“Igbà kan nlọ, igbà kan nbọ̀, igbà kan kò dúró titi” – “Time passes by...
Oriṣi mẹta ni Yorùbá ka igbà ẹ̀dá si. Gẹ́gẹ́ bi àgbà ninú Olórin ilẹ̀ Aláwọ̀dúdú Olóyè Ebenezer Obey (Fabiyi) ti kọ́ pé “Igbà mẹta ni igbà ẹ̀dá láyé, igbà òwúrọ̀, igbà ọ̀sán,...
View ArticleÀjọ jẹ kò dùn bi Ẹni kan kò ri: Ìná dànù àwọn ọmọ Olówó Nigeria ni...
Lati ọjọ́ ti aláyé ti dá ayé ni Olówó tàbi Ọlọ́rọ̀ ti wà. Ilẹ̀ Aláwọ̀dúdú kún fún ọrọ̀ oriṣiriṣi, ṣùgbọ́n, iwà àpà, ojúkòkòrò, ki kó ti ilé dà si ita, àti ìfẹ́ àjòjì ju ara...
View ArticleÀṢÀ ÌDÁBẸ́: A Culture of Female Genital Mutilation #IWDOriginally Posted on...
Ìdábẹ́ jẹ ìkan nínú àṣà Yorùbá tí ólòdì si ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin. Gẹ́gẹ́bí ìtàn ìdábẹ́, Yorùbá ndabẹ fún ob̀nrin ní àti ìkókó títí dé ọmọ ọdún kan, nwọn ní ìgbàgbọ́ wipe yio da ìṣekúṣe dúró lára...
View Article“Àgbá òfìfo ló ńdún woro-woro” –“Empty barrel makes most...
Àgbá ti ó kún fún epo-rọ̀bì – Barrel full of Crude oil Àgbá ti ó kún fún ohun ti ó wúlò bi epo-rọ̀bì, epo-pupa, epo-òróró, epo-oyinbo, ọ̀dà àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ ki pariwo. Àgbá...
View Article“Ilé làbọ̀ simi oko, ṣùgbọ́n bi ilé bá sanni àwọ̀ là nwò”: “Home is...
sún-kẹrẹ fà-kẹrẹ ọkọ̀ – Lagos Traffic jam. Courtesy: @theyorubablog Gbogbo olólùfẹ́ èdè Yorùbá, pataki àwọn ti o fi ìfẹ́ tẹ̀ lé àkọ-sílẹ̀ ọ̀rọ̀ gbígbé èdè àti àṣà Yorùbá́ lárugẹ...
View Article“Ori ló mọ iṣẹ́ àṣe là”: Ògbójú-ọdẹ di Adẹmu fún Ará-Ọ̀run –“Destiny...
Ọkunrin kan wa láyé àtijọ́, Ògbójú-ọdẹ ni, ṣùgbọ́n bi ó ti pa ẹran tó, kò fi dá nkan ṣe. Ọ̀pọ̀ igbà, ki ri ẹran ti ó bá pa tà, o ma ńpin fún ará ilú ni. Nigbati kò ri ẹran pa mọ́,...
View ArticleBi ọmọ ò jọ ṣòkòtò á jọ kíjìpá: Ibáṣe pọ Idilé Yorùbá – If a child...
Bàbá, iyá àti ọmọ ni wọn mọ si Idilé ni Òkè-òkun ṣùgbọ́n ni ilẹ̀ Yorùbá kò ri bẹ́ ẹ̀, nitori ẹbi Eg bàbá, ẹ̀gbọ́n àti àbúrò ẹni, ọmọ, ọkọ àti aya wọn ni a mọ̀ si Idilé. Yorùbá...
View ArticleÌkà ò jẹ́ ṣe ọmọ ẹ bẹ́ẹ̀ – Gbi gba wèrè mọ ẹ̀sìn Aláwọ̀-dúdú: The...
Libya migrants: Muslim refugees arrested in Italy for throwing Christians into sea after fight Ni ọjọ́ kẹrin-din-lógún, oṣ̀u kẹrin ọdún Ẹgbãlemẹdógún, ọwọ́ Ọlọpa Italy tẹ ọkunrin mẹ̃dogun ti ó...
View Article“Ilé làńwò ki a tó sọmọ lórúkọ – Orúkọ Yorùbá” – Home is examined...
Ni àṣà Yorùbá, ni ayé àtijọ́, ọjọ́ keje ni wọn ńsọmọ obinrin ni orúkọ, ọjọ́ kẹsan ni ti ọmọ ọkùnrin, ṣùgbọ́n ni ayé òde òni, ọjọ kẹjọ ni wọn sọ gbogbo ọmọ lórú̀kọ. Yorùbá ki sọmọ...
View Article“A kì í tó́ó báni gbé, ká má tòó ọ̀rọ̀-ọ́ báni sọ” – Ìdàpọ̀...
