Àròkọ ni Èdè Yorùbá – Essay in Yoruba LanguageOriginally Posted on June...
Idi ti a fi bẹ̀rẹ̀ si kọ iwé ni èdè Yorùbá lóri ayélujára ni lati jẹ́ ki ẹnikẹ́ni ti ó fẹ́ mọ̀ nipa èdè àti àṣà Yorùbá ri ìrànlọ́wọ́ lóri ayélujára. A ò bẹ̀rẹ̀ si kọ àwọn àròkọ ni...
View Article“Ìmọ́tótó borí àrùn mọ́lẹ̀, bi ọyẹ́ ti ḿborí ooru” –“Cleanliness...
http://www.theyorubablog.com/wp-content/uploads/2014/07/Imototo.wav Ìmọ́tótó borí àrùn mọlẹ̀, bọ́yẹ́ ti ḿborí ooru Àrùn ìwọ̀sí tinú ẹ̀gbin là wá Iná ni ḿborí aṣọ ẹlẹ́gbin Ni ayé àtijọ́...
View ArticleÌtán ti a fẹ́ kà loni dá lóri Bàbá tó kó gbogbo Ẹrù fún Ẹrú – The...
Originally posted 2017-12-06 00:23:08. Republished by Blog Post Promoter
View ArticleEwédú: Botanical Name Cochorus, Craincrain in Sierra LeoneOriginally Posted...
Ewédú jẹ ikan nínú ọbẹ̀ Yorùbá tó wọpọ ni agbègbè Ọ̀yó, Ọ̀sun, Ògùn gẹ́gẹ́bi ilá ti wọ́pọ̀ ni agbègbè Ondo àti Èkìti. Fún ẹni tó́ nkanju, ilá yára láti sè ju ewédú lọ, nítorí...
View Article“Ìtàn Ìjà laarin Ọ̀kẹ́rẹ́ àti Asin – Ìgbẹ̀hìn Ìjà fún Asin àti...
Ni ayé igbà kan ri, àwọn ẹranko ni ọjà ti wọn. Ni ọjọ́ ọjà, Kìnìún, Ajá, Ìgalà, Ikõkò, Kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀, Erin, Ẹkùn, Ìjàpá, Ọ̀kẹ́rẹ́, Eku-Asin, àti àwọn ẹranko yoku gbé irè oko àti...
View Article“Ìbẹ̀rẹ̀ kọ́ ló niṣẹ́” – Ẹ jade lọ dibò fún Gómìnà àti Aṣòfin Ipinlẹ̀...
Ipinlẹ̀ Orilẹ̀ Edè Nigeria – States in Nigeria À ṣe kágbá Idibò ni orilẹ̀ èdè Nigeria yio wáyé ni ọjọ́ Àbámẹ́ta, ọjọ́ Kọkọ̀nlá, oṣù kẹrin ọdún Ẹgbãlémẹ̃dógún, lati yan Gómìnà àti...
View Article“A kì í fi Oníjà sílẹ̀ ká gbájúmọ́ alápepe – Pí pa Àjòjì ni Gúsù...
Pí pa Àjòjì ni Gúsù ilẹ̀ Aláwọ̀-dúdú – South Africa’s xenophobic attacks Òwe Yorùbá kan sọ pé “Amúkun, ẹrù ẹ́ wọ́, ó ni ẹ̃ wò ìsàlẹ̀”. Òwe yi ṣe é lò lati ṣe àyẹ̀wò ìṣẹ̀lẹ̀ pí pa...
View ArticleBi ará ilé ẹni ba njẹ kòkòrò búburú ti a ò sọ fun, hẹ̀rẹ̀-huru rẹ kò...
Ó ti lé ni ọgbọ̀n ọdún ti ìyà iná monomono ti ńfi ìyà jẹ ará ilú orílẹ̀ èdè Nigeria. Nitori dáku-́dájí iná mọ̀nàmọ́na ti Ìjọba àpapọ̀ pèsè, ẹ̀rọ iná mọ̀nàmọ́na kékèké ti a lè...
View ArticleÀjọ̀dún Òmìnira Nigeria Kẹrindinlọgọta – Nigeria’s Fifty-six Independence...
Àjọ̀dún Òmìnira Nigeria Kẹrindinlaadọta – Nigeria’s Fifty-six Independence Celebration. Courtesy: @theyorubablog Originally posted 2016-10-01 00:37:30. Republished by Blog Post Promoter
View Article“Ọ̀run ńyabọ̀, ki ṣé ọ̀rọ̀ ẹnìkan”: “The sky is falling, is not a matter...
Ọ̀run ńyabọ̀ – the sky is falling. Courtesy: @theyroubablog Òwe Yorùbá yi ṣe gba àwọn ti o nbẹ̀rù nigba gbogbo níyànjú wípé ó yẹ ki èniyàn fara balẹ̀ lati ṣe iwadi ohun ti ó fẹ́ ṣẹlẹ̀ ki ó tó “kú sílẹ̀...
View Article“Àpẹrẹ Ẹrú ati Owó Àna fún Ìtọrọ Iyàwó ni Idilé Arinmájàgbẹ̀” –...
