Quantcast
Channel: The Yoruba Blog
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live

Image may be NSFW.
Clik here to view.

ATỌ́NÀ LÉDÈ YORÙBÁ – Cardinal Directions in Yoruba

A compass showing the poles in Yoruba language. The image is courtesy of @theyorubablog   Originally posted 2013-04-16 19:01:07. Republished by Blog Post Promoter

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Bàbá Ìtàn Ìkọ̀lé-Èkìtì, Olóògbé Ọj̀ọ̀gbọ́n-Àgbáyé Adé Àjàyí...

http://www.theyorubablog.com/wp-content/uploads/2014/09/Baba-rele-Burial-of-an-elders-song.wav Babá re lé ò, Ilé ló lọ́ tarà-rà Bàbá re lé ò, Ilé ló lọ́ tarà-rà Ilé ò, ilé, Ilé ò,...

View Article


Bi mo ṣe lo Ìsimi Àjíǹde tó kọjá – How I spent the last Easter Holiday

Ìsimi ọdún Àjíǹde tó kọjá dùn púpọ̀ nitori mo lọ lo ìsimi náà pẹ̀lú ẹ̀gbọ́n Bàbá mi àti ẹbí rẹ ni ilú Èkó. Èkó jinà si ilú mi nitori a pẹ́ púpọ̀ ninú ọkọ̀ elérò ti àwọn òbí...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ohun jíjẹ pàtàki ti à ńfi Iṣu Ewùrà ṣe: Ìfọ́kọrẹ́ tàbi Ìkọ́kọrẹ́...

Ẹ ṣe àyẹ̀wò bi a ti ńṣe Ìfọ́kọrẹ́/Ìkọ́kọrẹ́ lójú iwé yi. Gbé epo kaná Kó èlò bi ẹ̀jà tútù tàbi gbigbẹ, edé, pọ̀nmọ́ sinú ikòkò epo-pupa yi Fi iyọ̀ àti iyọ̀ igbàlódé àti omi si...

View Article

“Ìkà gbàgbé Àjọbi, adánilóró̀ gbàgbé ọ̀la, ẹ̀san á ké lóri...

Yorùbá ni ètò àti òfin ti àwọn Àgbà, Ọba àti Ìjòyè fi nto ilú ki aláwọ̀-funfun tó dé.  Onirúurú ọ̀nà ni wọn ma fi nṣe idájọ́ ìkà laarin àwùjọ.  Wọn lè fi orin tú àṣiri...

View Article


Ounjẹ Yorùbá: Yoruba Food

Ẹ GBA OUNJẸ YORÙBÁ LÀ: SAVE YORÙBÁ: SAVE YORUBA FOOD Ọpọlọpọ oriṣiriṣi ounjẹ Yorùbá nparẹ lọ, nípàtàkì larin awọn to ngbe ìlú nla.  Òwe Yorùbá ni “Ki àgbàdo to de ilẹ aye, adíyẹ njẹ, adíyẹ nmu”....

View Article

“Ilé làńwò ki a tó sọmọ lórúkọ – Orúkọ Yorùbá” – Home is examined...

Ni àṣà Yorùbá, ni ayé àtijọ́, ọjọ́ keje ni wọn ńsọmọ obinrin ni orúkọ, ọjọ́ kẹsan ni ti ọmọ ọkùnrin, ṣùgbọ́n ni ayé òde òni, ọjọ kẹjọ ni wọn sọ gbogbo ọmọ lórú̀kọ.  Yorùbá ki sọmọ...

View Article

“Ṣe bi o ti mọ ki i tẹ́ – Ọdún wọlé dé”: “One who acts moderately will not...

Ọdún Kérésì jẹ́ ọdún Onigbàgbọ́ lati ṣe iránti ọjọ́ ibi Jésù Olùgbàlà.  Ọjọ́ kẹjọ lẹhin ọdún Kérésìmesì ni ọdún  tuntun.  Fún ayẹyẹ ọdún, kò si iyàtọ̀ laarin Ìgbàgbọ́ àti...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ẹ̀rù ló sọ ọmọ Ẹkùn di Ológbò/Ológìní tó fi di ”Ẹran-àmúsìn –Ọdẹ...

Ni igbà àtijọ́, ẹranko ti wọn pè ni Ẹkùn jẹ alágbára ẹranko, bẹni Kìnìún si jẹ́ alágbára ẹranko.  Bi Kìnìún ti lágbára tó ninú igbó, bi ó bá bú ramúramù, ohun gbogbo ninú igbó á...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Òṣì ló njẹ tani mọ̀ ẹ́ ri, owó ló njẹ mo bá ẹ tan” – “Poverty is...

Ni ayé igbà kan, bi èniyàn bá jẹ́ alágbára, ti ó tẹpá-mọ́ṣẹ́, ti ó si tún ni iwà ọmọlúwàbí, iyi wà fun bi kò ti ẹ ni owó, ju olówó rẹpẹtẹ ti kò si ẹni ti ó mọ idi owó rẹ ni...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Bi Egúngún/Eégún bá ńlé ni ki a má rọ́jú, bi ó ṣe ńrẹ ará ayé,...

