Àmì – Yoruba AccentOriginally Posted on February 10, 2019, last updated on...
Àmì – ṣe pàtàkì ni èdè Yorùbá nitori lai si àmì, àṣìwí tàbi àṣìsọ á pọ̀. Ọ̀rọ̀ kan ni èdè Yorùbá lè ni itumọ rẹpẹtẹ, lai si àmì yio ṣòro lati mọ ìyàtọ. Àmì jẹ ki èdè Yorùbá...
View ArticleỌRỌ ÌYÀNJÙ (WORD OF ADVICE): Ẹni tólèdè lóni ayé ibi ti wọn ti nsọOriginally...
ỌRỌ ÌYÀNJÙ (WORD OF ADVICE) Ẹyin ọmọ Odùduwà ẹjẹ ki a ran rawa létí wípé “Ẹni tólèdè lóni ayé ibi ti wọn ti nsọ”. Mo bẹ yin ẹ maṣe jẹki a tara wa lọpọ nitorina ẹ maṣe jẹki èdè Yorùbà parẹ. Èdè ti a...
View ArticleYí Yára bi Ojú-ọjọ́ ti nyí padà nitori Èérí Àyíká – Effect of...
Ẹlẹkọ-ìjìnlẹ̀ ṣe àkiyesi pe enia ndá kún yí yára bi ojú-ọjọ́ ti nyi padà nitori èérí-àyíká. Ojú-ọjọ́ ti nyí padà lati ìgbà ti aláyé ti dá ayé, ṣùgbọ́n àyípadà ojú-ọjọ́ ni ayé...
View ArticleÈLÒ ỌBẸ̀ YORÙBÁ: YORUBA SAUCE/STEW/SOUP INGREDIENTOriginally Posted on May 1,...
Yorùbá English Yorùbá English Èlò Ọbẹ̀ Soup/Stew/Stew Ingredients Elo Obe Soup/Stew/Stew Ingredients Ẹja Fish Ẹyẹlé Pigeon Ẹja Gbígbẹ Dry Fish Epo pupa Palm Oil Akàn Crab Òróró Vegetable Oil Edé...
View ArticleBíbẹ Èkó wo fún Ọ̀sẹ̀ kan – Ọjọ́ kẹta: Visiting Lagos for one week – Day 3...
Apá Kinni – Part One Download: A conversation in Yoruba (Day 3) You can also download the conversation by right clicking this link: A conversation in Yoruba – Day 3(mp3) ONÍLÉ – HOST/HOSTESS &...
View ArticleÌkíni ni Èdè Yorùbá – Greetings in Yoruba LanguageOriginally Posted on July...
Yorùbá ni kíkí fún gbogbo àsìkò ọjọ́, ìṣẹ̀lẹ̀ àti èto.̀ Fún àpẹrẹ: a lérò wípé àwọn ti a kọ si abala ojú ìwé yi, àti bi a ti le pe ìkíni kankan a wúlò fún yin. ENGLISH TRANSLATION As a sign of...
View Article“Ohun ti ajá mã jẹ, Èṣù á ṣẽ”: “What the dog will eat, the Devil will...
Yorùbá ma nṣe rúbọ Èṣù nigba gbogbo ki ẹ̀sìn ìgbàgbọ́ tó gbalẹ̀. Ounjẹ ni wọn ma fi ṣè rúbo ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà. Irú ounjẹ yi ni Yorùbá npè ni “ẹbọ”. Ìta gbangba ni wọn ma ngbe irú...
View Article“Ìtàn bi Ìjàpá ti fa Àkóbá fún Ọ̀bọ: Ẹ Ṣọ́ra fún Ọ̀rẹ́ Burúkú”–...
Ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ itàn Yorùbá, Ìjàpá jẹ ọ̀lẹ, òbùrẹ́wà, kò tóbi tó àwọn ẹranko yoku, ṣùgbọ́n ó ni ọgbọ́n àrékérekè ti ó fi ngbé ilé ayé. Ò̀we Yorùbá sọ wi pé, “Iwà jọ iwà, ni...
View Article“Ẹ jáwọ́ lápọ̀n ti kò yọ̀, ẹ lọ dá omi ilá kaná” – “Restrain from...
Ọbẹ̀ àpọ̀n jẹ́ ọbẹ̀ yíyọ̀ bi ọbẹ̀ ilá, ṣùgbọ́n fún ẹni ti kò bá mọ̃ se, kò ni yọ̀. Ọbẹ̀ ti enia lè yára sè ju ọbẹ̀ ilá ni, nitori bi a bá ni àpọ̀n kíkù nile, a din àkókò ti ó yẹ ki...
View Article“Orí ọti ọlọ́tí ni eṣinṣin nkúlé” – “Fly often dies on top of other people’s...
Ìsọ̀ Ẹmu – Local Palm wine bar @theyorubablog. “Ọ̀mùtí gbàgbé ìṣẹ́” fún ìgbaì diẹ ni, nítorí bí ọ̀mùtí bá jí tán, ìṣẹ́ rẹ kò tán. Gbogbo àlàyé àti ìpolongo wípé ọtí àmun jù nfa oriṣiriṣi àìsàn burúkú...
View Article“Àdúrà ló ńgbà, agbára ki gbà” – ohun èlò fún àdúrà ìbílẹ̀: “It...
