“Bi ikú ilé ò pani, tòde ò lè pani” – “If the death at home does not...
“Bi ikú ilé ò pani, tòde ò lè pani” – “If the death at home does not kill, the death outside will not” Òwe Yorùbá ti o ni “Bi ikú ilé ò pani, tòde ò lè pani” bá ọ̀pọ̀ iṣẹ̀lẹ̀ ti o...
View ArticleOhun gbogbo ki i tó olè: Òṣèlú Ilẹ̀ Aláwọ̀-dúdú – Nothing ever...
Òṣèlú Ilẹ̀ Aláwọ̀-dúdú African Union leaders Kò si oye ọdún ti ọ̀pọ̀lọpọ̀ Òṣèlú Ilẹ̀ Aláwọ̀-dúdú lè lò ni ipò ti wọn lè gbà lẹ́rọ̀ lati kúrò. Bi àyè bá gbà wọn, wọn fẹ kú si ori...
View ArticleÒrìṣà òkè jẹ́ ki npé meji obinrin kò dé inú – Àṣà Ìkó-binrin-jọ:...
Ọkùnrin kan pẹ̀lú iyàwó púpọ̀ wọ́pọ̀ ni ilẹ̀ Yorùbá. Àwọn obinrin ti ó bá́ fẹ́ ọkọ kan naa ni à ńpè ni “Orogún”. Ìwà oriṣiriṣi ni ó ma ńhàn ni ilé olórogún, àrù̀n iyàwó ti...
View Article“Èkó – Aginjù laarin àwọn Olú Ilú Àgbáyé”: “Lagos – A Jungle among...
Èkó ni olú ilú Nigeria fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún ki àwọn Ijọba Ológun tó kó Olú Ilú Nigeria lọ si Abuja ni bi ọdún mẹrinlélógún sẹhin. Ki kó olú ilú kúrò ni Èkó kò din èrò ti o nwọ...
View ArticleỌJỌ GBOGBO NI TI OLÈ – Everyday is for the thief … a warning to...
“ỌJỌ GBOGBO NI TI OLÈ, ỌJỌ KAN NI TOLÓHUN”: “EVERYDAY IS FOR THE THIEF, ONE DAY FOR THE OWNER”. Ní ọjọ Ẹti ọjọ keji lelogun oṣu keji ọdún yi, Ẹrọ amóhùn máwòrán Iluọba (BBC 1) tu asiri ọmọkunrin kan ti...
View Article“Ṣòkòtò àgbàwọ̀, bi kò ṣoni lẹsẹ á fúnni nítan”: “A borrowed trouser/pant, if...
Ìwà àti ìṣe ọ̀dọ́ ìgbàlódé, kò fi àṣà àti èdè Yorùbá hàn rárá. Aṣọ àlòkù ti gbòde, dipò aṣọ ìbílẹ̀. Ọpọlọpọ aṣọ àgbàwọ̀ yi kò wà fún ara àti lilò ni ilẹ̀ aláwọ̀-dúdú. Ọ̀dọ́ miran a wọ asọ àti bàtà...
View Article“Ìsọ̀rọ̀ ni igbèsi: Ibere ti ó wọ́pọ́ ni èdè Yorùba” – “Questions calls...
Ọpọlọpọ ibere ni èdè Yorùbá bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lu “ọfọ̀ – K”. Yàtọ̀ fún li lò ọfọ̀ yi ninú ọ̀rọ̀, orúkọ enia tàbi ẹranko, ọfọ̀ yi wọ́pọ̀ fún li lò fún ibere. Fún àpẹrẹ, orúkọ enia ti ó bẹ̀rẹ̀...
View Article“Àjàpá fẹ́ kó bá Ajá – Kàkà ki eku májẹ sèsé, á fi ṣe àwàdànu” –...
Ajá dúró dèmί lọna, fẹrẹ kun fẹ 2ce Bί ὸ bá dúró dèmί lọna fẹrẹ kun fẹ Makékéké Olóko á gbọ fẹrẹ kun fẹ Á gbọ á gbéwa dè, fẹrẹ kun fẹ Á gbéwa dè, á gbàwá nίṣu fẹrẹ kun fẹ Ajá dúró dèmί lọna, fẹrẹ kun...
View Article“Igbà kan nlọ, igbà kan nbọ̀, igbà kan kò dúró titi” – “Time passes by...
Oriṣi mẹta ni Yorùbá ka igbà ẹ̀dá si. Gẹ́gẹ́ bi àgbà ninú Olórin ilẹ̀ Aláwọ̀dúdú Olóyè Ebenezer Obey (Fabiyi) ti kọ́ pé “Igbà mẹta ni igbà ẹ̀dá láyé, igbà òwúrọ̀, igbà ọ̀sán,...
View ArticleJọ mi, Jọ mi, Òkúrorò/Ìkanra ló ndà – Insisting on people doing things...
Yorùbá ni “Bi Ọmọdé ba ṣubú á wo iwájú, bi àgbà ba ṣubú á wo ẹ̀hìn”. Bi enia bá dé ipò àgbà, pàtàki gẹ́gẹ́ bi òbí, àgbà ìdílé tàbi ọ̀gá ilé iṣẹ́, ẹni ti ó bá ni ìfẹ́ kò ni...
