“Iwájú lèrò mbá èrò – Kò si ohun téni kan ṣe, téni kò ṣe ri” –...
Ọ̀rọ̀ ijinlẹ àti Òwe Yorùbá wà lati fi kọ́ ọgbọ́n àti imò bi èniyàn ti lè gbé igbésí ayé rere. Ọ̀gá àgbà ninú Olórin ilẹ̀ aláwọ̀-dúdú (Olóyè, Olùdarí Ebenezer Obey) kọ ninú...
View Article“Orúkọ idile Yorùbá ti ó ńparẹ́” – “Yoruba family names that are...
Orúkọ ẹni ni ìfihàn ẹni, orúkọ Yorùbá fi àṣà, iṣẹ́ àti Òriṣà idile hàn tàbi àtẹsẹ̀bi ọmọ. Yorùbá gbàgbọ́ ninú Ọlọrun/Eledumare ki ẹ̀sin igbàgbọ́ àti imọ̀le tó dé. Ifá jẹ́ ẹ̀sin...
View Article“Orin ẹ̀kọ́ lati bọ̀wọ̀ fún òbí ni ilé-ìwé alakọbẹrẹ”: Primary School...
Orin yi ni Olùkọ́ ma fi ńkọ́ àwọn ọmọ ilé-ìwé alakọbẹrẹ nigbà “ilé-ìwé ọ̀fẹ́” ti àwọn Òṣèlú ilẹ̀ Yorùbá ti Olóyè Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ ṣe olórí rẹ. Ni ayé ìgbà wọnyi, ọ̀pọ̀lọpọ̀ òbí...
View ArticleGbẹ̀dẹ̀ bi Ogún Ìyá, Ogún Bàbá ló ni ni lára – Maternal Inheritance...
Ogún jẹ́ gbogbo ohun ìní ti bàbá tàbi ìyá bá fi silẹ́ ti wọn bá kú. Ni ìgbà àtijọ́, kò wọ́pọ̀ ki olóògbé ṣe ìwé-ìhágún, bi wọn ṣe má a pín ohun ini wọn lẹhin ikú. Ọ̀pọ̀lọpọ̀...
View ArticleẸ káàbọ̀ si ọdún Ẹgbàálémẹ́tàdínlógún – Welcome to 2017
Originally posted 2016-12-31 23:30:32. Republished by Blog Post Promoter
View Article“BÍ A TI NṢE NI ILÉ WA…”: MICHELLE OBAMA’S DRESSING AT OSCAR 2013
Image is from MSNBC (http://tv.msnbc.com/2013/02/25/a-cover-up-by-the-iranian-press-michelle-obama-has-no-right-to-bare-arms/) They covered the story on the Iranian Press Agency that found Michelle...
View ArticleẸni tó ni Ẹrú ló ni Ẹrù – Ìtàn Bàbá tó kó gbogbo ogún fun Ẹrú...
Àwọn Alágbàṣe ni Oko -Labourers in the farm Ni ayé igbà kan ri ki ṣe oye ọkọ, ilé gogoro, aṣọ àti owó ni ilé-ìfowó-pamọ́ ni a fi nmọ Ọlọ́rọ̀ bi kò ṣe pé oye Ẹrú, Ìyàwó, Ọmọ, Ẹran ọsin àti...
View ArticleÀwòrán ati pi pe Orúkọ Ẹranko ni Èdè Yorùbá Apá Kini àti Apá Keji...
Bi ó ti ẹ̀ jẹ́ pé a ti kọ nipa orúkọ àti àwòrán ẹranko ni àwọn ìwé ti a ti kọ sẹhin, ṣùgbọ́n Yorùbá ni “Ọgbọ́n ki i tán”, nitori eyi, a ṣe àtúnṣe gẹ́gẹ́ bi “Ọ̀jọ̀gbọ́n Èdè Yorùbá” ti...
View Article“Ki Àgbàdo tó di Ẹ̀kọ, a lọ̀ ọ́ pa pọ̀: Ògì Ṣí ṣe” – “For Corn to become...
Ra Àgbàdo lọ́jà – Buy the Corn Àgbàdo ni wọn fi nṣe Ògì. Ògì ni wọn fi nṣe Ẹ̀kọ́. Ògì ṣí ṣe fẹ ìmọ́ tótó, nitori eyi, lai si omi, Ògì kò lè ṣe é ṣe. Ọkà oriṣiriṣi ló wà ṣùgbọ́n,...
View ArticleOrúkọ Ẹranko a fàyà fà tabi jomijòkè ni èdè Yorùbá: Names of...
Gẹgẹbi àpè júwe, ẹranko a fàyà fà jẹ ẹranko ti ó ni àwọ̀, omiran ni oro, omiran ni ikarawun, wọn si ńyé ẹyin. Bi Ejò, àti Ákẽke ti ni oró bẹ̃ ni Àjàpá àti Ìgbín ni ikarawun. Fún...
