Ni ìrántí àwọn ti ó gbé àṣà àti èdè Yorùbá lárugẹ ti ó di...
A bi Ọ̀jọ̀gbọ́n Akínwùnmí Ìṣọ̀lá si ìlú Ìbàdàn ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, ni oṣù kejìlá, ọjọ kẹrìnlélógún, ọdún Ẹdẹgbaalemọ́kàndínlógójì. Ó kú lẹhin ti ó pé ọdún méjìdínlọ́gọ́rin ni oṣù...
View ArticleMọ̀ mí, nmọ̀ ẹ́, “Ẹni tó lọ si ilé àna, lọ sọ èdè oyinbo, ni yio túmọ̀...
Ni ayé àtijọ́, òbi ni o nfẹ iyàwó fún ọmọ ọkùnrin wọn. Bi òbi bá ri ọmọ obinrin ti o dára ni idile ti o dára, wọn á lọ fi ara hàn lati tọrọ rẹ fún ọmọ wọn ọkunrin. Àṣà yi ti yàtọ̀ ni...
View ArticleABD YORÙBÁ – Yoruba AlphabetOriginally Posted on May 1, 2014, last updated on...
“ABD”, ìbẹ̀rẹ̀ iwé kikà ni èdè Yorùbá – Yoruba Alphabets “ABD” is the beginning of Yoruba education. Bi ọmọdé bá bẹrẹ ilé-iwé alakọbẹrẹ, èdè Yorùbá ni wọn fi nkọ ọmọ ni ilé-iwé lati...
View ArticleÀròkàn ló n fa ẹkún à sun à i dákẹ́: Anguish of mind is the root...
Ohun ti Yorùbá mọ̀ si àròkàn n irònú igbà gbogbo. Kò si ẹni ti ki ronú, ṣùgbọ́n àròkàn léwu. Inú rirò yàtọ si àròkàn. Inu rirò ni àwọn Onimọ-ijinlẹ̀ lò lati ṣe ọkọ̀ òfúrufú...
View ArticleÀròkọ ni Èdè Yorùbá – Essay in Yoruba LanguageOriginally Posted on June...
Idi ti a fi bẹ̀rẹ̀ si kọ iwé ni èdè Yorùbá lóri ayélujára ni lati jẹ́ ki ẹnikẹ́ni ti ó fẹ́ mọ̀ nipa èdè àti àṣà Yorùbá ri ìrànlọ́wọ́ lóri ayélujára. A ò bẹ̀rẹ̀ si kọ àwọn àròkọ ni...
View ArticleÀwòrán àti pípè orúkọ Èlò Ọbẹ̀ Yorùbá – Pictures and pronunciation...
Àwọn èlò ọbẹ̀ Yorùbá, ẹni ti ó bá mọ ọbẹ̀ se, yio mọ èlò ọbẹ̀ ti ohun yio ra àti bi yio ti se, ṣùgbọ́n ẹni ti kò mọ ọbẹ̀ se, lè lo owó ai mọye lati se ọbẹ̀, ki ọbẹ̀ rẹ má dùn. Fún...
View Article“Orúkọ ẹni ló njẹri ẹni lókèèrè: Yorùbá tó wà ni òkè-òkun...
Yorùbá ki dá gbé, nitori eyi, ẹbi àti ará á pa pọ̀ lati sọ ọmọ lórúkọ. Ni ọjọ́ ìsọmọ-lórúkọ, ki ṣe iyá àti bàbá ọmọ nikan ni ó nmú orúkọ silẹ̀, iyá àti bàbá àgbà àti ẹ̀gbọ́n...
View ArticleNi Iránti Bàbá Ẹgbẹ́ Òṣèré Nigeria: Olóògbé Olóyè Hubert Adédèji...
Ẹbi, ará, iránṣẹ́ Ìjọba àti àwọn ọmọ Olóògbé Olóyè Hubert Adédèji Ogunde pé jọ ni ọjọ́ kẹrinlélógún oṣù kẹrin ọdún Ẹgbãlemẹ̃dógún, ni ilú Ìjẹ̀bú Ọ̀sọ̀sà ti ipinlẹ̀ Ògùn lati...
View ArticleẸRÙ FÚN ÌDÍLÉ ÌYÀWÓ – LIST FOR BRIDE’S FAMILY – Apá Kẹta – Part...
Gifts at a modern Yoruba Traditional wedding — courtesy of @theYorubablog Ìyàtọ̀ diẹ̀ ló wà lãrin awọn ẹru igbéyàwó ti a kọ́ si ojú iwé yi lati idile si idile. Fún àpẹre: idile miran fẹ...
View ArticleBi ọmọ ò jọ ṣòkòtò á jọ kíjìpá: Ibáṣe pọ Idilé Yorùbá – If a child...
Bàbá, iyá àti ọmọ ni wọn mọ si Idilé ni Òkè-òkun ṣùgbọ́n ni ilẹ̀ Yorùbá kò ri bẹ́ ẹ̀, nitori ẹbi Eg bàbá, ẹ̀gbọ́n àti àbúrò ẹni, ọmọ, ọkọ àti aya wọn ni a mọ̀ si Idilé. Yorùbá...