View Article“A ki i jẹ Igún, a ki i fi Ìyẹ́ Igún rinti: Ẹnu Ayé Lẹbọ” –“It is...
Ohun ti o jẹ èèwọ̀ tàbi òfin ni ilú kan le ma jẹ èèwọ̀/òfin ni ilú miran ṣùgbọ́n bi èniyàn bá dé ilú, ó yẹ ki ó bọ̀wọ̀ fún àṣà àti òfin ilú. Bi èniyàn bá ṣe nkan èèwọ̀, ó...
View ArticleẸ bá wa gbé ọ̀rọ̀ yi yẹ̀wò. Àwọn Ilé Ìdájọ́ Àgbà ni ìlú Amerika ṣe...
A gay couple rejoicing over the repeal of the Defense of Marriage Act — June 26, 2013. Image is from AP/BBC Ẹ bá wa gbé ọ̀rọ̀ yi yẹ̀wò. Àwọn Ilé Ìdájọ́ Àgbà ni ìlú Amerika ṣe ìdájọ wípé...
View ArticleGbígbé Ìṣe Yorùbá Jáde Lórí Ẹ̀rọ Ayélujára – Publishing Yoruba...
Àwọn ọ̀nà oríṣiríṣi ni a le fi gbé àṣà Yorùbá àti lílò iṣẹ́ ọ̀nà ni ilẹ̀ Yorùbá jáde lórí ẹ̀rọ-alántakùn. Onírúurú ìṣe ọ̀nà ni a le fi sí ẹ̀rọ-alántakùn bí i sinimá,...
View ArticleẸ̀̀ya orí ni èdè Yorùbá – Parts of Head in Yoruba LanguageOriginally Posted...
Orúkọ ẹ̀yà ara ṣe pàtàkì lati mọ nípa kíkọ́ èdè nítorí ó ma nwà nínú ọ̀rọ̀. Mí mọ awọn orúkọ wọnyi á́ tún jẹ ki èdè Yorùbá yé àwọn ti ó ni ìfẹ́ lati kọ èdè. A lérò wípé àwòrán àti pípè tí ó wà ni...
View Article“Ori ló mọ iṣẹ́ àṣe là”: Ògbójú-ọdẹ di Adẹmu fún Ará-Ọ̀run –“Destiny...
Ọkunrin kan wa láyé àtijọ́, Ògbójú-ọdẹ ni, ṣùgbọ́n bi ó ti pa ẹran tó, kò fi dá nkan ṣe. Ọ̀pọ̀ igbà, ki ri ẹran ti ó bá pa tà, o ma ńpin fún ará ilú ni. Nigbati kò ri ẹran pa mọ́,...
View ArticleÀWÒRÁN ÈLÒ ỌBẸ̀ YORÙBÁ – PHOTO GALLERY OF SOME YORUBA SOUP/STEW/SAUCE...
Originally posted 2013-05-03 23:19:39. Republished by Blog Post Promoter
View Article“Èèmọ̀ ni ki ọkùnrin fẹ́ ọkùnrin tàbi ki obinrin fẹ́ obinrin ni Àṣà...
Ilé Ẹjọ́ Àgbà yi Àṣà Ìgbéyàwó Àdáyébá padà ni ilú Àmẹ́ríka. Ni ọjọ́ Ẹti, Oṣù kẹfà, ọjọ́ Kẹrindinlọ́gbọ́n, ọdún Ẹgbãlemẹdógún, Ilé Ẹjọ́ Àgbà ti ilú Àmẹ́ríkà ṣe òfin pé...
View Article“Ẹ jáwọ́ lápọ̀n ti kò yọ̀, ẹ lọ dá omi ilá kaná” – “Restrain from...
Ọbẹ̀ àpọ̀n jẹ́ ọbẹ̀ yíyọ̀ bi ọbẹ̀ ilá, ṣùgbọ́n fún ẹni ti kò bá mọ̃ se, kò ni yọ̀. Ọbẹ̀ ti enia lè yára sè ju ọbẹ̀ ilá ni, nitori bi a bá ni àpọ̀n kíkù nile, a din àkókò ti ó yẹ ki...
View ArticleEwu ifi Ilé-àpèjẹ dipò Ilé-ìkàwé, MTN fẹ́ gbé Ilé-ìkàwé kúrò ni...
Ilé-ìkàwé MTN – MTN to withdraw multi-million digital library donated to UNILAG Ilé-ìkàwé gẹ́gẹ́ bi orúkọ yi ti jẹ ni èdè Yorùbá, jẹ ibi ti wọn kó oriṣiriṣi iwé si, fún ọmọ ilé-iwé àti...
View Article“Ògòngò lọba ẹiyẹ” – “Ostrich is the King of Birds”Originally Posted on...
Ògòngò – Ostrich. Courtesy: @theyorubablog Ògòngò jẹ ẹiyẹ ti ó tóbi jù ninú gbogbo ẹiyẹ, ẹyin rẹ ló tún tóbi jù. Ọrùn àti ẹsẹ̀ rẹ ti ó gún jẹ́ ki ó ga ju gbogbo ẹiyẹ yoku....
View Article