‘Gómìnà Ìpínlẹ̀ Yorùbá, ẹ pèsè omi mi mun fún ará ilú ki wọ́n yé...
Ìjọba Ológun àkọ́kọ́ ni abẹ́ Olóògbé Ọ̀gágun Aguiyi Ironsi, da gbogbo ipinlẹ̀ pọ si abẹ́ Ìjọba àpapọ̀. Ki wọ́n tó dá àwọn ipinlẹ̀ pọ̀, àwọn ipinlẹ̀ ndàgbà sókè gẹ́gẹ́ bi ohun ti ó ṣe...
View Article“Ni ilú Afọ́jú, Olójú kan Lọba”: Ìjọba Òṣèlú tuntun gba Ìjọba ni...
Ọjọ́ itàn ni ọjọ́ kọkàndinlógún, oṣù karun, ọdún Ẹgbãlemẹ̃dógún jẹ fun orilẹ̀ èdè Nigeria àti gbogbo ilẹ̀ Aláwọ̀dúdú. Kò wọ́pọ̀ ki Ìjọba Ológun tàbi Ẹgbẹ́ Òṣèlú gbà lati gbé...
View Article“Ọgbọ́n àrékérekè sọ ìràwé inú aginjù di ilé fún Àjàpá” – Pípé...
Ni ayé igbà kan, ọ̀gbẹlẹ̀ wa ni ilú àwọn ẹranko, nitori ọ̀dá òjò fún igbà pi pẹ́. Ọ̀gbẹlẹ̀ yi fa ìyàn, wọn kò ri omi mu tàbi wẹ̀. Eleyi mú ki gbogbo ẹranko (Kìnìún, Ẹkùn, Erin, Ẹfọ̀n,...
View Article“Àjàpá fẹ́ kó bá Ajá – Kàkà ki eku májẹ sèsé, á fi ṣe àwàdànu” –...
Ajá dúró dèmί lọna, fẹrẹ kun fẹ 2ce Bί ὸ bá dúró dèmί lọna fẹrẹ kun fẹ Makékéké Olóko á gbọ fẹrẹ kun fẹ Á gbọ á gbéwa dè, fẹrẹ kun fẹ Á gbéwa dè, á gbàwá nίṣu fẹrẹ kun fẹ Ajá dúró dèmί lọna, fẹrẹ kun...
View ArticleBÍBẸ ÈKÓ WÒ FÚN Ọ̀SẸ̀ KAN: A One Week Visit to a Yoruba Speaking City...
These series of posts will center around learning the Yoruba words, phrases and sentences you might come across if you visited a Yoruba speaking city or state (here Lagos). A sample conversation is...
View Article“Òjò tó rọ̀ ló mú pẹ̀tẹ̀pẹ́tẹ̀ wá”: Ìgbà Òjò dé – “It is the rain...
Pẹ̀tẹ̀pẹ́tẹ̀ Òjò – Much Mud “Òjò ibùkún lọ́dọ̀ ẹni kan, ni òjò ìbànújẹ́ lọ́dọ̀ ẹlòmíràn”. Lai si òjò, ọ̀gbẹlẹ̀ á wà, ọ̀gbẹlẹ̀ pi pẹ́ ló nfa iyàn. Inú àgbẹ̀ ma ndun ni àsikò...
View Article“Àpọ́nlé kò si fún Ọba ti kò ni Olorì” – “There is no respect for a King...
Ọ̀rọ̀ Yorùbá ni “Bi ọmọdé bá tó ni ọkọ́, à fún lọ́kọ́”. Ọkọ́ jẹ irinṣẹ́ pàtàki fún Àgbẹ̀. Iṣẹ́-àgbẹ̀ ni ó wọ́pọ̀ ni ayé àtijọ́. Nitori eyi, bi bàbá ti nkọ́ ọmọ rẹ ọkùnrin ni...
View ArticleẸ̀̀ya orí ni èdè Yorùbá – Parts of Head in Yoruba Language
Orúkọ ẹ̀yà ara ṣe pàtàkì lati mọ nípa kíkọ́ èdè nítorí ó ma nwà nínú ọ̀rọ̀. Mí mọ awọn orúkọ wọnyi á́ tún jẹ ki èdè Yorùbá yé àwọn ti ó ni ìfẹ́ lati kọ èdè. A lérò wípé àwòrán àti pípè tí ó wà ni...
View Article“Ohun ti ó ntán lọdún eégún”– Kérésìmesì ọdún Ẹgbã-lé-mẹ́rìnlà ti...
Bàbá-Kérésì – Father Christmas Ìwà alajẹtan ti bori iránti ohun ti Kérésìmesì wà fún. Ọ̀pọ̀ kò ti ẹ̀ ránti pé iránti ọjọ́ ibi Jesu ni Ìjọba ṣe fún ará ilú ni ọjọ́ ìsimi ni ọjọ́...
View ArticleÌtẹ́lọ́rùn ni Baba Ìwà – Contentment is the Father of Character
Àìní ìtẹ́lọ́rùn ló bí gbogbo ìwà burúkú bi: irọ́ pípa, olè jíjà, àgbèrè, ojúkòkòrò àti bẹ̃bẹ lọ. Àìní ìtẹ́lọ́rùn ló wà ni ìdí àwọn Oṣèlú àti Olórí Ìjọ ti o nlo owó ìlú tàbi owó ìjọ fún ara wọn dipò ki...
