Ẹ̀̀ya orí ni èdè Yorùbá – Parts of Head in Yoruba LanguageOriginally Posted...
Orúkọ ẹ̀yà ara ṣe pàtàkì lati mọ nípa kíkọ́ èdè nítorí ó ma nwà nínú ọ̀rọ̀. Mí mọ awọn orúkọ wọnyi á́ tún jẹ ki èdè Yorùbá yé àwọn ti ó ni ìfẹ́ lati kọ èdè. A lérò wípé àwòrán àti pípè tí ó wà ni...
View Article“Ìkà gbàgbé Àjọbi, adánilóró̀ gbàgbé ọ̀la, ẹ̀san á ké lóri...
Yorùbá ni ètò àti òfin ti àwọn Àgbà, Ọba àti Ìjòyè fi nto ilú ki aláwọ̀-funfun tó dé. Onirúurú ọ̀nà ni wọn ma fi nṣe idájọ́ ìkà laarin àwùjọ. Wọn lè fi orin tú àṣiri...
View Article“Ikú tó fẹ́ pani, bó bá sini ni fìlà, ọpẹ́ ló yẹ ká dá”: Idibò yan...
Ni igbà ipalẹ̀mọ́ idibò, ẹ̀rù ba ará ilú nitori wọn kò mọ ohun ti ó lè sẹlẹ̀. Àwọn ti ó ndu ipò jade ni rẹpẹtẹ fún ètò-òṣèlú, eyi ti ó fa ki àwọn jàndùkú bẹ̀rẹ̀ ijà ti ó fa...
View ArticleOrukọ́ Ẹranko àti Àwòrán – Yoruba Names of Animals and picturesOriginally...
Originally posted 2013-06-21 22:30:27. Republished by Blog Post Promoter
View Article“Orúkọ ẹni ló njẹri ẹni lókèèrè: Yorùbá tó wà ni òkè-òkun...
Yorùbá ki dá gbé, nitori eyi, ẹbi àti ará á pa pọ̀ lati sọ ọmọ lórúkọ. Ni ọjọ́ ìsọmọ-lórúkọ, ki ṣe iyá àti bàbá ọmọ nikan ni ó nmú orúkọ silẹ̀, iyá àti bàbá àgbà àti ẹ̀gbọ́n...
View Article“Bi a bá pẹ́ láyé, a ó jẹ ẹran ti o ́tó Erin” – “If one lives long...
Erin – Elephant Erin jẹ ẹran ti ó tóbi ju gbogbo ẹranko ti a mọ̀ si ẹran inú igbó àti ẹran-àmúsìn, ti a mọ̀ ni ayé òde òni. Bi a bá ṣe àyẹ̀wò bi Yorùbá ti ńgé ẹran ọbẹ̀, ó ṣòro lati...
View Article“A ò mọ èyi ti Ọlọrun yio ṣe, kò jẹ́ ki á binú kú” – “We know not what...
Àṣà Yorùbá ma ńri ọpẹ́ ninú ohun gbogbo, nitori eyi ni àjọyọ̀ àti ayẹyẹ ṣe pọ ni ilẹ̀ Yorùbá. Bi kò bá ṣe ayẹyẹ igbéyàwó; á jẹ́ idúpẹ́ fun ikómọ/isọmọlórúkọ; ìsìnku arúgbó;...
View ArticleÌPANU – SNACKSOriginally Posted on February 22, 2013, last updated on...
Yorùbá ka ìpanu si ohun ti anjẹ lati mu inu duro pataki ni arin ounje aro ati ale. A le ka si ounje osan. Traditionally, Yoruba people regard snacks as stop-gap chewable, particularly between...
View ArticleObinrin kò ṣe e jánípò si ìdí Àdìrò nikan, Obinrin ló ni gbogbo Ilé –...
Ìtàn fi yé wa wi pé Yorùbá ka ọ̀rọ̀ obinrin si ni àṣà Yorùbá bi ó ti ẹ jẹ wi pé obinrin ki jẹ Ọba nitori ni àṣà ilú, ọkunrin ló njẹ olóri. Obinrin kò pọ̀ ni ipò agbára. Àwọn...
View Article“Ẹsẹ̀ yá ju mọ́tọ̀ (ọkọ̀) ara ló nfàbò sí” – ohun ìrìn-àjò ni èdè Yorùbá:...
Ni ayé àtijọ́ ẹsẹ̀ ni gbogbo èrò ma nlo lati rin lati ìlú kan si keji nigbati ọkọ̀ ìgbà̀lódé kò ti wọpọ. Ilé Ọba àti Ìjòyè ni a ti le ri ẹṣin nitori ẹṣin kò lè rin ninu igbó kìjikìji ti o yi ilẹ̀...
View Article“Ki Àgbàdo tó di Ẹ̀kọ, a lọ̀ ọ́ pa pọ̀: Ògì Ṣí ṣe” – “For Corn to become...
