Mọ̀ mí, nmọ̀ ẹ́, “Ẹni tó lọ si ilé àna, lọ sọ èdè oyinbo, ni yio túmọ̀...
Ni ayé àtijọ́, òbi ni o nfẹ iyàwó fún ọmọ ọkùnrin wọn. Bi òbi bá ri ọmọ obinrin ti o dára ni idile ti o dára, wọn á lọ fi ara hàn lati tọrọ rẹ fún ọmọ wọn ọkunrin. Àṣà yi ti yàtọ̀ ni...
View Article“Orúkọ ti òbi Yorùbá nsọ Àbíkú” – “Yoruba parental names associated...
(Olóògbé Ọ̀jọ̀gbọ́n Olikoye Ransome Kuti – Oníṣègùn-Ọmọdé ti gbogbo àgbáyé mọ̀, Òjíṣẹ́-Òṣèlú Nigeria ni ọdún keji-din-lọ́gbọ̀n si ọdún keji-lé-lógún sẹhin, ṣe irànlọ́wọ́ gidigidi...
View Article‘Gómìnà Ìpínlẹ̀ Yorùbá, ẹ pèsè omi mi mun fún ará ilú ki wọ́n yé...
Ìjọba Ológun àkọ́kọ́ ni abẹ́ Olóògbé Ọ̀gágun Aguiyi Ironsi, da gbogbo ipinlẹ̀ pọ si abẹ́ Ìjọba àpapọ̀. Ki wọ́n tó dá àwọn ipinlẹ̀ pọ̀, àwọn ipinlẹ̀ ndàgbà sókè gẹ́gẹ́ bi ohun ti ó ṣe...
View Article“Bi eyi ò ṣe, omiran yio ṣe – bi Ọlọrun o pani, ẹnikan ò lè pani”: If this...
Ìtàn yi dá lori Bàbá ti aládũgbò mọ si “Bàbá Beyioṣe”. Bàbá yi jẹ onígbàgbọ́, ti ki ja tabi ṣe ãpọn. O bi ọmọ mẹta ti wọn jọ ngbe nitori iyawo rẹ ti kú. Ni ilé ti o ngbe, ó fi ifẹ...
View Article“Ẹni bá wá iwa-kuwa, ojú rẹ á ri irikuri” – Ìtàn bi imú Erin ti di...
Ni igbà kan ri, imú Erin dàbi ti àwọn ẹranko tó kù ni, ṣùgbọ́n Erin fi aigbọ tara ẹni, di o ni imú gigùn. Gbogbo nkan tó nlọ ni ayé àwọn ẹranko yoku ni Erin fẹ tọpinpin rẹ. Yorùbá ni...
View Article“Orúkọ Yorùbá ti o ti inu Ẹsin Ìgbàgbọ jade” – “Yoruba names that...
Yorùbá jẹ èrè àti ka Ìwé Mímọ́ ti a mọ̀ si “Bibeli Mímọ́” nitori iṣẹ́ ribiribi ti Olõgbe Olóri àwọn Àlùfáà Samuel Ajayi-Crowther ṣe lati túmọ Bibeli Mímọ́ si èdè Yorùbá ni Àádóje...
View Article“Ọ̀pọ̀ ni eṣú fi nya igi oko: Ìbò ni ipinlẹ Ọ̀ṣun” – “There is strength in...
Ninú Ẹ̀yà mẹrin-din-logoji orilẹ̀ èdè Nigeria, ẹ̀yà mẹ́fà ni o wa ni ipinlẹ Yorùbá lápapọ̀. Àwọn ẹ̀yà wọnyi ni: Èkó – ti olú ilú rẹ jẹ Ìkẹjà; Èkiti – ti olú ilú rẹ jẹ Adó-Èkiti;...
View Article“Olóri Ẹbi, Baba Bùkátà” – “Headship of a Family is the Father of...
Olóri Ẹbi – Head of the Family connotes responsibiliies. Courtesy: @theyorubablog Olóri Ẹbi jẹ àkọ́bi ọkùnrin ni idilé. Bi àkọ́bi bá kú, ọkùnrin ti ó bá tẹ̀le yio bọ si ipò. Iṣẹ́ olóri...
View ArticleOrukọ́ Ẹranko àti Àwòrán – Yoruba Names of Animals and pictures
Originally posted 2013-06-21 22:30:27. Republished by Blog Post Promoter
View ArticleÀjùmòbí kò kan tãnu… Same parentage does not compel compassion…
Same parentage does not compel compassion. Òwe Yorùbá ní “Àjùmòbí kò kan tãnu, ẹni Olúwa bá rán síni ló nṣeni lõre”. Òwe yi wúlò lati gba àwọn ènìà tí o gbójúlé ẹbí níyànjú. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ rò wípé ẹ̀tọ́...
View ArticleOwó orí ìyàwó –“Bíbí ire kò ṣe fi owó ra”: Bride Price – “Good pedigree...