View ArticleYí Yára bi Ojú-ọjọ́ ti nyí padà nitori Èérí Àyíká – Effect of...
Ẹ wo àròkọ “Yí Yára bi Ojú-ọjọ́ ti nyí padà nitori Èérí Àyíká” lóri ayélujára ni ojú ewé yi: Check out the essay on “Effect of environmental pollution on rapid climate change” on our...
View Article“Àpẹrẹ Ẹrú ati Owó Àna fún Ìtọrọ Iyàwó ni Idilé Arinmájàgbẹ̀” –...
Gẹ́gẹ́ bi a ti kọ tẹ́lẹ̀, ẹrù àti owó àna yàtọ̀ lati idilé kan si ekeji, ṣùgbọ́n àwọn ohun àdúrà bára mu ni ilẹ̀ Yorùbá pàtàki Oyin, Obi, Ataare, Orógbó. Fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹbi...
View ArticleIjẹbu lo ni Ìfọ́kọrẹ́/Ìkọ́kọrẹ́ gbogbo Yorùbá ló ni Ọ̀jọ̀jọ̀ – Water Yam...
Ẹ ṣe àyẹ̀wò bi a ti ńṣe Ọ̀jọ̀jọ̀ lójú iwé yi. Fọ Iṣu Ewùrà kan Bẹ ewùrà yi Rin iṣu yi (pẹ̀lú pãnu ti a dálu lati fi rin gãri, ilá tàbi ewùrà) Po iyọ̀ àti iyọ̀ igbàlódé, ata gigún...
View ArticleIṣẹ́ ni oògùn ìṣẹ́ – Hard-work is a cure for poverty
Ẹ ṣe àyẹ̀wò ìwé akéwì-orin ni èdè Yorùbá ti àwọn ọmọ ilé-ìwé n kọ́ sórí ni ilé-ìwé ilẹ̀ Yorùbá ni ayé àtijọ: Iṣẹ́ ni oògùn ìṣẹ́, múra si iṣẹ́ rẹ ọ̀rẹ́ mi, iṣẹ́ ni a fi i di ẹni...
View Article“Àjẹ ìwẹ̀hìn ló ba Ẹlẹ́dẹ̀ jẹ́” – Ìkìlọ̀: ẹ jẹun díẹ̀ –Ẹ kú ọdún o, à...
Iyán àti ẹ̀fọ́ rírò – Pounded Yam and mixed stewed vegetable soup. Courtesy: @theyorubablog Ni asiko ọdún, pataki, asiko ọdún iranti ọjọ ibi Jesu, bi oúnjẹ ti pọ̀ tó fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ti o wa ni...
View Article“ABD” ni ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀ ni èdè Yorùbá́ – Alphabets is the beginning of...
Bi ó ti ẹ̀ jẹ́ pé a ti kọ nipa “abd” ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀ kikọ ni èdè Yorùbá sẹhin, a tu kọ fún iranti rẹ ni pi pè, kikọ àti lati tọka si ìyàtọ̀ larin ọ̀rọ̀ Yorùbá àti ọ̀rọ̀ Gẹ̀ẹ́si. Fún àpẹrẹ,...
View Article“Ni Ayé òde òni, njẹ́ ó yẹ ki a pọ́n Àṣà fi fẹ́ Iyàwó púpọ̀ lé ni...
Ni igbà àtijọ́, oníyàwó kan kò wọ́pọ̀ nitori iṣẹ́ Àgbẹ̀. Àṣà fi fẹ́ iyàwó púpọ̀ ṣe kókó nitori bibi ọmọ púpọ̀ pàtàki ọmọ ọkùnrin fún irànlọ́wọ́ iṣẹ́-oko. Fi fẹ̀ iyàwó púpọ̀ kò...
View Article“Bàbá Ìtàn Ìkọ̀lé-Èkìtì, Olóògbé Ọj̀ọ̀gbọ́n-Àgbáyé Adé Àjàyí...
http://www.theyorubablog.com/wp-content/uploads/2014/09/Baba-rele-Burial-of-an-elders-song.wav Babá re lé ò, Ilé ló lọ́ tarà-rà Bàbá re lé ò, Ilé ló lọ́ tarà-rà Ilé ò, ilé, Ilé ò,...
View Article“Orúkọ ẹni ló njẹri ẹni lókèèrè: Yorùbá tó wà ni òkè-òkun...
Yorùbá ki dá gbé, nitori eyi, ẹbi àti ará á pa pọ̀ lati sọ ọmọ lórúkọ. Ni ọjọ́ ìsọmọ-lórúkọ, ki ṣe iyá àti bàbá ọmọ nikan ni ó nmú orúkọ silẹ̀, iyá àti bàbá àgbà àti ẹ̀gbọ́n...
View Article“Njẹ́ ó yẹ ki Adájọ́ ti ó bá hu iwà ibàjẹ́ kọjá Òfin?” – “Should...
Ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ mú àwọn Adájọ́ ti wọn fi ẹ̀sùn iwà ibàjẹ́ kàn – DSS arrest of alleged corrupt Judges. Courtesy: @theyorubablog Ni ọjọ́ Ẹti, ọjọ́ keje, oṣù kẹwa ọdún Ẹgbàálémẹ̀rindinlógún,...
View Article