Quantcast
Channel: The Yoruba Blog
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live

Image may be NSFW.
Clik here to view.

ATỌ́NÀ LÉDÈ YORÙBÁ – Cardinal Directions in YorubaOriginally Posted on...

A compass showing the poles in Yoruba language. The image is courtesy of @theyorubablog   Originally posted 2013-04-16 19:01:07. Republished by Blog Post Promoter

View Article


Ẹ̀kọ́-ìṣirò ni èdè Yorùbá – Simple Arithmetic in Yoruba...

Yorùbá ni bi wọn ti ma nṣe ìṣirò ki wọn tó bẹ̀rẹ̀ si ka ni èdè Gẹ̀ẹ́sì.  Akọ̀wé yi kọ ìṣirò ki ó tó bẹ̀rẹ̀ ilé-ìwé lọdọ ìyá rẹ̀ àgbà.  Nígbàtí ìyá-àgbà bá nṣe iṣẹ́ òwú “Sányán”...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Gbẹ̀dẹ̀ bi Ogún Ìyá, Ogún Bàbá ló ni ni lára – Maternal Inheritance...

Ogún jẹ́ gbogbo ohun ìní ti bàbá tàbi ìyá bá fi silẹ́ ti wọn bá kú.  Ni ìgbà àtijọ́, kò wọ́pọ̀ ki olóògbé ṣe ìwé-ìhágún, bi wọn ṣe má a pín ohun ini wọn lẹhin ikú.  Ọ̀pọ̀lọpọ̀...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Bi ojú bá mọ́, Agbe á yalé Aláró, Àlùkò á yalé Olósùn,...

Bi a bá wo òwe yi, a o ri pe Agbe pọn bi aró, Àlùkò pupa bi osùn nigbati Lékeléke funfun bi ẹfun. Nitori eyi, bi wọn kò ti ẹ̀ lọ si ilé Aláró, Olósùn àti Ẹlẹ́fun, àwọ̀ wọn á si wa...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ọ̀run ńyabọ̀, ki ṣé ọ̀rọ̀ ẹnìkan”: “The sky is falling, is not a matter...

Ọ̀run ńyabọ̀ – the sky is falling. Courtesy: @theyroubablog Òwe Yorùbá yi ṣe gba àwọn ti o nbẹ̀rù nigba gbogbo níyànjú wípé ó yẹ ki èniyàn fara balẹ̀ lati ṣe iwadi ohun ti ó fẹ́ ṣẹlẹ̀ ki ó tó “kú sílẹ̀...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ìbà Àkọ́dá – Reverence to the First BeingOriginally Posted on October 2,...

Obinrin ti ó́ nṣe Ì̀bà Aṣẹ̀dá – A woman paying reverence to the Creator. Courtesy: @theyorubablog Ìbà Àkọ́dá, ìbà Aṣẹ̀dá Ìbà ni n ó f’òní jú, mo r’íbà, k’íbà ṣẹ Nínú ríríjẹ, nínú àìríjẹ Mo wá gbégbá...

View Article

“ABD” ni ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀ ni èdè Yorùbá́ – Alphabets is the beginning of...

Bi ó ti ẹ̀ jẹ́ pé a ti kọ nipa “abd” ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀ kikọ ni èdè Yorùbá sẹhin, a tu kọ fún iranti rẹ ni pi pè, kikọ àti lati tọka si ìyàtọ̀ larin ọ̀rọ̀ Yorùbá àti ọ̀rọ̀ Gẹ̀ẹ́si. Fún àpẹrẹ,...

View Article

Ìtán ti a fẹ́ kà loni dá lóri Bàbá tó kó gbogbo Ẹrù fún Ẹrú – The...

Originally posted 2017-12-06 00:23:08. Republished by Blog Post Promoter

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ayẹyẹ ṣi ṣe ni Òkèrè – Àṣà ti ó mba Owó Ilú jẹ́”: “Destination...

Yorùbá fẹ́ràn ayẹyẹ ṣi ṣe púpọ̀ pàtàki fún igbéyàwó.  Ni ayé àtijọ́, ìnáwó igbéyàwó kò tó bi ó ti dà ni ayé òde òni.  Titi di bi ogoji ọdún sẹhin, ilé Bàbá Iyàwó tàbi...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ori bí bẹ́, kọ́ ni oògùn ori-fí fọ́” – A fi àsikò ọdún Keresimesi mú...

Yorùbá ni “Ibi ti ẹlẹ́kún ti nsun ẹkún ni aláyọ̀ gbe nyọ́”.  Òwe yi fihan ohun tó nṣẹlẹ̀ ni àgbáyé.  Bi ọ̀pọ̀ àwọn ti ó wà ni Òkè-òkun ti nra ẹ̀bùn àti ọ̀pọ̀ oúnjẹ ni oriṣiriṣi fún...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Gbogbo ohun tó ndán kọ́ ni Wúrà” – “Not all that glitters is...

