Ìkini fún ọdún tuntun – New Year Greetings
Ẹ kú ọdún – Season Greetings. Courtesy: @theyorubablog
View ArticleẸ Jọ̀wọ́ Darapọ̀ Mọ́ Wa lati kọ nipa Àṣà àti Ìtàn Àdáyébá ni...
Gbogbo olólùfẹ́ èdè àti àṣà Yorùbá ti ó tẹ̀lé wa ni àwọn ọdún ti ó kọjá, a ki yin fún ọdún tuntun ti ó wọlé. Èdùmàrè á jẹ́ ki ọdún na a tura o. Inú wa yio dùn ti ẹ bá lè...
View Article“A ki i fi ọjọ́ kan bọ́ ọmọ tó rù”: Ìmọ̀ràn fún Òṣèlú tuntun àti...
Ọmọ ki dédé rù lai ni idi. Lára àwọn idi ti ọmọ lè fi rù ni: àìsàn, ebi, òùngbẹ, ìṣẹ́, ai ni alabojuto, òbí olójú kòkòrò, ai ni òbí àti bẹ ẹ bẹ lọ. Orilẹ̀ èdè Nigeria ti jẹ gbogbo...
View Article“Ilú-Oyinbo dára, ọ̀rẹ́ mi òtútù pọ̀” –“Europe is beautiful, but my...
Emperor Dele Ojo & His Star Brothers Band – Ilu Oyinbo Dara Gẹgẹbi, àgbà ninu olórin Yorùbá “Délé Òjó” ti kọ ni ọpọlọpọ ọdún sẹhin pe “Ilú Oyinbo dára, ọrẹ mi òtútù pọ̀, à ti gbọmọ...
View ArticleA ki yin lati Ilé – Greetings from Home
Ni ai pẹ yi, Olùkọ̀wé yi bẹ ilé wò fún bi ọ̀sẹ̀ mẹta. A ṣe àwọn akiyesi wọnyi. Ilú Èkó n fẹ̀ si, ṣùgbọ́n ọ̀nà kò fẹ̀ tó bi èrò àti ọkọ̀ ti pọ̀ tó, nitori eyi, sún-kẹrẹ fà-kẹrẹ ọkọ̀...
View Article“Olóri Ẹbi, Baba Bùkátà” – “Headship of a Family is the Father of...
Olóri Ẹbi – Head of the Family connotes responsibiliies. Courtesy: @theyorubablog Olóri Ẹbi jẹ àkọ́bi ọkùnrin ni idilé. Bi àkọ́bi bá kú, ọkùnrin ti ó bá tẹ̀le yio bọ si ipò. Iṣẹ́ olóri...
View Article“Awọ kò ká Ojú ìlù, Ọmọ Onílù ni òhun fẹ́ má a sun Awọ jẹ –...
Nigbati àwọn Òṣèlú gba Ìjọba ni igbà keji lọ́wọ́ Ìjọba Ológun, inú ará ilú dùn nitori wọn rò wi pé Ológun kò kọ iṣẹ́ Òṣèlú. Ilú rò wi pé Ìjọba Alágbádá yio ni àánú ilú ju...
View Article“Òṣèlú Nigeria, Ẹ Jọ̀wọ́, Ẹ Má Pe Ajá ni Ọ̀bọ fún Ará Ìlú” –...
Lati bi ogójì ọdún sẹhin, Epo-rọ̀bi nikan ni okùn ọrọ̀ ajé orilẹ̀ èdè Nigeria, ó si ti pa owó ribiribi wọlé fún ilú. Nigbati Epo-rọ̀bi bẹ̀rẹ̀ si pa owó wọlé, ará ilú kọ iṣẹ́ àgbẹ̀ àti...
View Article“Ẹ Kú Ọwọ́ Lómi Là Nki Ọlọ́mọ Tuntun – Ìtọ́jú Ọmọ Tuntun ni Àtijọ́”:...
Ni ayé àtijọ́, kò si itẹdi à lò sọnù bi ti ayé òde òni. Bẹni wọn kò lo ìgò oúnjẹ lati fún ọmọ tuntun ni oúnjẹ. Ri rọ ọmọ – Yoruba Traditional baby feeding. Courtesy:@theyorubablog Ọwọ́...
View Article“Kí Kà ni Èdè Yorùbá” – “Counting or Numbers in Yoruba”
Yorùbá ni bi wọn ti ma a nka nkàn ki wọ́n tó bẹ̀rẹ̀ si ka a ni èdè Gẹ̀ẹ́sì. Ẹ ṣe àyẹ̀wò kíkà ni èdè Yorùbá ni ojú ewé yi: ENGLISH TRANSLATION Counting or numbers in Yoruba before the...
