ẸGBẸ́́ YORÙBÁ NÍ ÌLÚỌBA: Finding Yoruba Food in the UK (Dalston...
Yorùbá ní “Bí ewé bá pẹ́ lára ọṣẹ, á dọṣẹ”,ọ̀rọ̀ yí bá ẹgbẹ́ Yorùbá ni Ìlúọba mu pàtàkì àwọn ti o ngbe ni Olú Ìlúọba. Títí di bi ọgbọ̀n ọdún sẹhin, àti rí oúnjẹ Yorùbá rà...
View Article“Ori bí bẹ́, kọ́ ni oògùn ori-fí fọ́” – A fi àsikò ọdún Keresimesi mú...
Yorùbá ni “Ibi ti ẹlẹ́kún ti nsun ẹkún ni aláyọ̀ gbe nyọ́”. Òwe yi fihan ohun tó nṣẹlẹ̀ ni àgbáyé. Bi ọ̀pọ̀ àwọn ti ó wà ni Òkè-òkun ti nra ẹ̀bùn àti ọ̀pọ̀ oúnjẹ ni oriṣiriṣi fún...
View ArticleAṣọ nla, Kọ́ lènìyàn nla – Wèrè ti wọ Àṣà Aṣọ Ẹbí: The hood does not...
Àṣà ilẹ̀ Yorùbá títí di àsìkò yi, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọkùnrin ma nni iyawo pupọ́ wọn si ma mbi ọmọ púpọ̀, wíwọ irú aṣọ kan naa fun ṣíṣe ma nfi ẹbi han. Aṣọ ẹbí bẹ̀rẹ̀ nípa ki ọkọ àti ìyàwó dá irú...
View Article“Ẹni ti ó bá mọ inú rò, á mọ ọpẹ́ dá”: Whoever can think/reason will...
Ọmọ bibi ni ewu púpọ̀, nitori eyi ni Yorùbá fi ma nki “ìyá ọmọ kú ewu”. Ni ọjọ́ ìsọmọ lórúkọ tàbi ìkómọ, Bàbá, Ìyá, ẹbi àti ọ̀rẹ́ òbí ọmọ tuntun á fi ìdùnnú hàn nipa ṣíṣe ọpẹ́...
View Article“Bi ojú bá mọ́, Agbe á yalé Aláró, Àlùkò á yalé Olósùn,...
Bi a bá wo òwe yi, a o ri pe Agbe pọn bi aró, Àlùkò pupa bi osùn nigbati Lékeléke funfun bi ẹfun. Nitori eyi, bi wọn kò ti ẹ̀ lọ si ilé Aláró, Olósùn àti Ẹlẹ́fun, àwọ̀ wọn á si wa...
View ArticleỌJỌ GBOGBO NI TI OLÈ – Everyday is for the thief … a warning to...
“ỌJỌ GBOGBO NI TI OLÈ, ỌJỌ KAN NI TOLÓHUN”: “EVERYDAY IS FOR THE THIEF, ONE DAY FOR THE OWNER”. Ní ọjọ Ẹti ọjọ keji lelogun oṣu keji ọdún yi, Ẹrọ amóhùn máwòrán Iluọba (BBC 1) tu asiri ọmọkunrin kan ti...
View Article“Àdúrà ló ńgbà, agbára ki gbà” – ohun èlò fún àdúrà ìbílẹ̀: “It...
Lati ọjọ́ ti aláyé ti dá ayé ni Yorùbá ti ni ìgbàgbọ́ ninu ki a gba àdúrà nitori pe ohun gbogbo fẹ́ àdúrà “Ohun ti o dára fẹ́ àdúrà ki ó bà lé dára si, eyi ti kò dára na fẹ́...
View Article“Àjẹ ìwẹ̀hìn ló ba Ẹlẹ́dẹ̀ jẹ́” – Ìkìlọ̀: ẹ jẹun díẹ̀ –Ẹ kú ọdún o, à...
Iyán àti ẹ̀fọ́ rírò – Pounded Yam and mixed stewed vegetable soup. Courtesy: @theyorubablog Ni asiko ọdún, pataki, asiko ọdún iranti ọjọ ibi Jesu, bi oúnjẹ ti pọ̀ tó fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ti o wa ni...
View ArticleẸ káàbọ̀ si ọdún Ẹgbàálémẹ́tàdínlógún – Welcome to 2017Originally...
Originally posted 2016-12-31 23:30:32. Republished by Blog Post Promoter
View Article“Awọ kò ká Ojú ìlù, Ọmọ Onílù ni òhun fẹ́ má a sun Awọ jẹ –...
Nigbati àwọn Òṣèlú gba Ìjọba ni igbà keji lọ́wọ́ Ìjọba Ológun, inú ará ilú dùn nitori wọn rò wi pé Ológun kò kọ iṣẹ́ Òṣèlú. Ilú rò wi pé Ìjọba Alágbádá yio ni àánú ilú ju...
View Article“Ọmọdé ò jobì, àgbà ò jẹ oyè” Èrè Òbí tó kọ ọmọ sílẹ̀: The...