OWO NAIRA Bi ọkọ ìyàwó bà ti lówó tó ni ó ti lè fi owó si inú àpò ìwé fún owó orí àti àwọn owó ẹbi yókù. Ni ayé òde òní, owó fún àpò ìwé méjìlá wọnyi lè bẹ̀rẹ̀ lati...
View Article“Àṣejù Baba Àṣetẹ́” – Ìtàn bi Ojúkòkòrò àti Ìgbéraga ti jẹ́...
Ni ìgbà àtijọ́, ọkùnrin kan wa ti orúkọ rẹ njẹ́ Ìgbéraga. Wọ́n bi Ìgbéraga si ilé olórogún, àwọn ìyàwó bàbá́ rẹ yoku ni ó tọ nitori ìyá rẹ kú nigbati ó wà ni kékeré. Lẹhin ti o...
View ArticleÀjàpá rẹ Erin sílẹ̀ – “Ìjàlọ ò lè jà, ó lè bọ́ ṣòkòtò ni idi...
Erin jẹ ẹranko ti Ọlọrun da lọ́lá pẹlu titobi rẹ ninu igbo. Yorùbá ni “Koríko ti Erin bá ti tẹ̀, àtẹ̀gbé ni láyé”, oko ti Erin bá wọ̀, olóko bẹ wọ igbèsè tori ibajẹ ti o ma ṣẹlẹ̀ si irú...
View Article“Ni Ayé òde òni, njẹ́ ó yẹ ki a pọ́n Àṣà fi fẹ́ Iyàwó púpọ̀ lé ni...
Ni igbà àtijọ́, oníyàwó kan kò wọ́pọ̀ nitori iṣẹ́ Àgbẹ̀. Àṣà fi fẹ́ iyàwó púpọ̀ ṣe kókó nitori bibi ọmọ púpọ̀ pàtàki ọmọ ọkùnrin fún irànlọ́wọ́ iṣẹ́-oko. Fi fẹ̀ iyàwó púpọ̀ kò...
View ArticleÌtàn iyàwó ti ó fi ẹ̀mi òkùnkùn pa iyá-ọkọ: Ẹni a fẹ́ la mọ̀, a ò...
Ìtàn ti ó wọ́pọ̀ ni, bi iyá-ọkọ ti burú lai ri ìtàn iyá-ọkọ ti ó dára sọ. Eyi dákún àṣà burúkú ti ó gbòde láyé òde òni, nipa àwọn ọmọge ti ó ti tó wọ ilé-ọkọ tàbi obinrin...
View Article“Gèlè ò dùn bi ká mọ̀ ọ́ wé, ká mọ̀ ọ́ wé, kò tó kó yẹni”: “Head tie is not...
Aṣọ Yorùbá, ìró àti bùbá kò pé lai si gèlè. Gèlè oriṣiriṣi ló wà̀, a lè lo gèlè aṣọ ìbílẹ̀ bi: aṣọ òfi/òkè, àdìrẹ, tàbi ki á yọ gèlè lára aṣọ. Ọpọlọpọ gèle ìgbàlódé wá lati òkè òkun. Ìmúra obinrin...
View Article“Ará Ilú Nigeria: “Fi Ẹ̀tẹ̀ silẹ̀ pa Làpálàpá” – Nigerians are:...
Ẹ̀tẹ̀ tó mbá ilú jà ni ‘iwà-ibàjẹ́’. Ìyà ti ará ilú njẹ lọ́wọ́lọ́wọ́, ki i ṣe èrè iwà-ibàjẹ́ ọdún kan, ṣùgbọ́n ti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún. Kò si ìfẹ́ ilú, nitori eyi, àwọn oniwà ibàjẹ́...
View Article“Ẹ Kú Ọwọ́ Lómi Là Nki Ọlọ́mọ Tuntun – Ìtọ́jú Ọmọ Tuntun ni Àtijọ́”:...
Ni ayé àtijọ́, kò si itẹdi à lò sọnù bi ti ayé òde òni. Bẹni wọn kò lo ìgò oúnjẹ lati fún ọmọ tuntun ni oúnjẹ. Ri rọ ọmọ – Yoruba Traditional baby feeding. Courtesy:@theyorubablog Ọwọ́...
View ArticleIMULO ÒWE YORUBA: APPLYING YORUBA PROVERBS
“A NGBA ÒRÒMỌDÌYẸ LỌWỌ IKÚ O NI WỌN O JẸ KI OHUN LỌ ATAN LỌJẸ” A le lo òwe yi lati kilọ fun ẹni to fẹ lọ si Òkèokun (Ìlu Òyìnbó) lọna kọna lai ni ase tabi iwe ìrìnà. Bi ẹbi, ọrẹ tabi ojulumọ to mọ...
View ArticleOrúkọ ti ó wọ́pọ̀ ni idile “Ọlá”, “Ọba”, “Ìjòyè” àti “Akinkanjú ni...
A Yoruba Names Short Form English meaning Abimbọ́lá Bimbọ Met wealth at birth Abisọ́lá Bisọ́lá Born into wealth Abiọ́lá Biọ́lá Born into wealth Adébisi Adé/Bisi Crown has increased by birth...
View Article