View ArticleÌtàn Yorùbá bi Àdán ti di “Ko ṣeku, kò ṣẹyẹ” – Yoruba Folklore on how the Bat...
Àdán fò lọ bá ẹyẹ – Bat flew to join the birds @theyorubablog Ìtàn sọ wí pé eku ni àdán tẹ́lẹ̀ ki ìjà nla tó bẹ́ sílẹ̀ laarin eku àti ẹyẹ. Àdán rò wípé àwọn ẹyẹ fẹ́ bori, nitorina o fo lati lọ darapọ̀...
View ArticleBi mo ṣe lo Ìsimi Àjíǹde tó kọjá – How I spent the last Easter Holiday
Ìsimi ọdún Àjíǹde tó kọjá dùn púpọ̀ nitori mo lọ lo ìsimi náà pẹ̀lú ẹ̀gbọ́n Bàbá mi àti ẹbí rẹ ni ilú Èkó. Èkó jinà si ilú mi nitori a pẹ́ púpọ̀ ninú ọkọ̀ elérò ti àwọn òbí...
View Article“Olúróhunbí jẹ́ ẹ̀jẹ́ ohun ti kò lè san”: “Olurohunbi made a vow/covenant she...
Yorùbá ka ọmọ bibi si ohun pàtàki fún ìdílé, nitori èyi, tijó tayọ̀ ni Yorùbá ma fi nki ọmọ titun káàbọ̀ si ayé. Gẹ́gẹ́bí Ọ̀gá ninu Olórin ilẹ̀-aláwọ̀ dúdú, Olóyè Ebenezer Obey ti kọ́ “Ẹ̀bùn pàtàki ni...
View Article“A sọ̀rọ̀ ẹran ti o ni ìwo, igbin yọjú”: “Talking of animals with horns, the...
Ẹfọ̀n – Buffalo Courtesy: @theyorubablog Ọ̀pọ̀ ẹranko ti ó ni ìwo lóri, ma nlo lati fi gbèjà ara wọ́n ti ewu bá dojú kọ wọ́n. Ni ìdà keji, ìwo igbin wà fún lati fura ninú ewu, nitorina, bi igbin bá rò...
View Article“Ọba Aládélúsi Ògúnladé-Aládétóyìnbó gun Ori Oyè ilu Àkúrẹ́” –...
Déjì Àkúrẹ́ Ọba Aládélúsi Ògúnladé-Aládétóyìnbó pari gbogbo ètùtù ibilẹ ti Ọba Àkúrẹ́ ma nṣe lati gori oyè ni Ọjọ́rú, ọjọ́ kẹjọ, oṣù keje, ọdún Ẹgbãlemẹ̃dógún, lati di Ọba...
View ArticleÀmì – Yoruba Accent
Àmì – ṣe pàtàkì ni èdè Yorùbá nitori lai si àmì, àṣìwí tàbi àṣìsọ á pọ̀. Ọ̀rọ̀ kan ni èdè Yorùbá lè ni itumọ rẹpẹtẹ, lai si àmì yio ṣòro lati mọ ìyàtọ. Àmì jẹ ki èdè Yorùbá...
View Article“Ọdún nlọ si òpin”: Ẹ ṣọ́ra fún oníjìbìtì/ẹlẹ́tàn – “End of year is fast...
Ìparí ọdún sún mọ́lé, àsikò yi ni àwọn oníjìbìtì/ẹlẹ́tàn ma nbọ́ sita lati ṣe iṣẹ́ ibi, nipa ji ja àwọn ará ilú ti kò bá funra ni olè. Àṣà Yorùbá ni ayé àtijọ́ ni lati gbé àwọn...
View ArticleÒṣèlú Ẹ Gbé Èdè Yorùbá Lárugẹ: Politicians – Promote Yoruba Language
Yoruba, other Nigerian languages on the verge of extinction, Prof Akinwunmi Isola warns Nínú ìwé ìròyìn “Vanguard”, ti ọjọ́ Àìkú, oṣù kẹta, ọjọ́ , ọdún kẹrinlélógún, Ẹgbaalémétàlá, Olùkọ́...
View ArticleÀwòrán àti pípè orúkọ Èlò Ọbẹ̀ Yorùbá – Pictures and pronunciation...
Àwọn èlò ọbẹ̀ Yorùbá, ẹni ti ó bá mọ ọbẹ̀ se, yio mọ èlò ọbẹ̀ ti ohun yio ra àti bi yio ti se, ṣùgbọ́n ẹni ti kò mọ ọbẹ̀ se, lè lo owó ai mọye lati se ọbẹ̀, ki ọbẹ̀ rẹ má dùn. Fún...
View Article