Quantcast
Channel: The Yoruba Blog
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ọ̀dájú ló bi owó, ìtìjú ló bi igbèsè”: “Shrewdness gives birth to money...

Gẹ́gẹ́bí ọ̀rọ̀ Yorùbá ti ó ni “Iṣẹ́ ni oogun ìṣẹ́”, jẹ́ òtítọ́, bi òṣìṣẹ́ bá ri owó gbà ni àsìkò, tàbi gba ojú owó fún iṣẹ́ ti wọn ṣe.  Òṣìṣẹ́ ti ó ṣiṣẹ́ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ wákàtí/àkókò lórí owó kékeré, kò...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ìtàn àròsọ bi obinrin ti sọ Àmọ̀tékùn di alábàwọ́n: The Folklore on...

Ni igba kan ri, Àmọ̀tékùn ni àwọ̀ dúdú ti ó jọ̀lọ̀, ṣùgbọ́n ni ọjọ́ kan, Àmọ̀tékùn wá oúnjẹ õjọ́ rẹ lọ.  Ó dé ahéré kan, ó ṣe akiyesi pe obinrin kan ńwẹ̀, inú rẹ dùn púpọ̀ pé...

View Article


Pi pè àti Orin fún orúkọ ọjọ́ ni èdè Yorùbá – Yoruba Days of the week...

http://www.theyorubablog.com/wp-content/uploads/2014/07/Oruko-Ojo-ni-ede-Yoruba-Days-of-the-week.wav Orúkọ Ọjọ́ni èdè Yorùbá                 Days of the Week In English Àìkú/Ọjọ́ Ọ̀sẹ̀/Ìsimi...

View Article

“Odò ti ó bá gbàgbé orisun gbi gbẹ ló ngbẹ” – “A river that forgets its...

Orúkọ idile Yorùbá ti ó nparẹ́ nitori èsìn.  Àwọn orúkọ ìdílé wọnyi kò di ẹlẹ́sìn lọ́wọ́ lati ṣe iṣẹ́ rere tàbi dé ọ̀run, ENGLISH TRANSLATION Yoruba family names that are disappearing....

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ará Ilú Nigeria: “Fi Ẹ̀tẹ̀ silẹ̀ pa Làpálàpá” – Nigerians are:...

Ẹ̀tẹ̀ tó mbá ilú jà ni ‘iwà-ibàjẹ́’.  Ìyà ti ará ilú njẹ lọ́wọ́lọ́wọ́, ki i ṣe èrè iwà-ibàjẹ́ ọdún kan, ṣùgbọ́n  ti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún.  Kò si ìfẹ́ ilú, nitori eyi, àwọn oniwà ibàjẹ́...

View Article


Ẹ̀̀ya orí ni èdè Yorùbá – Parts of Head in Yoruba LanguageOriginally Posted...

Orúkọ ẹ̀yà ara ṣe pàtàkì lati mọ nípa kíkọ́ èdè nítorí ó ma nwà nínú ọ̀rọ̀.  Mí mọ awọn orúkọ wọnyi á́ tún jẹ ki èdè Yorùbá yé àwọn ti ó ni ìfẹ́ lati kọ èdè.  A lérò wípé àwòrán àti pípè tí ó wà ni...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“A ki i fi ọjọ́ kan bọ́ ọmọ tó rù”: Ìmọ̀ràn fún Òṣèlú tuntun àti...

Ọmọ ki dédé rù lai ni idi.  Lára àwọn idi ti ọmọ lè fi rù ni: àìsàn, ebi, òùngbẹ, ìṣẹ́, ai ni alabojuto, òbí olójú kòkòrò, ai ni òbí àti bẹ ẹ bẹ lọ. Orilẹ̀ èdè Nigeria ti jẹ gbogbo...

View Article

BÍBẸ̀ ÈKÓ WÒ FÚN Ọ̀SẸ̀ KAN (ỌJỌ́ KEJÌ) – Visiting Lagos for a Week (Day...

Download: A conversation in Yoruba (Day 2) You can also download the Yoruba alphabets by right clicking this link: A conversation in Yoruba – Day 2(mp3) ỌJỌ́ KEJÌ – DAY TWO ONÍLÉ (HOST OR HOSTESS)...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ìṣe Ilé ló mbá ni dode – Trudy Alli-Balogun ja Ilé-Iṣẹ́ rẹ lólè – The...

Ìbá ṣe pọ̀ laarin Yorùbá àti Ìlú-Ọba ti lé ni igba ọdún nitori òwò Òkè-òkun, pàtàki òwò ẹrú àti fún ẹ̀kọ́ ni ilé iwé giga.  Nitori eyi, àṣà àti èdè Yorùbá kò ṣe fi ọwọ́...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ikú tó fẹ́ pani, bó bá sini ni fìlà, ọpẹ́ ló yẹ ká dá”: Idibò yan...

Ni igbà ipalẹ̀mọ́ idibò, ẹ̀rù ba ará ilú nitori wọn kò mọ ohun ti ó lè sẹlẹ̀.  Àwọn ti ó ndu ipò jade ni rẹpẹtẹ fún ètò-òṣèlú, eyi ti ó fa ki àwọn jàndùkú bẹ̀rẹ̀ ijà ti ó fa...