Ó pé ọgọrun ọdún ni ọjọ́ kini, oṣù kini ọdún Ẹgba-̃le-mẹrinla ti Ìjọba Ìlú-Ọba ti fi aṣẹ̀ da Àríwá àti Gũsu orílẹ̀ èdè ti a mọ̀ si Nigeria pọ. Ìjọba Ìlú-Ọba kò bere lọwọ ará ilú ki...
View ArticleÀWÒRÁN ÈLÒ ỌBẸ̀ YORÙBÁ – PHOTO GALLERY OF SOME YORUBA SOUP/STEW/SAUCE...
Originally posted 2013-05-03 23:19:39. Republished by Blog Post Promoter
View ArticleWi wé Gèlè Aṣọ Òfì/Òkè – How to tie Yoruba Traditional Woven...
Aṣọ-Òfì tàbi Aṣọ-Òkè jẹ́ aṣọ ilẹ̀ Yorùbá. Aṣọ òde ni, nitori kò ṣe gbé wọ lójojúmọ́. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Aṣọ-Òfì/Òkè wúwo, ṣùgbọ́n ti ìgbàlódé ti bẹ̀rẹ̀ si fúyẹ́ nitori òwú igbalode....
View Article“Bibi ire kò ṣe fi owó rà – Yoruba names” – “Good pedigree cannot be...
Kò di igbà ti enia bá ni owó rẹpẹtẹ ki ó tó sọ ọmọ rẹ ni “Ọlá” nitori Yorùbá ka ipò giga, ọmọ, ilera, orúkọ rere si “Ọlá”. Ibi ti “Ọlá” wà ninú orúkọ Yorùbá, a lè lo “Adé; Ibi;...
View ArticleỌJỌ GBOGBO NI TI OLÈ – Everyday is for the thief … a warning to...
“ỌJỌ GBOGBO NI TI OLÈ, ỌJỌ KAN NI TOLÓHUN”: “EVERYDAY IS FOR THE THIEF, ONE DAY FOR THE OWNER”. Ní ọjọ Ẹti ọjọ keji lelogun oṣu keji ọdún yi, Ẹrọ amóhùn máwòrán Iluọba (BBC 1) tu asiri ọmọkunrin kan ti...
View Article“Gbogbo ohun tó ndán kọ́ ni Wúrà” – “Not all that glitters is...
Wúrà jẹ ikan ninú ohun àlùmọ́ni iyebiye, pàtàki fún ohun ẹ̀ṣọ́. Ẹwà Wúrà ki hàn, titi di ìgbà ti wọn bá yọ gbogbo ẹ̀gbin rẹ̀ kúrò pẹ̀lú iná tó gbóná rara. Àwòrán ti ó wà...
View ArticleỌ̀tún wẹ Òsì, Òsì wẹ Ọ̀tún, Lọwọ́ fi Nmọ: Right Washing The Left & The...
There is a Yoruba saying that, the right hand washes the left, and the left washes the right for clean hands. Image is courtesy of Microsoft Free Images. Àṣà àtọwọ́dọ́wọ́, ọwọ́ ni a fi njẹ...
View ArticleỌwọ́ Ọmọdé Kòtó Pẹpẹ, Tagbalagba Ò Wọ Kèrègbè: The Child’s Hand Cannot...
Only a child’s hand can reach into this type of calabash. The image is from Wikipedia. Ọ̀rọ̀ Yorùbá sọ wípé “ọwọ́ ọmọde ko to pẹpẹ, tagbalagba ko wọ̀ kèrègbè”, èyí tí a lè túmọ̀ sí wípé,...
View Article“Ojú ọ̀run tó ẹyẹ fò lai fi ara gbọ́n ra” – “The sky is wide enough for...
Ẹ̀sìn ti wa láyé, ki ẹ̀sìn Ìgbàgbọ́ àti Mùsùlùmi tó dé. Fún àpẹrẹ, Yorùbá gbàgbọ́ ninú “Ọlọrun” ti Yorùbá mọ̀ si “Òrìṣà-òkè” tàbi “Eledumare”. Bi Yorùbá ṣe ḿbá Ọlọrun...
View ArticleBί a bá ránni ni iṣẹ ẹrú: One sent on a slavish errand (on man’s inhumanity...
The Mido Macia Story courtesy of NEWSY reporting from multiple sources and giving a broader view Yorὺbá nί “Bί a bá ránni nί iṣẹ ẹrú, a fi tọmọ jẹ”. Ọlọpa tί o yẹ ki o dãbo bo ará àti ẹrú nί ìlú,...
View Article“Ẹ̀mí ti ò jata, ẹ̀mí yẹpẹrẹ”: “Life devoid of consumption of pepper is...
Ata-ṣọmbọ, Ata-wẹ́wẹ́, Ata-Ijọsin, Ata gbigbẹ, Ata gígún àti awọn èlò ọbẹ̀ – Jalapeno, Serrano, Cayenne & various spices. Courtesy: @theyorubablog Ata ṣe pàtàki ninu àwọn èlò ọbẹ̀....
View Article