“Ọ̀pọ̀ ni eṣú fi nya igi oko: Ìbò ni ipinlẹ Ọ̀ṣun” – “There is strength in...
Ninú Ẹ̀yà mẹrin-din-logoji orilẹ̀ èdè Nigeria, ẹ̀yà mẹ́fà ni o wa ni ipinlẹ Yorùbá lápapọ̀. Àwọn ẹ̀yà wọnyi ni: Èkó – ti olú ilú rẹ jẹ Ìkẹjà; Èkiti – ti olú ilú rẹ jẹ Adó-Èkiti;...
View Article“A ki mọ́ ọkọ ọmọ, ki a tún mọ àlè rẹ” –“One does not acknowledge one’s...
Igbéyàwó ibilẹ̀ – Traditional marriage Ni ayé àtijọ́, wọn ma ńfi obinrin fún ọkọ ni, ṣùgbọ́n ni ayé òde òni, obinrin á mú̀ àfẹ́sọ́nà lati fi hàn òbi, nitori Yorùbá gba ọmọ obinrin ni...
View ArticleỌdún tuntun káàbọ̀ –Ẹgbà-lé-mẹ́rìnlà – Welcoming the New Year –...
Ẹ kú ọdún o – Season Greetings. Courtesy: @theyorubablog Ẹ kú ọdún Festive Greetings Ẹ kú ìyè dún Greetings on the return of the year Ọdún á ya abo Prosperous New Year À ṣèyí ṣe àmọ́dún...
View Article“Bi eyi ò ṣe, omiran yio ṣe – bi Ọlọrun o pani, ẹnikan ò lè pani”: If this...
Ìtàn yi dá lori Bàbá ti aládũgbò mọ si “Bàbá Beyioṣe”. Bàbá yi jẹ onígbàgbọ́, ti ki ja tabi ṣe ãpọn. O bi ọmọ mẹta ti wọn jọ ngbe nitori iyawo rẹ ti kú. Ni ilé ti o ngbe, ó fi ifẹ...
View ArticleẸNITÍ ỌLỌRU KÒ DÙN NÍNÚ TÓ NLA ṢÚGÀ, JẸ̀DÍJẸ̀DÍ LÓ MA PÁ: WHOEVER GOD HAS NOT...
Yorùbá ní “Ẹnití Ọlọrun kò dùn nínú, tó nla ṣúgà (iyọ̀ ìrèké), jẹ̀díjẹdí ló ma pá”. Ọ̀rọ̀ Yorùbá yi ṣ̀e àtìlẹhìn fún iwadi tó fihàn wípé ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ti ìrẹ̀wẹ̀sì mbaja ma mu ọtí àti jẹ oúnje...
View ArticleỌ̀tún wẹ Òsì, Òsì wẹ Ọ̀tún, Lọwọ́ fi Nmọ: Right Washing The Left & The...
There is a Yoruba saying that, the right hand washes the left, and the left washes the right for clean hands. Image is courtesy of Microsoft Free Images. Àṣà àtọwọ́dọ́wọ́, ọwọ́ ni a fi njẹ...
View ArticleEwédú: Botanical Name Cochorus, Craincrain in Sierra LeoneOriginally Posted...
Ewédú jẹ ikan nínú ọbẹ̀ Yorùbá tó wọpọ ni agbègbè Ọ̀yó, Ọ̀sun, Ògùn gẹ́gẹ́bi ilá ti wọ́pọ̀ ni agbègbè Ondo àti Èkìti. Fún ẹni tó́ nkanju, ilá yára láti sè ju ewédú lọ, nítorí...
View Article“Àjàpá fẹ́ kó bá Ajá – Kàkà ki eku májẹ sèsé, á fi ṣe àwàdànu” –...
Ajá dúró dèmί lọna, fẹrẹ kun fẹ 2ce Bί ὸ bá dúró dèmί lọna fẹrẹ kun fẹ Makékéké Olóko á gbọ fẹrẹ kun fẹ Á gbọ á gbéwa dè, fẹrẹ kun fẹ Á gbéwa dè, á gbàwá nίṣu fẹrẹ kun fẹ Ajá dúró dèmί lọna, fẹrẹ kun...
View ArticleA bèrè fún àròkọ ni Èdè àti Àṣa Yorùbá fún Idije Àkọ́kọ́ – The...
A rọ ẹnikẹni ti ó ni ìfẹ́ èdè àti àṣà Yorùbá (pàtàki ọmọ ilé-iwé giga ti ó nkọ ẹ̀kọ́ èdè Yorùbá) ki ó kọ àròkọ fún “theyorubablog” lóri ayélujára. Àròkọ ti èrò bá kà jù...
View ArticleBί a bá ránni ni iṣẹ ẹrú: One sent on a slavish errand (on man’s inhumanity...
The Mido Macia Story courtesy of NEWSY reporting from multiple sources and giving a broader view Yorὺbá nί “Bί a bá ránni nί iṣẹ ẹrú, a fi tọmọ jẹ”. Ọlọpa tί o yẹ ki o dãbo bo ará àti ẹrú nί ìlú,...