Yorùbá ma ńṣe ọdún Egúngún/Eégún ni ọdọ-dún lati ṣe iranti Bàbánlá/Ìyánlá wọn ti ó ti di olóògbé nitori wọn ni iṣẹ́ lati ṣe laarin alàyè lati rán ará ilú leti pé ki wọn di...

View Article

ỌRỌ ÌYÀNJÙ (WORD OF ADVICE): Ẹni tólèdè lóni ayé ibi ti wọn ti nsọ

ỌRỌ ÌYÀNJÙ (WORD OF ADVICE) Ẹyin ọmọ Odùduwà ẹjẹ ki a ran rawa létí wípé “Ẹni tólèdè lóni ayé ibi ti wọn ti nsọ”.  Mo bẹ yin  ẹ maṣe jẹki  a tara wa  lọpọ nitorina ẹ maṣe jẹki èdè Yorùbà parẹ. Èdè ti a...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ọ̀gẹ̀dẹ̀ – “Ọ̀gẹ̀dẹ̀ dúdú/burúkú kò yá bù ṣán, ọmọ burúkú kò yá...

Ọ̀gẹ̀dẹ̀ àgbagbà àti ọ̀gẹ̀dẹ̀ wẹ́wẹ́ – Bunch of unripe Plantains and Bananas Banana Ọ̀gẹ̀dẹ̀ jẹ́ èso ti ó wọ́pọ̀ lára àwọn ohun ọgbin ti a lè ri ni ilẹ̀ Yorùbá pàtàki ni agbègbè Okitipupa ni...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

ÌGBÉYÀWÓ ÌBÍLẸ̀ – TRADITIONAL MARRIAGE

Gifts at a modern Yoruba Traditional wedding — courtesy of @theYorubablog Ìgbéyàwó ìbíle ní Ilẹ̀ Yorùbá jẹ́ àsìkò ti ẹbí ọkọ àti ì̀yàwó ma nparapọ.  Ìyàwó ṣíṣe ni ilẹ̀ Yorùbá kò pin sí ãrin ọkọ àti...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Bi ojú bá mọ́, Agbe á yalé Aláró, Àlùkò á yalé Olósùn,...

Bi a bá wo òwe yi, a o ri pe Agbe pọn bi aró, Àlùkò pupa bi osùn nigbati Lékeléke funfun bi ẹfun. Nitori eyi, bi wọn kò ti ẹ̀ lọ si ilé Aláró, Olósùn àti Ẹlẹ́fun, àwọ̀ wọn á si wa...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Obinrin ki ṣe Ẹrú tabi Ẹrù ti wọn njẹ mọ́ Ogún – Àsikò tó lati Dáwọ́...

Yorùba Dáwọ́ Àṣà ṣì Ṣúpó Dúró – Yoruba Stop Bequeathing Widows. Courtesy: @theyorubablog Ni ayé àtijọ́, àṣà ṣì ṣúpó wọ́pọ̀ ni Ilẹ̀ Yorùbá. Obinrin ti ọkọ rẹ̀ bá kú wọn yio fi jogún...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ohun ti ajá mã jẹ, Èṣù á ṣẽ”: “What the dog will eat, the Devil will...

Yorùbá ma nṣe rúbọ Èṣù nigba gbogbo ki ẹ̀sìn ìgbàgbọ́ tó gbalẹ̀.  Ounjẹ ni wọn ma fi ṣè rúbo ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà.  Irú ounjẹ yi ni Yorùbá npè ni “ẹbọ”.  Ìta gbangba ni wọn ma ngbe irú...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ki Àgbàdo tó di Ẹ̀kọ, a lọ̀ ọ́ pa pọ̀: Ògì Ṣí ṣe” – “For Corn to become...

Ra Àgbàdo lọ́jà – Buy the Corn Àgbàdo ni wọn fi nṣe Ògì.  Ògì ni wọn fi nṣe Ẹ̀kọ́.  Ògì ṣí ṣe fẹ ìmọ́ tótó, nitori eyi, lai si omi, Ògì kò lè ṣe é ṣe.  Ọkà oriṣiriṣi ló wà ṣùgbọ́n,...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Àjàpá fẹ́ kó bá Ajá – Kàkà ki eku májẹ sèsé, á fi ṣe àwàdànu” –...

Ajá dúró dèmί lọna, fẹrẹ kun fẹ 2ce Bί ὸ bá dúró dèmί lọna fẹrẹ kun fẹ Makékéké Olóko á gbọ fẹrẹ kun fẹ Á gbọ á gbéwa dè, fẹrẹ kun fẹ Á gbéwa dè, á gbàwá nίṣu fẹrẹ kun fẹ Ajá dúró dèmί lọna, fẹrẹ kun...

View Article

“Ìsọ̀rọ̀ ni igbèsi: Ibere ti ó wọ́pọ́ ni èdè Yorùba” – “Questions calls...

Ọpọlọpọ ibere ni èdè Yorùbá bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lu “ọfọ̀ – K”.  Yàtọ̀ fún li lò ọfọ̀ yi ninú ọ̀rọ̀, orúkọ enia tàbi ẹranko, ọfọ̀ yi wọ́pọ̀ fún li lò fún ibere.  Fún àpẹrẹ, orúkọ enia ti ó bẹ̀rẹ̀...

View Article
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live