan si ekeji, ṣùgbọ́n àwọn ohun àdúrà bára mu ni ilẹ̀ Yorùbá pàtàki Oyin, Obi, Ataare, Orógbó. Fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹbi...
View ArticleÌkini Ọdún Ẹgbàálélógún – 2020 Yoruba Season Greetings
Originally posted 2020-01-02 02:46:36. Republished by Blog Post Promoter
View Article“Ẹni bá wá iwa-kuwa, ojú rẹ á ri irikuri” – Ìtàn bi imú Erin ti di...
Ni igbà kan ri, imú Erin dàbi ti àwọn ẹranko tó kù ni, ṣùgbọ́n Erin fi aigbọ tara ẹni, di o ni imú gigùn. Gbogbo nkan tó nlọ ni ayé àwọn ẹranko yoku ni Erin fẹ tọpinpin rẹ. Yorùbá ni...
View Article“Òjò tó rọ̀ ló mú pẹ̀tẹ̀pẹ́tẹ̀ wá”: Ìgbà Òjò dé – “It is the rain...
Pẹ̀tẹ̀pẹ́tẹ̀ Òjò – Much Mud “Òjò ibùkún lọ́dọ̀ ẹni kan, ni òjò ìbànújẹ́ lọ́dọ̀ ẹlòmíràn”. Lai si òjò, ọ̀gbẹlẹ̀ á wà, ọ̀gbẹlẹ̀ pi pẹ́ ló nfa iyàn. Inú àgbẹ̀ ma ndun ni àsikò...
View Article“Àbíkú sọ Olóògùn di èké” – “Child mortality mis-portray the...
Ìgbàgbọ́ Yorùbá yàtọ̀ si ohun ti àwọn Ẹlẹko-Ijinlẹ fi hàn ni ayé òde òni. Ni igbà àtijọ́, bi obinrin/iyàwó bá bi ọmọ, ti ó kú ni ikókó tàbi ki ó tó gba àbúrò, ọmọ ti wọn bá...
View ArticleLADÉJOMORE – How Babies Lost Their Ability to Speak
A SAMPLE OF AN EKITI VARIANT OF THE FOLK TALE “LADÉJOMORE” Ọmọ titun – a baby Courtesy: @theyorubablog Ladéjomore Ladéjomore1 Èsun Oyà* Ajà gbusi Èsun Oyà ‘lé fon ‘ná lo 5 Èsun Iy’uná k ó ti l’éin Èsun...
View ArticleKò si ọgbọ́n to lè dá, kò si ìwà ti o lè hù, ti o lè fi tẹ́ aiyé...
Oni – kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ – The Horseman & his son Ni aiyé àtijọ́, ẹsin àti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ló dàbi ọkọ̀ igbàlódé ti wọn ńpè ni mọ́tò. Ẹni ti ó jẹ́ ọlọ́rọ̀, ló lè ni ẹsin tàbi kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́....
View ArticleÌtẹ́lọ́rùn ni Baba Ìwà – Contentment is the Father of Character
Àìní ìtẹ́lọ́rùn ló bí gbogbo ìwà burúkú bi: irọ́ pípa, olè jíjà, àgbèrè, ojúkòkòrò àti bẹ̃bẹ lọ. Àìní ìtẹ́lọ́rùn ló wà ni ìdí àwọn Oṣèlú àti Olórí Ìjọ ti o nlo owó ìlú tàbi owó ìjọ fún ara wọn dipò ki...
View ArticleWi wé Gèlè Aṣọ Òfì/Òkè – How to tie Yoruba Traditional Woven Fabric
Aṣọ-Òfì tàbi Aṣọ-Òkè jẹ́ aṣọ ilẹ̀ Yorùbá. Aṣọ òde ni, nitori kò ṣe gbé wọ lójojúmọ́. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Aṣọ-Òfì/Òkè wúwo, ṣùgbọ́n ti ìgbàlódé ti bẹ̀rẹ̀ si fúyẹ́ nitori òwú igbalode....
View ArticleÒjò nrọ̀ si kòtò, gegele mbinú – The rain is filling up the gully to the...
Ójò rẹpẹtẹ – Heavy rain Bi inú ọpọ ti ndùn, ni inú ẹlòmíràn mbàjẹ́ ni àsikò òjò. Yorùbá ni orin fún igbà ti kò ba si òjò, igbà ti òjò bá ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ si rọ̀, tàbi ti ó bá...
View ArticleBi Egúngún/Eégún bá ńlé ni ki a má rọ́jú, bi ó ṣe ńrẹ ará ayé,...
Yorùbá ma ńṣe ọdún Egúngún/Eégún ni ọdọ-dún lati ṣe iranti Bàbánlá/Ìyánlá wọn ti ó ti di olóògbé nitori wọn ni iṣẹ́ lati ṣe laarin alàyè lati rán ará ilú leti pé ki wọn di...
View ArticleỌ̀gẹ̀dẹ̀ – “Ọ̀gẹ̀dẹ̀ dúdú/burúkú kò yá bù ṣán, ọmọ burúkú kò yá...
Ọ̀gẹ̀dẹ̀ àgbagbà àti ọ̀gẹ̀dẹ̀ wẹ́wẹ́ – Bunch of unripe Plantains and Bananas Banana Ọ̀gẹ̀dẹ̀ jẹ́ èso ti ó wọ́pọ̀ lára àwọn ohun ọgbin ti a lè ri ni ilẹ̀ Yorùbá pàtàki ni agbègbè Okitipupa ni...
View Article“Ẹ Kú Ọwọ́ Lómi Là Nki Ọlọ́mọ Tuntun – Ìtọ́jú Ọmọ Tuntun ni Àtijọ́”:...
Ni ayé àtijọ́, kò si itẹdi à lò sọnù bi ti ayé òde òni. Bẹni wọn kò lo ìgò oúnjẹ lati fún ọmọ tuntun ni oúnjẹ. Ri rọ ọmọ – Yoruba Traditional baby feeding. Courtesy:@theyorubablog Ọwọ́...
View Article