View Article“Ẹgbẹ́ Iṣu kọ́ ni Ewùrà – Ìfọ́kọrẹ́/Ìkọ́kọrẹ́ àti Ọ̀jọ̀jọ̀ là ńfi...
Ewùrà – Water Yam. Courtesy: @theyorubablog Ẹbi Iṣu ni Ewùrà ṣùgbọ́n a lè pe Iṣu ni ẹ̀gbọ́n Ewùrà nitori ohun ti a lè fi Iṣu ṣe gbayì laarin gbogbo Yorùbá ju eyi ti a lè fi Ewùrà ṣe....
View Article“Ilé làbọ̀sinmi oko” – “Home is for rest after the farm or hard day’s...
Bi ènìà lówó tàbi bi kò ni, àwọn ohun kan ṣe pàtàki lati wà ni ílé ki a tó lè pẽ ibẹ̀ ni ilé. Fún àpẹrẹ: ilé ti ó ni òrùlé, ilẹ̀kùn àti fèrèsé; àdìrò àti àdògán; omi: Ki ba jẹ omi ẹ̀rọ, omi òjò tàbí...
View ArticleÌtàn àròsọ bi obinrin ti sọ Àmọ̀tékùn di alábàwọ́n: The Folklore on...
Ni igba kan ri, Àmọ̀tékùn ni àwọ̀ dúdú ti ó jọ̀lọ̀, ṣùgbọ́n ni ọjọ́ kan, Àmọ̀tékùn wá oúnjẹ õjọ́ rẹ lọ. Ó dé ahéré kan, ó ṣe akiyesi pe obinrin kan ńwẹ̀, inú rẹ dùn púpọ̀ pé...
View ArticleÌkini fún ọdún tuntun – New Year GreetingsOriginally Posted on January 1,...
Ẹ kú ọdún – Season Greetings. Courtesy: @theyorubablog Originally posted 2016-01-01 20:10:23. Republished by Blog Post Promoter
View ArticleIṣẹ́ ni oògùn ìṣẹ́ – Hard-work is a cure for povertyOriginally Posted on...
Ẹ ṣe àyẹ̀wò ìwé akéwì-orin ni èdè Yorùbá ti àwọn ọmọ ilé-ìwé n kọ́ sórí ni ilé-ìwé ilẹ̀ Yorùbá ni ayé àtijọ: Iṣẹ́ ni oògùn ìṣẹ́, múra si iṣẹ́ rẹ ọ̀rẹ́ mi, iṣẹ́ ni a fi i di ẹni...
View ArticleÀwòrán àti pi pè orúkọ ẹ̀yà ara lati ori dé ọrùn – Pictures and...
Download: Parts of the body in Yoruba – head to neck You can also download the Parts of the body in Yoruba by right clicking this link: Parts of the body in Yoruba – head to neck (mp3) ORÍ DÉ ỌRÙN...
View ArticleGbẹ̀dẹ̀ bi Ogún Ìyá, Ogún Bàbá ló ni ni lára – Maternal Inheritance...
Ogún jẹ́ gbogbo ohun ìní ti bàbá tàbi ìyá bá fi silẹ́ ti wọn bá kú. Ni ìgbà àtijọ́, kò wọ́pọ̀ ki olóògbé ṣe ìwé-ìhágún, bi wọn ṣe má a pín ohun ini wọn lẹhin ikú. Ọ̀pọ̀lọpọ̀...
View Article“Àgbá òfìfo ló ńdún woro-woro” –“Empty barrel makes most...
Àgbá ti ó kún fún epo-rọ̀bì – Barrel full of Crude oil Àgbá ti ó kún fún ohun ti ó wúlò bi epo-rọ̀bì, epo-pupa, epo-òróró, epo-oyinbo, ọ̀dà àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ ki pariwo. Àgbá...
View Article“Igbà kan nlọ, igbà kan nbọ̀, igbà kan kò dúró titi” – “Time passes by...
Oriṣi mẹta ni Yorùbá ka igbà ẹ̀dá si. Gẹ́gẹ́ bi àgbà ninú Olórin ilẹ̀ Aláwọ̀dúdú Olóyè Ebenezer Obey (Fabiyi) ti kọ́ pé “Igbà mẹta ni igbà ẹ̀dá láyé, igbà òwúrọ̀, igbà ọ̀sán,...
View Article“Àjẹ ìwẹ̀hìn ló ba Ẹlẹ́dẹ̀ jẹ́” – Ìkìlọ̀: ẹ jẹun díẹ̀ –Ẹ kú ọdún o, à...
Iyán àti ẹ̀fọ́ rírò – Pounded Yam and mixed stewed vegetable soup. Courtesy: @theyorubablog Ni asiko ọdún, pataki, asiko ọdún iranti ọjọ ibi Jesu, bi oúnjẹ ti pọ̀ tó fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ti o wa ni...
View Article