Quantcast
Channel: The Yoruba Blog
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Mọ̀ mí, nmọ̀ ẹ́, “Ẹni tó lọ si ilé àna, lọ sọ èdè oyinbo, ni yio túmọ̀...

Ni ayé àtijọ́, òbi ni o nfẹ iyàwó fún ọmọ ọkùnrin wọn.  Bi òbi bá ri ọmọ obinrin ti o dára ni idile ti o dára, wọn á lọ fi ara hàn lati tọrọ rẹ fún ọmọ wọn ọkunrin.  Àṣà yi ti yàtọ̀ ni...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ìtàn àròsọ bi obinrin ti sọ Àmọ̀tékùn di alábàwọ́n: The Folklore on...

Ni igba kan ri, Àmọ̀tékùn ni àwọ̀ dúdú ti ó jọ̀lọ̀, ṣùgbọ́n ni ọjọ́ kan, Àmọ̀tékùn wá oúnjẹ õjọ́ rẹ lọ.  Ó dé ahéré kan, ó ṣe akiyesi pe obinrin kan ńwẹ̀, inú rẹ dùn púpọ̀ pé...

View Article


ỌJỌ GBOGBO NI TI OLÈ – Everyday is for the thief … a warning to fraudsters

“ỌJỌ GBOGBO NI TI OLÈ, ỌJỌ KAN NI TOLÓHUN”: “EVERYDAY IS FOR THE THIEF, ONE DAY FOR THE OWNER”. Ní ọjọ Ẹti ọjọ keji lelogun oṣu keji ọdún yi, Ẹrọ amóhùn máwòrán Iluọba (BBC 1) tu asiri ọmọkunrin kan ti...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

A Dúpẹ́ fún Ẹyin Àyànfẹ́ tó Bẹ̀rẹ̀ sí Tẹ̀léwa ní Twitter: Thank You to Our...

Twitter followers Ẹfi ojú sọ́na lọ́sọ̀sẹ̀ fún kíkọ nípa àwọn nkan wọnyi lédè Yorùbá àti ìtum̀ọ lédè Gẹ̀ẹ́sì: Ìmúlò Òwe, Kíkọ Èdè, Ìtàn àti Ìròyìn tí a lè fi kọ́gbọ́n, Ẹgbẹ́ àti Oúnjẹ Yorùbá ni ìlú...

View Article

“Ẹni ti ó bá mọ inú rò, á mọ ọpẹ́ dá”: Whoever can think/reason will...

Ọmọ bibi ni ewu púpọ̀, nitori eyi ni Yorùbá fi ma nki “ìyá ọmọ kú ewu”.  Ni ọjọ́ ìsọmọ lórúkọ tàbi ìkómọ, Bàbá, Ìyá, ẹbi àti ọ̀rẹ́ òbí ọmọ tuntun á fi ìdùnnú hàn nipa ṣíṣe ọpẹ́...

View Article


Àmì – Yoruba Accent

Àmì – ṣe pàtàkì ni èdè Yorùbá nitori lai si àmì, àṣìwí tàbi àṣìsọ á pọ̀.  Ọ̀rọ̀ kan ni èdè Yorùbá lè ni itumọ rẹpẹtẹ, lai si àmì yio ṣòro lati mọ ìyàtọ.  Àmì jẹ ki èdè Yorùbá...

View Article

“Ìwé àti kọ Yorùba lọfẹ lọwọ Àjàyí Crowther Fún Ra Rẹ”: Learn Yoruba for Free...

Ise Alagba Yoruba, Ajayi Crowther fun ra re. A Yoruba dictionary to look up basic vocabulary     Originally posted 2013-05-23 05:38:56. Republished by Blog Post Promoter

View Article

“Igbà kan nlọ, igbà kan nbọ̀, igbà kan kò dúró titi” – “Time passes by...

Oriṣi mẹta ni Yorùbá ka igbà ẹ̀dá si.  Gẹ́gẹ́ bi àgbà ninú Olórin ilẹ̀ Aláwọ̀dúdú Olóyè Ebenezer Obey (Fabiyi) ti kọ́ pé “Igbà mẹta ni igbà ẹ̀dá láyé, igbà òwúrọ̀, igbà ọ̀sán,...

View Article


Ẹ̀kọ́ àti Ọgbọ́n ni Ọ̀rọ̀ Àgbà lati Ẹnu Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọmọlolú Olunlọyọ lórí...

Bi a ba fi eti si ọ̀rọ̀ ti àgbà Yorùbá Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọmọlolú Olunlọyọ  ni ori ẹ̀rọ “Amóhùnmáwòrán Òpómúléró”, ni ori ayélujára, a o ṣe àkíyèsí àwọn nkan wọnyi:...

View Article


“Ilé làńwò ki a tó sọmọ lórúkọ – Orúkọ Yorùbá” – Home is examined...

Ni àṣà Yorùbá, ni ayé àtijọ́, ọjọ́ keje ni wọn ńsọmọ obinrin ni orúkọ, ọjọ́ kẹsan ni ti ọmọ ọkùnrin, ṣùgbọ́n ni ayé òde òni, ọjọ kẹjọ ni wọn sọ gbogbo ọmọ lórú̀kọ.  Yorùbá ki sọmọ...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ni ilú Afọ́jú, Olójú kan Lọba”: Ìjọba Òṣèlú tuntun gba Ìjọba ni...