Gẹ́gẹ́ bi a ti kọ tẹ́lẹ̀, ẹrù àti owó àna yàtọ̀ lati idilé kan si ekeji, ṣùgbọ́n àwọn ohun àdúrà bára mu ni ilẹ̀ Yorùbá pàtàki Oyin, Obi, Ataare, Orógbó. Fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹbi...
View Article“Ìgbésí Ayé Aláwọ̀-dúdú Ṣe pàtàki” pé Àwọ Lè Yàtọ̀, Ṣùgbọ́n...
B;ack Lives Matter protesters Ikú àwọn ọkùnrin Aláwọ̀-dúdú ni ọwọ́ Ọlọpa ni orilẹ̀ èdè Àméríkà pọ̀ ju pi pa àwọn aláwọ̀ funfun tàbi laarin àwọn ẹ̀yà kékeré miran. Ọ̀sẹ̀ kini oṣù...
View Article“Ọgbọ́n àrékérekè sọ ìràwé inú aginjù di ilé fún Àjàpá” – Pípé...
Ni ayé igbà kan, ọ̀gbẹlẹ̀ wa ni ilú àwọn ẹranko, nitori ọ̀dá òjò fún igbà pi pẹ́. Ọ̀gbẹlẹ̀ yi fa ìyàn, wọn kò ri omi mu tàbi wẹ̀. Eleyi mú ki gbogbo ẹranko (Kìnìún, Ẹkùn, Erin, Ẹfọ̀n,...
View ArticleÌránti Aadọta Ọdún ti Ọ̀gágun Adékúnlé Fájuyi fi ara rẹ ji fún...
Yorùbá fẹ́ràn àlejò púpọ̀. Ìwà ti ọmọ ilú lè hù ti yio fa ibinú, bi àlejò bá hu irú ìwà bẹ́ ẹ̀, wọn yio ni àlejò ni, ki wọn fori ji i. Òwe Yorùbá ti ó sọ wi pé “Ojú àlejò...
View ArticleÌHÀ TI AWỌN ÒBÍ NI ILẸ̀ KAARỌ OOJIRE KỌ SI ÈDÈ YORÙBÁ: THE ATTITUDE...
A sọ wipe ọmọ kò gbọ́ èdè, tani kó kọ̃? Àwa òbí nii ṣe púpọ ni bi àwọn ọmọ wa ṣe mú èdè abi-nibi wọn. Àwa òbí lati yi ìhà ti a kọ si èdè Yorùbá padá, ti a kò bá fẹ́ ki o pòórá....
View ArticleOríkì Àjọbí, Àṣà Yorùbá ti ó nparẹ́ lọ – Family Lineage Odes, a Dying...
Oríkì* jẹ ọ̀rọ̀ ìwúrí ti Yorùbá ma nlò lati fi sọ ìtàn àṣà àti ìṣe ìdílé lati ìran dé ìran. Ninú oríkì ni a ti lè mọ ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ ẹbí ẹni àti ohun ti a mọ ìdílé mọ́, bí i irú iṣẹ ti...
View Article“A ki mọ́ ọkọ ọmọ, ki a tún mọ àlè rẹ” –“One does not acknowledge one’s...
Igbéyàwó ibilẹ̀ – Traditional marriage Ni ayé àtijọ́, wọn ma ńfi obinrin fún ọkọ ni, ṣùgbọ́n ni ayé òde òni, obinrin á mú̀ àfẹ́sọ́nà lati fi hàn òbi, nitori Yorùbá gba ọmọ obinrin ni...
View ArticleÌṣe Ilé ló mbá ni dode – Trudy Alli-Balogun ja Ilé-Iṣẹ́ rẹ lólè – The...
Ìbá ṣe pọ̀ laarin Yorùbá àti Ìlú-Ọba ti lé ni igba ọdún nitori òwò Òkè-òkun, pàtàki òwò ẹrú àti fún ẹ̀kọ́ ni ilé iwé giga. Nitori eyi, àṣà àti èdè Yorùbá kò ṣe fi ọwọ́...
View Article“A ki i jẹ Igún, a ki i fi Ìyẹ́ Igún rinti: Ẹnu Ayé Lẹbọ” –“It is...
Ohun ti o jẹ èèwọ̀ tàbi òfin ni ilú kan le ma jẹ èèwọ̀/òfin ni ilú miran ṣùgbọ́n bi èniyàn bá dé ilú, ó yẹ ki ó bọ̀wọ̀ fún àṣà àti òfin ilú. Bi èniyàn bá ṣe nkan èèwọ̀, ó...
View Article“Ọ̀run nyabọ̀, ki ṣé ọ̀rọ̀ ẹnìkan – Ayé Móoru” –“Heaven is collapsing, is...
Ọ̀run nyabọ̀ – Nature’s fury Ìbẹ̀rù tó gbòde ayé òde òni ni pé “Ayé Móoru”, nitori iṣẹ̀lẹ̀ ti o nṣẹlẹ̀ ni àgbáyé bi òjò àrọ̀ irọ̀ dá ni ilú kan, ilẹ̀-riru ni òmìràn, ọ̀gbẹlẹ̀,...
View Article