Quantcast
Channel: The Yoruba Blog
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live

Ẹ̀kọ́ àti Ọgbọ́n ni Ọ̀rọ̀ Àgbà lati Ẹnu Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọmọlolú Olunlọyọ lórí...

Bi a ba fi eti si ọ̀rọ̀ ti àgbà Yorùbá Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọmọlolú Olunlọyọ  ni ori ẹ̀rọ “Amóhùnmáwòrán Òpómúléró”, ni ori ayélujára, a o ṣe àkíyèsí àwọn nkan wọnyi:...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ìgbésí Ayé Aláwọ̀-dúdú Ṣe pàtàki” pé Àwọ Lè Yàtọ̀, Ṣùgbọ́n...

B;ack Lives Matter protesters Ikú àwọn ọkùnrin Aláwọ̀-dúdú ni ọwọ́ Ọlọpa ni orilẹ̀ èdè Àméríkà pọ̀ ju pi pa àwọn aláwọ̀ funfun tàbi laarin àwọn ẹ̀yà kékeré miran.  Ọ̀sẹ̀ kini oṣù...

View Article


Ohun ti mo fẹ́ràn nipa Ìsimi Iparí Ọ̀sẹ̀ – What I love about the Weekend...

Ni ọjọ́ Ẹti, ọjọ́ karun ti a ti bẹ̀rẹ̀ ilé-iwé ni ọ̀sẹ̀, inú mi ma ń dùn nitori ilé-iwé ti pari ni agogo kan ọ̀sán, ti ìsimi bẹ̀rẹ̀. Mo fẹ́ràn ìsimi ipari ọ̀sẹ̀ nitori mo ma nri àwọn òbí mi....

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Àjàpá àti Ọmọdé Mẹta – “Ẹnu àìmẹ́nu, ètè àìmétè, ló́ nmú ọ̀ràn bá ẹ̀rẹ̀kẹ́” –...

Ni abúlé Yorùbá nigbati ko ti si ẹ̀rọ asọ̀rọ̀-mágbèsì tabi ẹ̀rọ amú-òhùn-máwòrán àti ẹ̀rọ ayélujára, àwọn ọmọdé má nkó ara jọ lati ṣe eré lẹhin iṣẹ́ oojọ Bàbá àti Ìyá wọn.  Pataki, ni igba ọ̀gbẹlẹ̀...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“A sọ̀rọ̀ ẹran ti o ni ìwo, igbin yọjú”: “Talking of animals with horns, the...

Ẹfọ̀n – Buffalo Courtesy: @theyorubablog Ọ̀pọ̀ ẹranko ti ó ni ìwo lóri, ma nlo lati fi gbèjà ara wọ́n ti ewu bá dojú kọ wọ́n.  Ni ìdà keji, ìwo igbin wà fún lati fura ninú ewu, nitorina, bi igbin bá rò...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Òjò nrọ̀ si kòtò, gegele mbinú – The rain is filling up the gully to the...

Ójò rẹpẹtẹ – Heavy rain Bi inú ọpọ ti ndùn, ni inú ẹlòmíràn mbàjẹ́ ni àsikò òjò.  Yorùbá ni orin fún igbà ti kò ba si òjò, igbà ti òjò bá ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ si rọ̀, tàbi ti ó bá...

View Article

“Ṣe bi o ti mọ ki i tẹ́ – Ọdún wọlé dé”: “One who acts moderately will not...

Ọdún Kérésì jẹ́ ọdún Onigbàgbọ́ lati ṣe iránti ọjọ́ ibi Jésù Olùgbàlà.  Ọjọ́ kẹjọ lẹhin ọdún Kérésìmesì ni ọdún  tuntun.  Fún ayẹyẹ ọdún, kò si iyàtọ̀ laarin Ìgbàgbọ́ àti...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Olóri Ẹbi, Baba Bùkátà” – “Headship of a Family is the Father of...

Olóri Ẹbi – Head of the Family connotes responsibiliies. Courtesy: @theyorubablog Olóri Ẹbi jẹ àkọ́bi ọkùnrin ni idilé.  Bi àkọ́bi bá kú, ọkùnrin ti ó bá tẹ̀le yio bọ si ipò.  Iṣẹ́ olóri...

View Article


“Orúkọ idile Yorùbá ti ó ńparẹ́” – “Yoruba family names that are...

Orúkọ ẹni ni ìfihàn ẹni, orúkọ Yorùbá fi àṣà, iṣẹ́ àti Òriṣà idile hàn tàbi àtẹsẹ̀bi ọmọ.  Yorùbá gbàgbọ́ ninú Ọlọrun/Eledumare ki ẹ̀sin igbàgbọ́ àti imọ̀le tó dé.    Ifá jẹ́ ẹ̀sin...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Àjàpá àti Ìyá Alákàrà –“Ọjọ́ gbogbo ni ti olè, ọjọ́ kan ni ti olóhun” – The...