View Article

Wi wé Gèlè Ìgbàlódé – How to tie Modern Head ScarfsOriginally Posted...

Originally posted 2015-07-07 19:41:40. Republished by Blog Post Promoter

View Article

Ìtán ti a fẹ́ kà loni dá lóri Bàbá tó kó gbogbo Ẹrù fún Ẹrú – The...

Originally posted 2017-12-06 00:23:08. Republished by Blog Post Promoter

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ìtàn Ìjà laarin Ọ̀kẹ́rẹ́ àti Asin – Ìgbẹ̀hìn Ìjà fún Asin àti...

Ni ayé igbà kan ri, àwọn ẹranko ni ọjà ti wọn.  Ni ọjọ́ ọjà, Kìnìún, Ajá, Ìgalà, Ikõkò, Kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀, Erin, Ẹkùn,  Ìjàpá, Ọ̀kẹ́rẹ́, Eku-Asin, àti àwọn ẹranko yoku gbé irè oko àti...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Bi a bá pẹ́ láyé, a ó jẹ ẹran ti o ́tó Erin” – “If one lives long...

Erin – Elephant Erin jẹ ẹran ti ó tóbi ju gbogbo ẹranko ti a mọ̀ si ẹran inú igbó àti ẹran-àmúsìn, ti a mọ̀ ni ayé òde òni.  Bi a bá ṣe àyẹ̀wò bi Yorùbá ti ńgé ẹran ọbẹ̀, ó ṣòro lati...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ààntéré ọmọ Òrìṣà-Omi – “Ọmọ o láyọ̀lé, ẹni ọmọ sin lo bimọ”: Aantere...

Yorùbá ka ọmọ si ọlá àti iyì ti yio tọ́jú ìyá àti bàbá lọ́jọ́ alẹ́.  Eyi han ni orúkọ ti Yorùbá nsọ ọmọ bi: Ọmọlọlá, Ọmọniyi, Ọmọlẹ̀yẹ, Ọmọ́yẹmi, Ọlọ́mọ́là, Ọlọ́mọlólayé, Ọmọdunni,...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Bi Ọdẹ bá ro ìṣẹ́ ro ìyà inú igbó, ti ó bá pa ẹran kòní fẹ́nì kan jẹ – If the...

Ọlọ́dẹ/Ọdẹ – Hunter Láyé àtijọ́, iṣẹ́ Ọdẹ jẹ ikan ninú iṣẹ gidi ni ile Yorùbá.  Ògbójú Ọdẹ ló npa ẹranko bi Erin, Ẹkùn, Kìnìún àti Ẹfòn, Ìmàdò, Ikõkò, nígbàtí àwọn to nṣe Ọdẹ etílé npa ẹranko ìtòsí ilé...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“A kì í fi Oníjà sílẹ̀ ká gbájúmọ́ alápepe – Pí pa Àjòjì ni Gúsù...

Pí pa Àjòjì ni Gúsù ilẹ̀ Aláwọ̀-dúdú – South Africa’s xenophobic attacks Òwe Yorùbá kan sọ pé “Amúkun, ẹrù ẹ́ wọ́, ó ni ẹ̃ wò ìsàlẹ̀”.  Òwe yi ṣe é lò lati ṣe àyẹ̀wò ìṣẹ̀lẹ̀ pí pa...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ori bí bẹ́, kọ́ ni oògùn ori-fí fọ́” – A fi àsikò ọdún Keresimesi mú...

Yorùbá ni “Ibi ti ẹlẹ́kún ti nsun ẹkún ni aláyọ̀ gbe nyọ́”.  Òwe yi fihan ohun tó nṣẹlẹ̀ ni àgbáyé.  Bi ọ̀pọ̀ àwọn ti ó wà ni Òkè-òkun ti nra ẹ̀bùn àti ọ̀pọ̀ oúnjẹ ni oriṣiriṣi fún...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Àjàpá sọ Ẹlẹ́dẹ̀ di ọ̀bùn – “Alágbára má mèrò; baba ọ̀le; Ọgbọ́n ju...

Ọ̀rọ̀ Yorùbá ni “Àlébù ki ṣe ẹ̀gàn tàbi agọ̀; ṣùgbọ́n, ẹ̀gàn àti agọ̀ ni fún ẹni ti ojú rẹ fọ́ si àlébù ara rẹ”.  Irú ẹni bẹ̃, kò lè ri àtúnṣe tàbi sọ àlèbú yi di ohun ini....

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ki Àgbàdo tó di Ẹ̀kọ, a lọ̀ ọ́ pa pọ̀: Ògì Ṣí ṣe” – “For Corn to become...

Ra Àgbàdo lọ́jà – Buy the Corn Àgbàdo ni wọn fi nṣe Ògì.  Ògì ni wọn fi nṣe Ẹ̀kọ́.  Ògì ṣí ṣe fẹ ìmọ́ tótó, nitori eyi, lai si omi, Ògì kò lè ṣe é ṣe.  Ọkà oriṣiriṣi ló wà ṣùgbọ́n,...

View Article
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live