Ọjọ́ itàn ni ọjọ́ kọkàndinlógún, oṣù karun, ọdún Ẹgbãlemẹ̃dógún jẹ fun orilẹ̀ èdè Nigeria àti gbogbo ilẹ̀ Aláwọ̀dúdú.  Kò wọ́pọ̀ ki Ìjọba Ológun tàbi Ẹgbẹ́ Òṣèlú gbà lati gbé...

View Article

“Kí Kà ni Èdè Yorùbá” – “Counting or Numbers in Yoruba”

Yorùbá ni bi wọn ti ma a nka nkàn ki wọ́n tó bẹ̀rẹ̀ si ka a ni èdè Gẹ̀ẹ́sì.  Ẹ ṣe àyẹ̀wò kíkà ni èdè Yorùbá ni ojú ewé yi: ENGLISH TRANSLATION Counting or numbers in Yoruba before the...

View Article

“Ti ibi, ti ire la wá ilé ayé” –Ọ̀rọ̀ àti Ìṣe Ìgboro ni Èkó: “We came into...

Èkó jẹ́ olú ìlú Nigeria fún ọpọlọpọ ọdún, ki wọn tó sọ Abuja di olú ìlú Nigeria, ṣùgbọ́n Èkó ṣi jẹ́ olú ìlú fún iṣẹ ọrọ̀ gbogbo Nigeria.  Nitori eyi, gbogbo ẹ̀yà Nigeria àti àwọn ará ìlú miran titi dé...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Bi eyi ò ṣe, omiran yio ṣe – bi Ọlọrun o pani, ẹnikan ò lè pani”: If this...

Ìtàn yi dá lori Bàbá ti aládũgbò mọ si “Bàbá Beyioṣe”.  Bàbá yi jẹ onígbàgbọ́, ti ki ja tabi ṣe ãpọn.  O bi ọmọ mẹta ti wọn jọ ngbe nitori iyawo rẹ ti kú. Ni ilé ti o ngbe, ó fi ifẹ...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ránti Ọmọ Ẹni ti Iwọ Nṣe: Olè ki ṣe Orúkọ Rere lati fi Jogún” –...

Oriṣiriṣi òwe ni Yorùbá ni lati fihàn pé iwà rere ló ni ayé.  Iwà ni Yorùbá kàsí ni ayé àtijọ́ ju owó ti gbogbo ilú bẹ̀rẹ̀ si bọ ni ayé òde òni.  Fún àpẹrẹ, Yorùbá ni “Ẹni bá...

View Article


Ẹ̀̀ya orí ni èdè Yorùbá – Parts of Head in Yoruba Language

Orúkọ ẹ̀yà ara ṣe pàtàkì lati mọ nípa kíkọ́ èdè nítorí ó ma nwà nínú ọ̀rọ̀.  Mí mọ awọn orúkọ wọnyi á́ tún jẹ ki èdè Yorùbá yé àwọn ti ó ni ìfẹ́ lati kọ èdè.  A lérò wípé àwòrán àti pípè tí ó wà ni...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ìfẹ́ kò fọ́jú, ẹni ti ó wọnú ìfẹ́ ló fọ́jú: ‘Igbéyàwó ki ṣe ọjà...

Ni ayé àtijọ́, ki òbí tó gbà lati fi ọmọ fún ọkọ, wọn yio ṣe iwadi irú iwà àti àìsàn ti ó wọ́pọ̀ ni irú idile bẹ́ ẹ̀.  Nitori eyi, igbéyàwó ibilẹ̀ ayé  àtijọ́ ma npẹ́ ju ti ayé òde...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ìtàn iyàwó ti ó fi ẹ̀mi òkùnkùn pa iyá-ọkọ: Ẹni a fẹ́ la mọ̀, a ò...

Ìtàn ti ó wọ́pọ̀ ni, bi iyá-ọkọ ti burú lai ri ìtàn iyá-ọkọ ti ó dára sọ.  Eyi dákún àṣà burúkú ti ó gbòde láyé òde òni, nipa àwọn ọmọge ti ó ti tó wọ ilé-ọkọ tàbi obinrin...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ẹ Kú Ọwọ́ Lómi Là Nki Ọlọ́mọ Tuntun – Ìtọ́jú Ọmọ Tuntun ni Àtijọ́”:...

Ni ayé àtijọ́, kò si itẹdi à lò sọnù bi ti ayé òde òni.   Bẹni wọn kò lo ìgò oúnjẹ lati fún ọmọ tuntun ni oúnjẹ. Ri rọ ọmọ – Yoruba Traditional baby feeding. Courtesy:@theyorubablog Ọwọ́...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Bi Ọdẹ bá ro ìṣẹ́ ro ìyà inú igbó, ti ó bá pa ẹran kòní fẹ́nì kan jẹ – If the...

Ọlọ́dẹ/Ọdẹ – Hunter Láyé àtijọ́, iṣẹ́ Ọdẹ jẹ ikan ninú iṣẹ gidi ni ile Yorùbá.  Ògbójú Ọdẹ ló npa ẹranko bi Erin, Ẹkùn, Kìnìún àti Ẹfòn, Ìmàdò, Ikõkò, nígbàtí àwọn to nṣe Ọdẹ etílé npa ẹranko ìtòsí ilé...

View Article
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live