Quantcast
Channel: The Yoruba Blog
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live

Image may be NSFW.
Clik here to view.

ẸRÙ FÚN ÌDÍLÉ ÌYÀWÓ – LIST FOR BRIDE’S FAMILY – Apá Kẹta – Part Three

Gifts at a modern Yoruba Traditional wedding — courtesy of @theYorubablog Ìyàtọ̀ diẹ̀ ló wà lãrin awọn ẹru igbéyàwó ti a kọ́ si ojú iwé yi lati idile si idile. Fún àpẹre: idile miran fẹ...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Iṣẹ́ ajé, sọ ọmọ nù bí òkò” –“Working for survival throws away the child...

Ọjọ́ ti pẹ́ ti Yorùbá ti ńkúrò ni ilú kan si ilú keji, yálà fún ọrọ̀ ajé tàbi fún ẹ̀kọ-kikọ́.   Ni ayé àtijọ́, ọjọ́ pípẹ́ ni wọn fi ńrin irin-àjò nitori irin ti ọkọ̀ òfúrufú lè...

View Article


“Kí Kà ni Èdè Yorùbá” – “Counting or Numbers in Yoruba”

Yorùbá ni bi wọn ti ma a nka nkàn ki wọ́n tó bẹ̀rẹ̀ si ka a ni èdè Gẹ̀ẹ́sì.  Ẹ ṣe àyẹ̀wò kíkà ni èdè Yorùbá ni ojú ewé yi: ENGLISH TRANSLATION Counting or numbers in Yoruba before the...

View Article

“Ọbẹ̀ tó dùn, Owó ló pá: Àwòrán àti pi pè Èlò Ọbẹ̀”–“Tasty Soup,...

Òwe Yorùbá ni “Ọbẹ̀ tó dùn, owó ló pá”, ṣùgbọ́n kò ri bẹ̃ fún ẹni ti kò mọ ọbẹ̀ se.  Elomiran lè lo ọ̀kẹ́ àimọye owó lati fi se ọbẹ̀ kó má dùn nitori, bi iyọ̀ ò ja, ata á pọ̀jù...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Bi a bá pẹ́ láyé, a ó jẹ ẹran ti o ́tó Erin” – “If one lives long...

Erin – Elephant Erin jẹ ẹran ti ó tóbi ju gbogbo ẹranko ti a mọ̀ si ẹran inú igbó àti ẹran-àmúsìn, ti a mọ̀ ni ayé òde òni.  Bi a bá ṣe àyẹ̀wò bi Yorùbá ti ńgé ẹran ọbẹ̀, ó ṣòro lati...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Àròkàn ló n fa ẹkún à sun à i dákẹ́: Anguish of mind is the root...

Ohun ti Yorùbá mọ̀ si àròkàn n irònú igbà gbogbo.  Kò si ẹni ti ki ronú, ṣùgbọ́n àròkàn léwu.  Inú rirò yàtọ si àròkàn. Inu rirò ni àwọn Onimọ-ijinlẹ̀ lò lati ṣe ọkọ̀ òfúrufú...

View Article

Àwòrán àti pípè orúkọ Èlò Ọbẹ̀ Yorùbá – Pictures and pronunciation...

Àwọn èlò ọbẹ̀ Yorùbá, ẹni ti ó bá mọ ọbẹ̀ se, yio mọ èlò ọbẹ̀ ti ohun yio ra àti bi yio ti se, ṣùgbọ́n ẹni ti kò mọ ọbẹ̀ se, lè lo owó ai mọye lati se ọbẹ̀, ki ọbẹ̀ rẹ má dùn.  Fún...

View Article

Àmì – Yoruba Accent

Àmì – ṣe pàtàkì ni èdè Yorùbá nitori lai si àmì, àṣìwí tàbi àṣìsọ á pọ̀.  Ọ̀rọ̀ kan ni èdè Yorùbá lè ni itumọ rẹpẹtẹ, lai si àmì yio ṣòro lati mọ ìyàtọ.  Àmì jẹ ki èdè Yorùbá...

View Article


Kòró/Kòrọ́nà – Ogun ti a kò rí: Coronavirus – the invisible war

Kòró/Kòrọ́nà – Ogun ti a kò rí: Coronavirus – the invisible war Àjàkálẹ̀ àrùn ma ńṣẹlẹ̀ láti ìgbà-dé-ìgbà. Ni igba kan ri, àjàkálẹ̀ àrùn bi Ṣọ̀pọ̀ná/Olóde, Ikọ́-ife, Onígbáméjì...

View Article


Àpẹrẹ Ìsìnkú Ìbílẹ̀ fún Arúgbó ni Ilẹ́ Yorùbá – Example of Yoruba...

Ìnáwó rẹpẹtẹ ni ìsìnkú arúgbó jẹ́ ni ilé Yorùbá.  Bi arúgbó bá kú ni ilé Yorùbá ki ṣe òkú ọ̀fọ̀ ṣùgbọ́n òkú ijọ àti ji jẹ, mi mu ni pàtàki bi irú arúgbó bá bi àwọn ọmọ ti...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ọba Aládélúsi Ògúnladé-Aládétóyìnbó gun Ori Oyè ilu Àkúrẹ́” –...