Lati ọjọ́ ti aláyé ti dá ayé ni Yorùbá ti ni ìgbàgbọ́ ninu ki a gba àdúrà nitori pe ohun gbogbo fẹ́ àdúrà “Ohun ti o dára fẹ́ àdúrà ki ó bà lé dára si, eyi ti kò dára na fẹ́...
View ArticleÀwòrán ati pi pe Orúkọ Ẹranko ni Èdè Yorùbá Apá Kini àti Apá Keji...
Bi ó ti ẹ̀ jẹ́ pé a ti kọ nipa orúkọ àti àwòrán ẹranko ni àwọn ìwé ti a ti kọ sẹhin, ṣùgbọ́n Yorùbá ni “Ọgbọ́n ki i tán”, nitori eyi, a ṣe àtúnṣe gẹ́gẹ́ bi “Ọ̀jọ̀gbọ́n Èdè Yorùbá” ti...
View ArticleÒjò nrọ̀ si kòtò, gegele mbinú – The rain is filling up the gully to the...
Ójò rẹpẹtẹ – Heavy rain Bi inú ọpọ ti ndùn, ni inú ẹlòmíràn mbàjẹ́ ni àsikò òjò. Yorùbá ni orin fún igbà ti kò ba si òjò, igbà ti òjò bá ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ si rọ̀, tàbi ti ó bá...
View ArticleÌfẹ́ kò fọ́jú, ẹni ti ó wọnú ìfẹ́ ló fọ́jú: ‘Igbéyàwó ki ṣe ọjà...
Ni ayé àtijọ́, ki òbí tó gbà lati fi ọmọ fún ọkọ, wọn yio ṣe iwadi irú iwà àti àìsàn ti ó wọ́pọ̀ ni irú idile bẹ́ ẹ̀. Nitori eyi, igbéyàwó ibilẹ̀ ayé àtijọ́ ma npẹ́ ju ti ayé òde...
View Article“Àṣejù Baba Àṣetẹ́” – Ìtàn bi Ojúkòkòrò àti Ìgbéraga ti jẹ́...
Ni ìgbà àtijọ́, ọkùnrin kan wa ti orúkọ rẹ njẹ́ Ìgbéraga. Wọ́n bi Ìgbéraga si ilé olórogún, àwọn ìyàwó bàbá́ rẹ yoku ni ó tọ nitori ìyá rẹ kú nigbati ó wà ni kékeré. Lẹhin ti o...
View Article“Ọmọdé ò jobì, àgbà ò jẹ oyè” Èrè Òbí tó kọ ọmọ sílẹ̀: The...
Yorùbá ni “Ọmọdé ò jobì, àgbà ò jẹ oye”, òwe yi bá àwọn òbí ti ó kọ ọmọ sílẹ̀, ìyá ti ó ta ọmọ, bàbá ti ó sá fi ọmọ sílẹ̀ àti àwọn ti o fi ìyà jẹ ọmọ, irú ọ̀pọ̀lọpọ̀ òbí bayi ni...
View Article“Ori bí bẹ́, kọ́ ni oògùn ori-fí fọ́” – A fi àsikò ọdún Keresimesi mú...
Yorùbá ni “Ibi ti ẹlẹ́kún ti nsun ẹkún ni aláyọ̀ gbe nyọ́”. Òwe yi fihan ohun tó nṣẹlẹ̀ ni àgbáyé. Bi ọ̀pọ̀ àwọn ti ó wà ni Òkè-òkun ti nra ẹ̀bùn àti ọ̀pọ̀ oúnjẹ ni oriṣiriṣi fún...
View ArticleÀròkọ ni Èdè Yorùbá – Essay in Yoruba LanguageOriginally Posted on June...
Idi ti a fi bẹ̀rẹ̀ si kọ iwé ni èdè Yorùbá lóri ayélujára ni lati jẹ́ ki ẹnikẹ́ni ti ó fẹ́ mọ̀ nipa èdè àti àṣà Yorùbá ri ìrànlọ́wọ́ lóri ayélujára. A ò bẹ̀rẹ̀ si kọ àwọn àròkọ ni...
View ArticleÌpalẹ̀mọ́ Ìbò oṣù keji, ọjọ́ kẹrinla ọdún Ẹgbãlemẹ̃dogun – Wọn fi ẹ̀tẹ̀...
Ibò ni gbogbo orilẹ̀ èdè Nigeria lati yan Olóri Òṣèlú àti Gómìnà fún agbègbè yio wáyé ni ọjọ́ Àbámẹ́ta, ọjọ́ kẹrinla, oṣù keji odun Ẹgbãlemẹ̃dogun. Ki i ṣe ẹgbẹ́ Òṣèlú meji ló...
View Article“Ọgbọ́n àrékérekè sọ ìràwé inú aginjù di ilé fún Àjàpá” – Pípé...
Ni ayé igbà kan, ọ̀gbẹlẹ̀ wa ni ilú àwọn ẹranko, nitori ọ̀dá òjò fún igbà pi pẹ́. Ọ̀gbẹlẹ̀ yi fa ìyàn, wọn kò ri omi mu tàbi wẹ̀. Eleyi mú ki gbogbo ẹranko (Kìnìún, Ẹkùn, Erin, Ẹfọ̀n,...
View Article