Àròkàn ló n fa ẹkún à sun à i dákẹ́: Anguish of mind is the root...
Ohun ti Yorùbá mọ̀ si àròkàn n irònú igbà gbogbo. Kò si ẹni ti ki ronú, ṣùgbọ́n àròkàn léwu. Inú rirò yàtọ si àròkàn. Inu rirò ni àwọn Onimọ-ijinlẹ̀ lò lati ṣe ọkọ̀ òfúrufú...
View ArticleYORÙBÁ alphabets – A B D
A B D E Ẹ F G GB H I J K L M N O Ọ P R S Ṣ T U W Y http://www.theyorubablog.com/wp-content/uploads/2016/05/Yoruba-Alphabets.mp4 You can also download the Yoruba alphabets by right clicking this link:...
View ArticleMuhammad Ali – Ọ̀gá pátápátá Afẹ̀ṣẹ́ kù bi Òjò àwọn Akànṣẹ́ Relé:...
Worshipers and well-wishers take photographs as the casket with the body of the late boxing champion Muhammad Ali is brought for his jenazah, … Ìròyìn ikú Muhammad Ali ọmọ ọdún mẹ́rinlélaadọrin...
View ArticleAyẹyẹ Ọjọ́-ibi Aadọrun Ọdún, Ọbabinrin Elizabeth Keji – Celebration of 90th...
Ọbabinrin Elizabeth Keji ni ibi Ayẹyẹ Ọjọ́-ibi Aadọrun Ọdún – Queen Elizabeth II at her 90th Birthday celebration. Ọbabinrin Elizabeth Keji, pé aadọrun ọdún láyé ni ọjọ́ kọkànlélógún, oṣù...
View ArticleÀjọ jẹ kò dùn bi Ẹni kan kò ri: Ìná dànù àwọn ọmọ Olówó Nigeria ni...
Lati ọjọ́ ti aláyé ti dá ayé ni Olówó tàbi Ọlọ́rọ̀ ti wà. Ilẹ̀ Aláwọ̀dúdú kún fún ọrọ̀ oriṣiriṣi, ṣùgbọ́n, iwà àpà, ojúkòkòrò, ki kó ti ilé dà si ita, àti ìfẹ́ àjòjì ju ara...
View ArticleBẹni, Bẹ́ẹ̀kọ́ Ìbò Ọ̀rọ̀ Ìlú ni Ìlú-Ọba: Ẹ̀kọ́ fún Orilẹ̀-èdè...
Ì̀bò Ọ̀rọ̀ Ìlu ni Ìlú-Ọba’ UK Referendum Ni Ìlú-Ọba, lẹhin ọdún mẹtalelogoji, èrò jade lati di ìbò bẹni-bẹ́ẹ̀kọ́ lori àjọṣepọ̀ pẹ̀lú ẹgbẹ́ Ìlú-Oyinbo méjidinlọ́gbọ̀n ni Ọjọ́bọ̀, oṣu...
View Article“Ìgbésí Ayé Aláwọ̀-dúdú Ṣe pàtàki” pé Àwọ Lè Yàtọ̀, Ṣùgbọ́n...
B;ack Lives Matter protesters Ikú àwọn ọkùnrin Aláwọ̀-dúdú ni ọwọ́ Ọlọpa ni orilẹ̀ èdè Àméríkà pọ̀ ju pi pa àwọn aláwọ̀ funfun tàbi laarin àwọn ẹ̀yà kékeré miran. Ọ̀sẹ̀ kini oṣù...
View ArticleÌránti Aadọta Ọdún ti Ọ̀gágun Adékúnlé Fájuyi fi ara rẹ ji fún...
Yorùbá fẹ́ràn àlejò púpọ̀. Ìwà ti ọmọ ilú lè hù ti yio fa ibinú, bi àlejò bá hu irú ìwà bẹ́ ẹ̀, wọn yio ni àlejò ni, ki wọn fori ji i. Òwe Yorùbá ti ó sọ wi pé “Ojú àlejò...
View ArticleOrúkọ Gbogbo Ẹ̀yà Ara ni Èdè Yorùbá – Names of part of Human Body in...
Nitotọ àti ṣe ẹ̀yà orí tẹlẹ ṣugbọn a lérò wípé orúkọ gbogbo ẹ̀yà ara lati orí dé ẹsẹ á wúlò fún kíkà. Ẹ̀yà Ara ni Èdè Yorùbá and the English Translation of names of part of the body...
View Article‘Gómìnà Ìpínlẹ̀ Yorùbá, ẹ pèsè omi mi mun fún ará ilú ki wọ́n yé...