View ArticleẸ̀kọ́-ìṣirò ni èdè Yorùbá – Simple Arithmetic in Yoruba Language
Yorùbá ni bi wọn ti ma nṣe ìṣirò ki wọn tó bẹ̀rẹ̀ si ka ni èdè Gẹ̀ẹ́sì. Akọ̀wé yi kọ ìṣirò ki ó tó bẹ̀rẹ̀ ilé-ìwé lọdọ ìyá rẹ̀ àgbà. Nígbàtí ìyá-àgbà bá nṣe iṣẹ́ òwú “Sányán”...
View ArticleẸ̀rù ló sọ ọmọ Ẹkùn di Ológbò/Ológìní tó fi di ”Ẹran-àmúsìn –Ọdẹ...
Ni igbà àtijọ́, ẹranko ti wọn pè ni Ẹkùn jẹ alágbára ẹranko, bẹni Kìnìún si jẹ́ alágbára ẹranko. Bi Kìnìún ti lágbára tó ninú igbó, bi ó bá bú ramúramù, ohun gbogbo ninú igbó á...
View Article“Odò ti ó bá gbàgbé orisun gbi gbẹ ló ngbẹ” – “A river that forgets its...
Orúkọ idile Yorùbá ti ó nparẹ́ nitori èsìn. Àwọn orúkọ ìdílé wọnyi kò di ẹlẹ́sìn lọ́wọ́ lati ṣe iṣẹ́ rere tàbi dé ọ̀run, ENGLISH TRANSLATION Yoruba family names that are disappearing....
View Article“À ì sí Iná Mọ̀nà-mọ́ná àti Epo Ọkọ̀ bá Onílé pẹ̀lú Àlejò”: –...
Ki gbogbo Nigeria tó gba ominira ni àwọn Òṣèlú lábẹ́ olùdari Olóyè Ọbáfẹ́mi Awolọwọ ti fi owó kòkó àti iṣẹ́-àgbẹ̀ dá nkan ṣe fún gbogbo ilẹ̀ Yorùbá. Yorùbá jẹ èrè àwọn ohun...
View Article“A ò mọ èyi ti Ọlọrun yio ṣe, kò jẹ́ ki á binú kú” – “We know not what...
Àṣà Yorùbá ma ńri ọpẹ́ ninú ohun gbogbo, nitori eyi ni àjọyọ̀ àti ayẹyẹ ṣe pọ ni ilẹ̀ Yorùbá. Bi kò bá ṣe ayẹyẹ igbéyàwó; á jẹ́ idúpẹ́ fun ikómọ/isọmọlórúkọ; ìsìnku arúgbó;...
View Article“Ọ̀run nyabọ̀, ki ṣé ọ̀rọ̀ ẹnìkan – Ayé Móoru” –“Heaven is collapsing, is...
Ọ̀run nyabọ̀ – Nature’s fury Ìbẹ̀rù tó gbòde ayé òde òni ni pé “Ayé Móoru”, nitori iṣẹ̀lẹ̀ ti o nṣẹlẹ̀ ni àgbáyé bi òjò àrọ̀ irọ̀ dá ni ilú kan, ilẹ̀-riru ni òmìràn, ọ̀gbẹlẹ̀,...
View Article“Ayẹyẹ ṣi ṣe ni Òkèrè – Àṣà ti ó mba Owó Ilú jẹ́”: “Destination...
Yorùbá fẹ́ràn ayẹyẹ ṣi ṣe púpọ̀ pàtàki fún igbéyàwó. Ni ayé àtijọ́, ìnáwó igbéyàwó kò tó bi ó ti dà ni ayé òde òni. Titi di bi ogoji ọdún sẹhin, ilé Bàbá Iyàwó tàbi...
View ArticleÌṣe Ilé ló mbá ni dode – Trudy Alli-Balogun ja Ilé-Iṣẹ́ rẹ lólè – The...
Ìbá ṣe pọ̀ laarin Yorùbá àti Ìlú-Ọba ti lé ni igba ọdún nitori òwò Òkè-òkun, pàtàki òwò ẹrú àti fún ẹ̀kọ́ ni ilé iwé giga. Nitori eyi, àṣà àti èdè Yorùbá kò ṣe fi ọwọ́...
View ArticleẸni gbé epo lájà, kò jalè̀ tó ẹni gba a – Olóri Òṣèlú Ilú Ọba, Na...
David Cameron’s ‘corrupt’ countries remarks to Queen branded ‘unfair’ By PRESS ASSOCIATION David Cameron called Nigeria ‘fantastically corrupt’ before the Queen Ìròyìn ti o jade ni ọjọ́ Ìṣẹ́gun,...
View Article“Ará Ilú Nigeria: “Fi Ẹ̀tẹ̀ silẹ̀ pa Làpálàpá” – Nigerians are:...
Ẹ̀tẹ̀ tó mbá ilú jà ni ‘iwà-ibàjẹ́’. Ìyà ti ará ilú njẹ lọ́wọ́lọ́wọ́, ki i ṣe èrè iwà-ibàjẹ́ ọdún kan, ṣùgbọ́n ti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún. Kò si ìfẹ́ ilú, nitori eyi, àwọn oniwà ibàjẹ́...
View Article