Quantcast
Channel: The Yoruba Blog
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ọ̀dọ́ Kọ̀yà Ọlọpa orílẹ̀-èdè Nigeria – Nigeria Youths protest Police...

Ọlọpa ti fi iyà jẹ ará ilú fún igbà pípẹ́, nitori iwà-ibàjẹ́ àti gbi gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ ni iṣẹ́ Ọlọpa àti ni orilẹ̀-èdè Nigeria.  Ọlọpa ti tori àti gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ fi iyà jẹ ọlọ́jà, àgbẹ,...

View Article


IMULO ÒWE YORUBA: APPLYING YORUBA PROVERBS

“A NGBA ÒRÒMỌDÌYẸ LỌWỌ IKÚ O NI WỌN O JẸ KI OHUN LỌ ATAN LỌJẸ”  A le lo òwe yi lati kilọ fun ẹni to fẹ lọ si Òkèokun (Ìlu Òyìnbó)  lọna kọna lai ni ase tabi iwe ìrìnà.  Bi ẹbi, ọrẹ tabi ojulumọ to mọ...

View Article


“Orúkọ Yorùbá ti o ti inu Ẹsin Ìgbàgbọ jade” – “Yoruba names that...

Yorùbá jẹ èrè àti ka Ìwé Mímọ́ ti a mọ̀ si “Bibeli Mímọ́” nitori iṣẹ́ ribiribi ti Olõgbe Olóri àwọn Àlùfáà Samuel Ajayi-Crowther ṣe lati túmọ Bibeli Mímọ́ si èdè Yorùbá ni Àádóje...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Obinrin ki ṣe Ẹrú tabi Ẹrù ti wọn njẹ mọ́ Ogún – Àsikò tó lati Dáwọ́...

Yorùba Dáwọ́ Àṣà ṣì Ṣúpó Dúró – Yoruba Stop Bequeathing Widows. Courtesy: @theyorubablog Ni ayé àtijọ́, àṣà ṣì ṣúpó wọ́pọ̀ ni Ilẹ̀ Yorùbá. Obinrin ti ọkọ rẹ̀ bá kú wọn yio fi jogún...

View Article

Bi mo ṣe lo Ìsimi Àjíǹde tó kọjá – How I spent the last Easter Holiday

Ìsimi ọdún Àjíǹde tó kọjá dùn púpọ̀ nitori mo lọ lo ìsimi náà pẹ̀lú ẹ̀gbọ́n Bàbá mi àti ẹbí rẹ ni ilú Èkó. Èkó jinà si ilú mi nitori a pẹ́ púpọ̀ ninú ọkọ̀ elérò ti àwọn òbí...

View Article


Àgbo – Ewé àti Egbòigi fún ìtọ́jú – Yoruba Herbal remedies/Traditional...

Ki oògùn Òyinbó tó gbòde, ewé àti egbòigi ti ó wà ni oko tàbi àyíká ilé ni Yorùbá fi nki àgbo lati dí àisàn lọ́wọ́ tàbi wo àisàn.  Àwọn gbajúmọ̀ àti ọ̀dọ́ ayé òde òni ti...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ọ̀dájú ló bi owó, ìtìjú ló bi igbèsè”: “Shrewdness gives birth to money...

Gẹ́gẹ́bí ọ̀rọ̀ Yorùbá ti ó ni “Iṣẹ́ ni oogun ìṣẹ́”, jẹ́ òtítọ́, bi òṣìṣẹ́ bá ri owó gbà ni àsìkò, tàbi gba ojú owó fún iṣẹ́ ti wọn ṣe.  Òṣìṣẹ́ ti ó ṣiṣẹ́ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ wákàtí/àkókò lórí owó kékeré, kò...