Wúrà jẹ ikan ninú ohun àlùmọ́ni iyebiye, pàtàki fún ohun ẹ̀ṣọ́.  Ẹwà Wúrà ki hàn, titi di ìgbà ti wọn bá yọ gbogbo ẹ̀gbin rẹ̀ kúrò pẹ̀lú iná tó gbóná rara.    Àwòrán ti ó wà...

View Article

ẸNITÍ ỌLỌRU KÒ DÙN NÍNÚ TÓ NLA ṢÚGÀ, JẸ̀DÍJẸ̀DÍ LÓ MA PÁ: WHOEVER GOD HAS NOT...

Yorùbá ní “Ẹnití Ọlọrun kò dùn nínú, tó nla ṣúgà (iyọ̀ ìrèké), jẹ̀díjẹdí ló ma pá”.  Ọ̀rọ̀ Yorùbá yi ṣ̀e àtìlẹhìn fún iwadi tó fihàn wípé ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ti ìrẹ̀wẹ̀sì mbaja ma mu ọtí àti jẹ oúnje...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ìṣòro ti Agbalésanwó n ri ni Ilú Nlá lati ri Ibùgbé”– “Prospective...

Abúlé – A Village. Courtesy: @theyorubablog Ni ayé àtijọ́, kò si ohun ti ó njẹ́ Agbalésanwó nitori kò si ẹni ti kò ni ẹbi ti wọn lè bá gbé ni ọ̀fẹ́.  Kò wọ́pọ̀ ki èniyàn kúrò ni ilé...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ẹgbẹ́ Iṣu kọ́ ni Ewùrà – Ìfọ́kọrẹ́/Ìkọ́kọrẹ́ àti Ọ̀jọ̀jọ̀ là ńfi...

Ewùrà – Water Yam. Courtesy: @theyorubablog Ẹbi Iṣu ni Ewùrà ṣùgbọ́n a lè pe Iṣu ni ẹ̀gbọ́n Ewùrà nitori ohun ti a lè fi Iṣu ṣe gbayì laarin gbogbo Yorùbá ju eyi ti a lè fi Ewùrà ṣe....

View Article

A bèrè fún àròkọ ni Èdè àti Àṣa Yorùbá fún Idije Àkọ́kọ́ – The...

A rọ ẹnikẹni ti ó ni ìfẹ́ èdè àti àṣà Yorùbá (pàtàki ọmọ ilé-iwé giga ti ó nkọ ẹ̀kọ́ èdè Yorùbá) ki ó kọ àròkọ fún “theyorubablog” lóri ayélujára.  Àròkọ ti èrò bá kà jù...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ìpolongo tó nlọ lọ́wọ́ ni orilẹ́ èdè Nigeria ni pe“Àyípadà bẹ̀rẹ̀...

Ohun ti wọ́n bá fi ogún ọdún tàbi ju bẹ́ ẹ̀ lọ kọ́, ṣe é bàjẹ́ ni iṣéjú akàn, ṣùgbọ́n lati ṣe àtúnṣe lè gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún bakan na a.  Ó ṣe pataki ki gbogbo ọmọ ilú pinu ni ikan kan...

View Article

“Ṣe bi o ti mọ ki i tẹ́ – Ọdún wọlé dé”: “One who acts moderately will not...

Ọdún Kérésì jẹ́ ọdún Onigbàgbọ́ lati ṣe iránti ọjọ́ ibi Jésù Olùgbàlà.  Ọjọ́ kẹjọ lẹhin ọdún Kérésìmesì ni ọdún  tuntun.  Fún ayẹyẹ ọdún, kò si iyàtọ̀ laarin Ìgbàgbọ́ àti...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ã Ò PÉ KÁMÁ JỌ BABA ẸNI…”: It is not enough to have a striking resemblance...

Yorùbá ní “Ã ò pé kámá jọ Baba ẹni timútimú, ìwà lọmọ àlè”.   Òwe yi bá ọpọlọpọ Yorùbá tí o nyi orúkọ ìdílé wọn padà nítorí ẹ̀sìn lai yi ìwà padà̀ lati bá orúkọ titun áti ẹ̀sìn mu.  Yorùbá ni “ilé...

View Article

“Ìwé àti kọ Yorùba lọfẹ lọwọ Àjàyí Crowther Fún Ra Rẹ”: Learn Yoruba for Free...

Ise Alagba Yoruba, Ajayi Crowther fun ra re. A Yoruba dictionary to look up basic vocabulary     Originally posted 2013-05-23 05:38:56. Republished by Blog Post Promoter

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ìfẹ́ kò fọ́jú, ẹni ti ó wọnú ìfẹ́ ló fọ́jú: ‘Igbéyàwó ki ṣe ọjà...

Ni ayé àtijọ́, ki òbí tó gbà lati fi ọmọ fún ọkọ, wọn yio ṣe iwadi irú iwà àti àìsàn ti ó wọ́pọ̀ ni irú idile bẹ́ ẹ̀.  Nitori eyi, igbéyàwó ibilẹ̀ ayé  àtijọ́ ma npẹ́ ju ti ayé òde...

View Article
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live