Ra Àgbàdo lọ́jà – Buy the Corn Àgbàdo ni wọn fi nṣe Ògì. Ògì ni wọn fi nṣe Ẹ̀kọ́. Ògì ṣí ṣe fẹ ìmọ́ tótó, nitori eyi, lai si omi, Ògì kò lè ṣe é ṣe. Ọkà oriṣiriṣi ló wà ṣùgbọ́n,...
View Article“Kí Kà ni Èdè Yorùbá” – “Counting or Numbers in Yoruba”Originally Posted...
Yorùbá ni bi wọn ti ma a nka nkàn ki wọ́n tó bẹ̀rẹ̀ si ka a ni èdè Gẹ̀ẹ́sì. Ẹ ṣe àyẹ̀wò kíkà ni èdè Yorùbá ni ojú ewé yi: ENGLISH TRANSLATION Counting or numbers in Yoruba before the...
View Article“Obinrin ti kò ni orogún, kò ti mọ àrùn ara rẹ̀”: A woman who has no...
Òwe yi fi ara han ni itan iyàwó Aṣojú-ọba, ti a ò pè ni Tinumi pẹ̀lú ọmọ rẹ̀ kan ṣoṣo, ọkùnrin ti a mọ̀ si Mofẹ́. Mofẹ́ dàgbà lati fẹ obinrin. Ó̀ yan obinrin ti à ńpè ni Àyànfẹ́ ni...
View ArticleÌbà Àkọ́dá – Reverence to the First BeingOriginally Posted on October 2,...
Obinrin ti ó́ nṣe Ì̀bà Aṣẹ̀dá – A woman paying reverence to the Creator. Courtesy: @theyorubablog Ìbà Àkọ́dá, ìbà Aṣẹ̀dá Ìbà ni n ó f’òní jú, mo r’íbà, k’íbà ṣẹ Nínú ríríjẹ, nínú àìríjẹ Mo wá gbégbá...
View Article“Orin ẹ̀kọ́ lati bọ̀wọ̀ fún òbí ni ilé-ìwé alakọbẹrẹ”: Primary School...
Orin yi ni Olùkọ́ ma fi ńkọ́ àwọn ọmọ ilé-ìwé alakọbẹrẹ nigbà “ilé-ìwé ọ̀fẹ́” ti àwọn Òṣèlú ilẹ̀ Yorùbá ti Olóyè Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ ṣe olórí rẹ. Ni ayé ìgbà wọnyi, ọ̀pọ̀lọpọ̀ òbí...
View Article“Iwájú lèrò mbá èrò – Kò si ohun téni kan ṣe, téni kò ṣe ri” –...
Ọ̀rọ̀ ijinlẹ àti Òwe Yorùbá wà lati fi kọ́ ọgbọ́n àti imò bi èniyàn ti lè gbé igbésí ayé rere. Ọ̀gá àgbà ninú Olórin ilẹ̀ aláwọ̀-dúdú (Olóyè, Olùdarí Ebenezer Obey) kọ ninú...
View Article“Ohun ti ajá mã jẹ, Èṣù á ṣẽ”: “What the dog will eat, the Devil will...
Yorùbá ma nṣe rúbọ Èṣù nigba gbogbo ki ẹ̀sìn ìgbàgbọ́ tó gbalẹ̀. Ounjẹ ni wọn ma fi ṣè rúbo ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà. Irú ounjẹ yi ni Yorùbá npè ni “ẹbọ”. Ìta gbangba ni wọn ma ngbe irú...
View ArticleÀmì – Yoruba Accent
Àmì – ṣe pàtàkì ni èdè Yorùbá nitori lai si àmì, àṣìwí tàbi àṣìsọ á pọ̀. Ọ̀rọ̀ kan ni èdè Yorùbá lè ni itumọ rẹpẹtẹ, lai si àmì yio ṣòro lati mọ ìyàtọ. Àmì jẹ ki èdè Yorùbá...
View ArticleÀjàpá rẹ Erin sílẹ̀ – “Ìjàlọ ò lè jà, ó lè bọ́ ṣòkòtò ni idi...
Erin jẹ ẹranko ti Ọlọrun da lọ́lá pẹlu titobi rẹ ninu igbo. Yorùbá ni “Koríko ti Erin bá ti tẹ̀, àtẹ̀gbé ni láyé”, oko ti Erin bá wọ̀, olóko bẹ wọ igbèsè tori ibajẹ ti o ma ṣẹlẹ̀ si irú...
View Article“Bàbá Ìtàn Ìkọ̀lé-Èkìtì, Olóògbé Ọj̀ọ̀gbọ́n-Àgbáyé Adé Àjàyí...
http://www.theyorubablog.com/wp-content/uploads/2014/09/Baba-rele-Burial-of-an-elders-song.wav Babá re lé ò, Ilé ló lọ́ tarà-rà Bàbá re lé ò, Ilé ló lọ́ tarà-rà Ilé ò, ilé, Ilé ò,...
View Article