Ìpolówó Àkàrà              Hawker’s advert http://www.theyorubablog.com/wp-content/uploads/2013/09/Akara-advert.mp3 Àkàrà gbóná re,              Here comes hot fried bean fritters Ẹ bámi ra àkàrà...

View Article

Ẹ̀kọ́-ìṣirò ni èdè Yorùbá – Simple Arithmetic in Yoruba...

Yorùbá ni bi wọn ti ma nṣe ìṣirò ki wọn tó bẹ̀rẹ̀ si ka ni èdè Gẹ̀ẹ́sì.  Akọ̀wé yi kọ ìṣirò ki ó tó bẹ̀rẹ̀ ilé-ìwé lọdọ ìyá rẹ̀ àgbà.  Nígbàtí ìyá-àgbà bá nṣe iṣẹ́ òwú “Sányán”...

View Article

BÍBẸ̀ ÈKÓ WÒ FÚN Ọ̀SẸ̀ KAN (ỌJỌ́ KEJÌ) – Visiting Lagos for a Week (Day...

Download: A conversation in Yoruba (Day 2) You can also download the Yoruba alphabets by right clicking this link: A conversation in Yoruba – Day 2(mp3) ỌJỌ́ KEJÌ – DAY TWO ONÍLÉ (HOST OR HOSTESS)...

View Article

ÀWÒRÁN ÀTI PÍPÈ ORÚKỌ ẸRANKO, APA KEJI – Names of Wild/Domestic...

Originally posted 2018-03-22 01:59:26. Republished by Blog Post Promoter

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

ÌJÀPÁ JẸ ÈRÈ AIGBỌRAN ÀTI ÌWÀ Ọ̀KANJÚÀ: The Tortoise is Punished for not...

ÌJÀPÁ/Àjàpá JẸ ÈRÈ AIGBỌRAN ÀTI ÌWÀ Ọ̀KANJÚÀ: THE RESULT OF DISOBEDIENCE AND GREED The tragic Tortoise — having eaten food made for his wife by the Herbalist — there really should have been a warning...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ni Ayé òde òni, njẹ́ ó yẹ ki a pọ́n Àṣà fi fẹ́ Iyàwó púpọ̀ lé ni...

Ni igbà àtijọ́, oníyàwó kan kò wọ́pọ̀ nitori iṣẹ́ Àgbẹ̀.  Àṣà fi fẹ́ iyàwó púpọ̀ ṣe kókó nitori bibi ọmọ púpọ̀ pàtàki ọmọ ọkùnrin fún irànlọ́wọ́ iṣẹ́-oko.  Fi fẹ̀ iyàwó púpọ̀ kò...

View Article


Ìtàn ti a o kà loni dá lórí ìdí ti ọmọ Ẹkùn fi di Ológbò – The Yoruba...

Yorùbá ma npa ìtàn lati fi ṣe à ri kọ́gbọ́n tàbi fún ìkìlọ̀.  Ẹ ṣọ́ra lati fi ìbẹ̀rù àti ojo bẹ̀rẹ̀ ọdún nitori a ma a géni kúrú. Lára ẹ̀kọ́ ti a lè ri fi kọ́ ọgbọ́n ni ìtàn ti a ka yi...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

ATỌ́NÀ LÉDÈ YORÙBÁ – Cardinal Directions in YorubaOriginally Posted on...

A compass showing the poles in Yoruba language. The image is courtesy of @theyorubablog   Originally posted 2013-04-16 19:01:07. Republished by Blog Post Promoter

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ọ̀kan-lé-nigba lọkọ ọmọge, ikan ori rẹ ni ọkọ gidi: ìyànjú fún àwọn...

Ni ayé àtijọ́, òbi si òbi àti ẹbi si ẹbi ló nṣe ètò iyàwó fi fẹ́ fún ọmọ ọkùnrin ti ó bá ti bàláágà, ti wọn rò pé ó lè tọ́jú iyàwó.  Obinrin ki tètè bàláágà, nitori ki...

View Article

“Obinrin ti kò ni orogún, kò ti mọ àrùn ara rẹ̀”: A woman who has no...

Òwe yi fi ara han ni itan iyàwó Aṣojú-ọba, ti a ò pè ni Tinumi pẹ̀lú ọmọ rẹ̀ kan ṣoṣo, ọkùnrin ti a mọ̀ si Mofẹ́.  Mofẹ́ dàgbà lati fẹ obinrin.  Ó̀ yan obinrin ti à ńpè ni Àyànfẹ́ ni...

View Article

Bi mo ṣe lo Ìsimi Àjíǹde tó kọjá – How I spent the last Easter...

Ìsimi ọdún Àjíǹde tó kọjá dùn púpọ̀ nitori mo lọ lo ìsimi náà pẹ̀lú ẹ̀gbọ́n Bàbá mi àti ẹbí rẹ ni ilú Èkó. Èkó jinà si ilú mi nitori a pẹ́ púpọ̀ ninú ọkọ̀ elérò ti àwọn òbí...

View Article
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live