Yorùbá ni “Ọmọdé ò jobì, àgbà ò jẹ oye”, òwe yi bá àwọn òbí ti ó kọ ọmọ sílẹ̀, ìyá ti ó ta ọmọ, bàbá ti ó sá fi ọmọ sílẹ̀ àti àwọn ti o fi ìyà jẹ ọmọ, irú ọ̀pọ̀lọpọ̀ òbí bayi ni...
View ArticleÌGBÉYÀWÓ ÌBÍLẸ̀ – TRADITIONAL MARRIAGEOriginally Posted on April 12, 2013,...
Gifts at a modern Yoruba Traditional wedding — courtesy of @theYorubablog Ìgbéyàwó ìbíle ní Ilẹ̀ Yorùbá jẹ́ àsìkò ti ẹbí ọkọ àti ì̀yàwó ma nparapọ. Ìyàwó ṣíṣe ni ilẹ̀ Yorùbá kò pin sí ãrin ọkọ àti...
View ArticleBi ọmọ ò jọ ṣòkòtò á jọ kíjìpá: Ibáṣe pọ Idilé Yorùbá – If a child...
Bàbá, iyá àti ọmọ ni wọn mọ si Idilé ni Òkè-òkun ṣùgbọ́n ni ilẹ̀ Yorùbá kò ri bẹ́ ẹ̀, nitori ẹbi Eg bàbá, ẹ̀gbọ́n àti àbúrò ẹni, ọmọ, ọkọ àti aya wọn ni a mọ̀ si Idilé. Yorùbá...
View ArticleÌkíni ni Èdè Yorùbá – Greetings in Yoruba LanguageOriginally Posted on July...
Yorùbá ni kíkí fún gbogbo àsìkò ọjọ́, ìṣẹ̀lẹ̀ àti èto.̀ Fún àpẹrẹ: a lérò wípé àwọn ti a kọ si abala ojú ìwé yi, àti bi a ti le pe ìkíni kankan a wúlò fún yin. ENGLISH TRANSLATION As a sign of...
View ArticleKòkòrò – Names of Insects & Bugs in YorubaOriginally Posted on January 29,...
Kòkòrò jẹ́ ohun ẹ̀dá kékeré tó ni ìyẹ́, ti ó lè fò, òmíràn kò ni iyẹ́, ṣugbọn wọn ni ẹsẹ̀ mẹfa. Ẹ ṣe àyẹ̀wò àpẹrẹ, àwòrán àti pi pè ni ojú ewé wọnyi. ENGLISH TRANSLATION Insects...
View ArticleÌfẹ́ kò fọ́jú, ẹni ti ó wọnú ìfẹ́ ló fọ́jú: ‘Igbéyàwó ki ṣe ọjà...
Ni ayé àtijọ́, ki òbí tó gbà lati fi ọmọ fún ọkọ, wọn yio ṣe iwadi irú iwà àti àìsàn ti ó wọ́pọ̀ ni irú idile bẹ́ ẹ̀. Nitori eyi, igbéyàwó ibilẹ̀ ayé àtijọ́ ma npẹ́ ju ti ayé òde...
View Article“Ìsọ̀rọ̀ ni igbèsi: Ibere ti ó wọ́pọ́ ni èdè Yorùba” – “Questions calls...
Ọpọlọpọ ibere ni èdè Yorùbá bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lu “ọfọ̀ – K”. Yàtọ̀ fún li lò ọfọ̀ yi ninú ọ̀rọ̀, orúkọ enia tàbi ẹranko, ọfọ̀ yi wọ́pọ̀ fún li lò fún ibere. Fún àpẹrẹ, orúkọ enia ti ó bẹ̀rẹ̀...
View Article“Bi a bà jẹ̀kọ à dári ji Ewé”: À-lò-tún-lò – “After eating the corn...
Ewé iran – Organic food wrapping leaves. Courtesy: @theyorubablog Ki ariwo à-lò-tún-lò tó gbòde ni aiyé òde òni nipa àti dáàbò bo àyíká ni Yorùbá ti ńlo à-lò-tún-lò pàtàki li...
View ArticleYí Yára bi Ojú-ọjọ́ ti nyí padà nitori Èérí Àyíká – Effect of...
Ẹ wo àròkọ “Yí Yára bi Ojú-ọjọ́ ti nyí padà nitori Èérí Àyíká” lóri ayélujára ni ojú ewé yi: Check out the essay on “Effect of environmental pollution on rapid climate change” on our...
View Article“Ọ̀kọ́lé, kò lè mu ràjò” – “Home-owner cannot travel with his/her...
IIé ihò inú àpáta – Cave House Òrùlé wà lára ohun ini pàtàki ti ó yẹ ki èniyàn ni, ṣùgbọ́n èniyàn kò lè sun yàrá meji pọ̀ lẹ́ẹ̀kan. Ki ṣe bi èniyàn bá fi owó ara rẹ̀ kọ́ ilé...
View Article