Quantcast
Channel: The Yoruba Blog
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Orukọ́ Ẹranko àti Àwòrán – Yoruba Names of Animals and picturesOriginally...

Originally posted 2013-06-21 22:30:27. Republished by Blog Post Promoter

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“A ki i jẹ Igún, a ki i fi Ìyẹ́ Igún rinti: Ẹnu Ayé Lẹbọ” –“It is...

Ohun ti o jẹ èèwọ̀ tàbi òfin ni ilú kan le ma jẹ èèwọ̀/òfin ni ilú miran ṣùgbọ́n bi èniyàn bá dé ilú, ó yẹ ki ó bọ̀wọ̀ fún àṣà àti òfin ilú.  Bi èniyàn bá ṣe nkan èèwọ̀, ó...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ìkà ò jẹ́ ṣe ọmọ ẹ bẹ́ẹ̀ – Gbi gba wèrè mọ ẹ̀sìn Aláwọ̀-dúdú: The...

Libya migrants: Muslim refugees arrested in Italy for throwing Christians into sea after fight Ni ọjọ́ kẹrin-din-lógún, oṣ̀u kẹrin ọdún Ẹgbãlemẹdógún, ọwọ́ Ọlọpa Italy tẹ ọkunrin mẹ̃dogun ti ó...

View Article

Gbígbé Ìṣe Yorùbá Jáde Lórí Ẹ̀rọ Ayélujára – Publishing Yoruba...

Àwọn ọ̀nà oríṣiríṣi ni a le fi gbé àṣà Yorùbá àti lílò iṣẹ́ ọ̀nà ni ilẹ̀ Yorùbá jáde lórí ẹ̀rọ-alántakùn. Onírúurú ìṣe ọ̀nà ni a le fi sí ẹ̀rọ-alántakùn bí i sinimá,...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Bi ojú bá mọ́, Agbe á yalé Aláró, Àlùkò á yalé Olósùn,...

Bi a bá wo òwe yi, a o ri pe Agbe pọn bi aró, Àlùkò pupa bi osùn nigbati Lékeléke funfun bi ẹfun. Nitori eyi, bi wọn kò ti ẹ̀ lọ si ilé Aláró, Olósùn àti Ẹlẹ́fun, àwọ̀ wọn á si wa...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ilé làbọ̀ simi oko, ṣùgbọ́n bi ilé bá sanni àwọ̀ là nwò”: “Home is...

sún-kẹrẹ fà-kẹrẹ ọkọ̀ – Lagos Traffic jam. Courtesy: @theyorubablog Gbogbo olólùfẹ́ èdè Yorùbá, pataki àwọn ti o fi ìfẹ́ tẹ̀ lé  àkọ-sílẹ̀ ọ̀rọ̀ gbígbé èdè àti àṣà Yorùbá́  lárugẹ...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Gèlè ò dùn bi ká mọ̀ ọ́ wé, ká mọ̀ ọ́ wé, kò tó kó yẹni”: “Head tie is not...

Aṣọ Yorùbá, ìró àti bùbá kò pé lai si gèlè. Gèlè oriṣiriṣi ló wà̀, a lè lo gèlè aṣọ ìbílẹ̀ bi: aṣọ òfi/òkè, àdìrẹ, tàbi ki á yọ gèlè lára aṣọ.  Ọpọlọpọ gèle ìgbàlódé wá lati òkè òkun. Ìmúra obinrin...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

ẸRÙ FÚN ÌDÍLÉ ÌYÀWÓ – LIST FOR BRIDE’S FAMILY – Apá Kẹta – Part...

Gifts at a modern Yoruba Traditional wedding — courtesy of @theYorubablog Ìyàtọ̀ diẹ̀ ló wà lãrin awọn ẹru igbéyàwó ti a kọ́ si ojú iwé yi lati idile si idile. Fún àpẹre: idile miran fẹ...

View Article


Jọ mi, Jọ mi, Òkúrorò/Ìkanra ló ndà – Insisting on people doing things...

Yorùbá ni “Bi Ọmọdé ba ṣubú á wo iwájú, bi àgbà ba ṣubú á wo ẹ̀hìn”.  Bi enia bá dé ipò àgbà, pàtàki gẹ́gẹ́ bi òbí, àgbà ìdílé tàbi ọ̀gá ilé iṣẹ́, ẹni ti ó bá ni ìfẹ́ kò ni...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ẹ̀mí ti ò jata, ẹ̀mí yẹpẹrẹ”: “Life devoid of consumption of pepper is...

Ata-ṣọmbọ, Ata-wẹ́wẹ́, Ata-Ijọsin, Ata gbigbẹ, Ata gígún àti awọn èlò ọbẹ̀ – Jalapeno, Serrano, Cayenne & various spices. Courtesy: @theyorubablog Ata ṣe pàtàki ninu àwọn èlò ọbẹ̀....

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“À ì sí Iná Mọ̀nà-mọ́ná àti Epo Ọkọ̀ bá Onílé pẹ̀lú Àlejò”: –...