Déjì Àkúrẹ́ Ọba Aládélúsi Ògúnladé-Aládétóyìnbó pari gbogbo ètùtù ibilẹ ti Ọba Àkúrẹ́ ma nṣe lati gori oyè ni Ọjọ́rú, ọjọ́ kẹjọ, oṣù keje, ọdún Ẹgbãlemẹ̃dógún, lati di Ọba...

View Article

ÌHÀ TI AWỌN ÒBÍ NI ILẸ̀ KAARỌ OOJIRE KỌ SI ÈDÈ YORÙBÁ: THE ATTITUDE...

A sọ wipe ọmọ kò gbọ́ èdè, tani kó kọ̃? Àwa òbí nii ṣe púpọ ni bi àwọn ọmọ wa ṣe mú èdè abi-nibi wọn. Àwa òbí lati yi ìhà ti a kọ si èdè Yorùbá padá, ti a kò bá fẹ́ ki o pòórá....

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ọ̀run nyabọ̀, ki ṣé ọ̀rọ̀ ẹnìkan – Ayé Móoru” –“Heaven is collapsing, is...

Ọ̀run nyabọ̀ – Nature’s fury Ìbẹ̀rù tó gbòde ayé òde òni ni pé “Ayé Móoru”, nitori iṣẹ̀lẹ̀ ti o nṣẹlẹ̀ ni àgbáyé bi òjò àrọ̀ irọ̀ dá ni ilú kan, ilẹ̀-riru ni òmìràn, ọ̀gbẹlẹ̀,...

View Article


“Ìwé àti kọ Yorùba lọfẹ lọwọ Àjàyí Crowther Fún Ra Rẹ”: Learn Yoruba for Free...

Ise Alagba Yoruba, Ajayi Crowther fun ra re. A Yoruba dictionary to look up basic vocabulary     Originally posted 2013-05-23 05:38:56. Republished by Blog Post Promoter

View Article

Kòkòrò – Names of Insects & Bugs in Yoruba

Kòkòrò jẹ́ ohun ẹ̀dá kékeré tó ni ìyẹ́, ti ó lè fò, òmíràn kò ni iyẹ́, ṣugbọn wọn ni ẹsẹ̀ mẹfa.  Ẹ ṣe àyẹ̀wò àpẹrẹ, àwòrán àti pi pè ni ojú ewé wọnyi. ENGLISH TRANSLATION Insects...

View Article


“Ẹni ti ó bá mọ inú rò, á mọ ọpẹ́ dá”: Whoever can think/reason will...

Ọmọ bibi ni ewu púpọ̀, nitori eyi ni Yorùbá fi ma nki “ìyá ọmọ kú ewu”.  Ni ọjọ́ ìsọmọ lórúkọ tàbi ìkómọ, Bàbá, Ìyá, ẹbi àti ọ̀rẹ́ òbí ọmọ tuntun á fi ìdùnnú hàn nipa ṣíṣe ọpẹ́...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Àṣejù Baba Àṣetẹ́” – Ìtàn bi Ojúkòkòrò àti Ìgbéraga ti jẹ́...

Ni ìgbà àtijọ́, ọkùnrin kan wa ti orúkọ rẹ njẹ́ Ìgbéraga.  Wọ́n bi Ìgbéraga si ilé olórogún, àwọn ìyàwó bàbá́ rẹ yoku ni ó tọ nitori ìyá rẹ kú nigbati ó wà ni kékeré.  Lẹhin ti o...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Gbẹ̀dẹ̀ bi Ogún Ìyá, Ogún Bàbá ló ni ni lára – Maternal Inheritance...

Ogún jẹ́ gbogbo ohun ìní ti bàbá tàbi ìyá bá fi silẹ́ ti wọn bá kú.  Ni ìgbà àtijọ́, kò wọ́pọ̀ ki olóògbé ṣe ìwé-ìhágún, bi wọn ṣe má a pín ohun ini wọn lẹhin ikú.  Ọ̀pọ̀lọpọ̀...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ori ló mọ iṣẹ́ àṣe là”: Ògbójú-ọdẹ di Adẹmu fún Ará-Ọ̀run –“Destiny...

Ọkunrin kan wa láyé àtijọ́, Ògbójú-ọdẹ ni, ṣùgbọ́n bi ó ti pa ẹran tó, kò fi dá nkan ṣe.  Ọ̀pọ̀ igbà, ki ri ẹran ti ó bá pa tà, o ma ńpin fún ará ilú ni.  Nigbati kò ri ẹran pa mọ́,...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ohun ti ó ntán lọdún eégún”– Kérésìmesì ọdún Ẹgbã-lé-mẹ́rìnlà ti...

Bàbá-Kérésì – Father Christmas Ìwà alajẹtan ti bori iránti ohun ti Kérésìmesì wà fún.  Ọ̀pọ̀ kò ti ẹ̀ ránti pé iránti ọjọ́ ibi Jesu ni Ìjọba ṣe fún ará ilú ni ọjọ́ ìsimi ni ọjọ́...

View Article
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live