Ìjọba Ológun àkọ́kọ́ ni abẹ́ Olóògbé Ọ̀gágun Aguiyi Ironsi, da gbogbo ipinlẹ̀ pọ si abẹ́ Ìjọba àpapọ̀. Ki wọ́n tó dá àwọn ipinlẹ̀ pọ̀, àwọn ipinlẹ̀ ndàgbà sókè gẹ́gẹ́ bi ohun ti ó ṣe...
View Article“Ìpolongo tó nlọ lọ́wọ́ ni orilẹ́ èdè Nigeria ni pe“Àtúnṣe bẹ̀rẹ̀...
Ohun ti wọ́n bá fi ogún ọdún tàbi ju bẹ́ ẹ̀ lọ kọ́, ṣe é bàjẹ́ ni iṣéjú akàn, ṣùgbọ́n lati ṣe àtúnṣe lè gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún bakan na a. Ó ṣe pataki ki gbogbo ọmọ ilú pinu ni ikan kan...
View ArticleÀjọ̀dún Òmìnira Nigeria Kẹrindinlaadọta – Nigeria’s Fifty-six Independence...
Àjọ̀dún Òmìnira Nigeria Kẹrindinlaadọta – Nigeria’s Fifty-six Independence Celebration. Courtesy: @theyorubablog
View Article“Njẹ́ ó yẹ ki Adájọ́ ti ó bá hu iwà ibàjẹ́ kọjá Òfin?” – “Should...
Ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ mú àwọn Adájọ́ ti wọn fi ẹ̀sùn iwà ibàjẹ́ kàn – DSS arrest of alleged corrupt Judges. Courtesy: @theyorubablog Ni ọjọ́ Ẹti, ọjọ́ keje, oṣù kẹwa ọdún Ẹgbàálémẹ̀rindinlógún,...
View ArticleObinrin kò ṣe e jánípò si ìdí Àdìrò nikan, Obinrin ló ni gbogbo Ilé –...
Ìtàn fi yé wa wi pé Yorùbá ka ọ̀rọ̀ obinrin si ni àṣà Yorùbá bi ó ti ẹ jẹ wi pé obinrin ki jẹ Ọba nitori ni àṣà ilú, ọkunrin ló njẹ olóri. Obinrin kò pọ̀ ni ipò agbára. Àwọn...
View ArticleAriwo Nigeria lóri èsi Idibo ni Amẹ́rikà: Nigerian’s noise on American...
Èsi ibò ti wọn di ni ilú Amẹ́rikà ni oṣù kọkànlá, ọjọ́ kẹjọ jade ni òru ọjọ́ kẹjọ mọ́jú ọjọ́ kẹsan ọdún Ẹgbàálémẹ́rindinlógún. Àwọn mẹta ti ó gbé àpóti ibò fún ipò olóri...
View Article“Bi o kò bá lágbára ohun ti o fẹ́, ni ìfẹ́ ohun ti o ni”: “If you cannot...
Ẹ kú ipalẹ̀mọ́ ọdún o. Bi ọdún bá sún mọ́ etílé, oúnjẹ àti ohun èlò gbogbo maa nwọn nitori àwọn ọlọ́jà yio ti fi owó kún ọjà nitori èrò ti ó fẹ́ ra ọjà maa n pọ̀ si ni àsikò yi....
View ArticleỌdún wọlé dé, ẹ ṣọ́ra fún ewu àfọwọ́fà ti ọti àmu párà lè fà – End...
Ẹ kú àsikò yi o. Bawo ni ipalẹ̀mọ́ ọdún Kérésìmesì àti ọdún titun? Ni àsikò ọdún, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ma nfi oúnjẹ àjẹ jù àti ọti à mu para yọ ayọ̀ ọdún. Ni òtitọ́, ará ilú nké pé kò...
View ArticleÌwé akéwì-orin nípa èrè iṣẹ́ lati ọwọ́ Olóògbé Olóyè J.F. Ọdúnjọ –...
Ẹ ṣe àyẹ̀wò ìwé akéwì-orin ni èdè Yorùbá ti àwọn ọmọ ilé-ìwé n kọ́ sórí ni ilé-ìwé ilẹ̀ Yorùbá ni ayé àtijọ: Iṣẹ́ ni oògùn ìṣẹ́ – Yoruba poem by J F Odunjo Ẹ ṣe àyẹ̀wò ìwé...
View Article“Àṣejù Baba Àṣetẹ́” – Ìtàn bi Ojúkòkòrò àti Ìgbéraga ti jẹ́...
Ni ìgbà àtijọ́, ọkùnrin kan wa ti orúkọ rẹ njẹ́ Ìgbéraga. Wọ́n bi Ìgbéraga si ilé olórogún, àwọn ìyàwó bàbá́ rẹ yoku ni ó tọ nitori ìyá rẹ kú nigbati ó wà ni kékeré. Lẹhin ti o...
View Article