View ArticleẸkáàbọ̀ si ọdún Ẹgbàálémọ̀kándínlógún – Welcome to 2019
Àwọn ohun ti a kò rò wọ̀nyí kò ni wọlé tọ̀ wá – All these unexpected will not come near.
View ArticleÀpẹrẹ Ìsìnkú Ìbílẹ̀ fún Arúgbó ni Ilẹ́ Yorùbá – Example of Yoruba...
Ìnáwó rẹpẹtẹ ni ìsìnkú arúgbó jẹ́ ni ilé Yorùbá. Bi arúgbó bá kú ni ilé Yorùbá ki ṣe òkú ọ̀fọ̀ ṣùgbọ́n òkú ijọ àti ji jẹ, mi mu ni pàtàki bi irú arúgbó bá bi àwọn ọmọ ti...
View ArticleỌ̀tún wẹ Òsì, Òsì wẹ Ọ̀tún, Lọwọ́ fi Nmọ: Right Washing The Left & The...
There is a Yoruba saying that, the right hand washes the left, and the left washes the right for clean hands. Image is courtesy of Microsoft Free Images. Àṣà àtọwọ́dọ́wọ́, ọwọ́ ni a fi njẹ...
View ArticleEwu ifi Ilé-àpèjẹ dipò Ilé-ìkàwé, MTN fẹ́ gbé Ilé-ìkàwé kúrò ni...
Ilé-ìkàwé MTN – MTN to withdraw multi-million digital library donated to UNILAG Ilé-ìkàwé gẹ́gẹ́ bi orúkọ yi ti jẹ ni èdè Yorùbá, jẹ ibi ti wọn kó oriṣiriṣi iwé si, fún ọmọ ilé-iwé àti...
View ArticleÌPANU – SNACKSOriginally Posted on February 22, 2013, last updated on...
Yorùbá ka ìpanu si ohun ti anjẹ lati mu inu duro pataki ni arin ounje aro ati ale. A le ka si ounje osan. Traditionally, Yoruba people regard snacks as stop-gap chewable, particularly between...
View ArticleÌbà Àkọ́dá – Reverence to the First BeingOriginally Posted on October 2,...
Obinrin ti ó́ nṣe Ì̀bà Aṣẹ̀dá – A woman paying reverence to the Creator. Courtesy: @theyorubablog Ìbà Àkọ́dá, ìbà Aṣẹ̀dá Ìbà ni n ó f’òní jú, mo r’íbà, k’íbà ṣẹ Nínú ríríjẹ, nínú àìríjẹ Mo wá gbégbá...
View Article“Orúkọ Yorùbá ti o ti inu Ẹsin Ìgbàgbọ jade” – “Yoruba names that...
Yorùbá jẹ èrè àti ka Ìwé Mímọ́ ti a mọ̀ si “Bibeli Mímọ́” nitori iṣẹ́ ribiribi ti Olõgbe Olóri àwọn Àlùfáà Samuel Ajayi-Crowther ṣe lati túmọ Bibeli Mímọ́ si èdè Yorùbá ni Àádóje...
View Article“Òṣì ló njẹ tani mọ̀ ẹ́ ri, owó ló njẹ mo bá ẹ tan” – “Poverty is...
Ni ayé igbà kan, bi èniyàn bá jẹ́ alágbára, ti ó tẹpá-mọ́ṣẹ́, ti ó si tún ni iwà ọmọlúwàbí, iyi wà fun bi kò ti ẹ ni owó, ju olówó rẹpẹtẹ ti kò si ẹni ti ó mọ idi owó rẹ ni...
View ArticleOhun ti mo fẹ́ràn nipa Ìsimi Iparí Ọ̀sẹ̀ – What I love about the Weekend...
Ni ọjọ́ Ẹti, ọjọ́ karun ti a ti bẹ̀rẹ̀ ilé-iwé ni ọ̀sẹ̀, inú mi ma ń dùn nitori ilé-iwé ti pari ni agogo kan ọ̀sán, ti ìsimi bẹ̀rẹ̀. Mo fẹ́ràn ìsimi ipari ọ̀sẹ̀ nitori mo ma nri àwọn òbí mi....
View ArticleBẹni, Bẹ́ẹ̀kọ́ Ìbò Ọ̀rọ̀ Ìlú ni Ìlú-Ọba: Ẹ̀kọ́ fún Orilẹ̀-èdè...
Ì̀bò Ọ̀rọ̀ Ìlu ni Ìlú-Ọba’ UK Referendum Ni Ìlú-Ọba, lẹhin ọdún mẹtalelogoji, èrò jade lati di ìbò bẹni-bẹ́ẹ̀kọ́ lori àjọṣepọ̀ pẹ̀lú ẹgbẹ́ Ìlú-Oyinbo méjidinlọ́gbọ̀n ni Ọjọ́bọ̀, oṣu...
View Article