Ki gbogbo Nigeria tó gba ominira ni àwọn Òṣèlú lábẹ́ olùdari Olóyè Ọbáfẹ́mi Awolọwọ ti fi owó kòkó àti iṣẹ́-àgbẹ̀ dá nkan ṣe fún gbogbo ilẹ̀ Yorùbá.  Yorùbá jẹ èrè àwọn ohun...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Njẹ́ ó yẹ ki Adájọ́ ti ó bá hu iwà ibàjẹ́ kọjá Òfin?” – “Should...

Ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ mú àwọn Adájọ́ ti wọn fi ẹ̀sùn iwà ibàjẹ́ kàn – DSS arrest of alleged corrupt Judges. Courtesy: @theyorubablog Ni ọjọ́ Ẹti, ọjọ́ keje, oṣù kẹwa ọdún Ẹgbàálémẹ̀rindinlógún,...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Kò si ohun a nfi ọ̀gẹ̀dẹ̀ ṣe ni Ijeṣa, ẹiyẹ ló njẹ́” – Oú́njẹ ti a lè fi...

Iyán ni oúnjẹ gidi fún Ijẹṣa, nitori wọn ni iṣu ju ọ̀gẹ̀dẹ̀ lọ.  Òwe àtijọ́ ni pé “Kò si ohun a nfi ọ̀gẹ̀dẹ̀ ṣe ni Ijeṣa, ẹiyẹ ló njẹ́” nitori ọ̀pọ̀ ohun ni a lè fi ọ̀gẹ̀dẹ̀ ṣe, ni ayé òde...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ìmọ́tótó borí àrùn mọ́lẹ̀, bi ọyẹ́ ti ḿborí ooru” –“Cleanliness...

http://www.theyorubablog.com/wp-content/uploads/2014/07/Imototo.wav Ìmọ́tótó borí àrùn mọlẹ̀, bọ́yẹ́ ti ḿborí ooru Àrùn ìwọ̀sí tinú ẹ̀gbin là wá Iná ni ḿborí aṣọ ẹlẹ́gbin Ni ayé àtijọ́...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Òjò tó rọ̀ ló mú pẹ̀tẹ̀pẹ́tẹ̀ wá”: Ìgbà Òjò dé – “It is the rain...

Pẹ̀tẹ̀pẹ́tẹ̀ Òjò – Much Mud “Òjò ibùkún lọ́dọ̀ ẹni kan, ni òjò ìbànújẹ́ lọ́dọ̀ ẹlòmíràn”.  Lai si òjò, ọ̀gbẹlẹ̀ á wà, ọ̀gbẹlẹ̀ pi pẹ́ ló nfa iyàn.  Inú àgbẹ̀ ma ndun ni àsikò...

View Article


“Obinrin ti kò ni orogún, kò ti mọ àrùn ara rẹ̀”: A woman who has no...

Òwe yi fi ara han ni itan iyàwó Aṣojú-ọba, ti a ò pè ni Tinumi pẹ̀lú ọmọ rẹ̀ kan ṣoṣo, ọkùnrin ti a mọ̀ si Mofẹ́.  Mofẹ́ dàgbà lati fẹ obinrin.  Ó̀ yan obinrin ti à ńpè ni Àyànfẹ́ ni...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ìgbésí Ayé Aláwọ̀-dúdú Ṣe pàtàki” pé Àwọ Lè Yàtọ̀, Ṣùgbọ́n...

B;ack Lives Matter protesters Ikú àwọn ọkùnrin Aláwọ̀-dúdú ni ọwọ́ Ọlọpa ni orilẹ̀ èdè Àméríkà pọ̀ ju pi pa àwọn aláwọ̀ funfun tàbi laarin àwọn ẹ̀yà kékeré miran.  Ọ̀sẹ̀ kini oṣù...

View Article


“Ilé làńwò ki a tó sọmọ lórúkọ – Orúkọ Yorùbá” – Home is examined...

Ni àṣà Yorùbá, ni ayé àtijọ́, ọjọ́ keje ni wọn ńsọmọ obinrin ni orúkọ, ọjọ́ kẹsan ni ti ọmọ ọkùnrin, ṣùgbọ́n ni ayé òde òni, ọjọ kẹjọ ni wọn sọ gbogbo ọmọ lórú̀kọ.  Yorùbá ki sọmọ...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ààntéré ọmọ Òrìṣà-Omi – “Ọmọ o láyọ̀lé, ẹni ọmọ sin lo bimọ”: Aantere...

Yorùbá ka ọmọ si ọlá àti iyì ti yio tọ́jú ìyá àti bàbá lọ́jọ́ alẹ́.  Eyi han ni orúkọ ti Yorùbá nsọ ọmọ bi: Ọmọlọlá, Ọmọniyi, Ọmọlẹ̀yẹ, Ọmọ́yẹmi, Ọlọ́mọ́là, Ọlọ́mọlólayé, Ọmọdunni,...

View Article

ỌJỌ GBOGBO NI TI OLÈ – Everyday is for the thief … a warning to...

“ỌJỌ GBOGBO NI TI OLÈ, ỌJỌ KAN NI TOLÓHUN”: “EVERYDAY IS FOR THE THIEF, ONE DAY FOR THE OWNER”. Ní ọjọ Ẹti ọjọ keji lelogun oṣu keji ọdún yi, Ẹrọ amóhùn máwòrán Iluọba (BBC 1) tu asiri ọmọkunrin kan ti...

View Article
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live