View Article

Ẹ̀kọ́-ìṣirò ni èdè Yorùbá – Simple Arithmetic in Yoruba Language

Yorùbá ni bi wọn ti ma nṣe ìṣirò ki wọn tó bẹ̀rẹ̀ si ka ni èdè Gẹ̀ẹ́sì.  Akọ̀wé yi kọ ìṣirò ki ó tó bẹ̀rẹ̀ ilé-ìwé lọdọ ìyá rẹ̀ àgbà.  Nígbàtí ìyá-àgbà bá nṣe iṣẹ́ òwú “Sányán”...

View Article


Ìtàn ti a o kà loni dá lórí ìdí ti ọmọ Ẹkùn fi di Ológbò – The Yoruba...

Yorùbá ma npa ìtàn lati fi ṣe à ri kọ́gbọ́n tàbi fún ìkìlọ̀.  Ẹ ṣọ́ra lati fi ìbẹ̀rù àti ojo bẹ̀rẹ̀ ọdún nitori a ma a géni kúrú. Lára ẹ̀kọ́ ti a lè ri fi kọ́ ọgbọ́n ni ìtàn ti a ka yi...

View Article


Oriṣiriṣi Gèlè – Various types of Head Ties

Aṣọ Yorùbá kò pé, lai si Gèlè.  Bi Yorùbá bá wọ aṣọ ìbílẹ̀ fún òde ojoojúmọ́ tàbi fún ayẹyẹ, wọn ni lati wé gèlè ki imúra lè pé.  Fún ji jade ojoojúmọ́, a lè lo ipèlé aṣọ...

View Article

Ìtán ti a fẹ́ kà loni dá lóri Bàbá tó kó gbogbo Ẹrù fún Ẹrú – The...

Originally posted 2017-12-06 00:23:08. Republished by Blog Post Promoter

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

ÌGBÉYÀWÓ ÌBÍLẸ̀ – TRADITIONAL MARRIAGE

Gifts at a modern Yoruba Traditional wedding — courtesy of @theYorubablog Ìgbéyàwó ìbíle ní Ilẹ̀ Yorùbá jẹ́ àsìkò ti ẹbí ọkọ àti ì̀yàwó ma nparapọ.  Ìyàwó ṣíṣe ni ilẹ̀ Yorùbá kò pin sí ãrin ọkọ àti...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ẹ̀rù ló sọ ọmọ Ẹkùn di Ológbò/Ológìní tó fi di ”Ẹran-àmúsìn –Ọdẹ...

Ni igbà àtijọ́, ẹranko ti wọn pè ni Ẹkùn jẹ alágbára ẹranko, bẹni Kìnìún si jẹ́ alágbára ẹranko.  Bi Kìnìún ti lágbára tó ninú igbó, bi ó bá bú ramúramù, ohun gbogbo ninú igbó á...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Njẹ́ ó yẹ ki Adájọ́ ti ó bá hu iwà ibàjẹ́ kọjá Òfin?” – “Should...

Ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ mú àwọn Adájọ́ ti wọn fi ẹ̀sùn iwà ibàjẹ́ kàn – DSS arrest of alleged corrupt Judges. Courtesy: @theyorubablog Ni ọjọ́ Ẹti, ọjọ́ keje, oṣù kẹwa ọdún Ẹgbàálémẹ̀rindinlógún,...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ògòngò lọba ẹiyẹ” – “Ostrich is the King of Birds”

Ògòngò – Ostrich. Courtesy: @theyorubablog Ògòngò jẹ ẹiyẹ ti ó tóbi jù ninú gbogbo ẹiyẹ, ẹyin rẹ ló tún tóbi jù.  Ọrùn àti ẹsẹ̀ rẹ ti ó gún jẹ́ ki ó ga ju gbogbo ẹiyẹ yoku....

View Article


Ẹ̀YÀ ARA – ÈJÌKÁ DÉ ẸSẸ̀: PARTS OF THE BODY – SHOULDERS TO TOES

Download: Parts of the body in Yoruba – shoulders to toes You can also download the mp3 by right clicking here: Parts of the body in Yoruba – shoulders to toes (mp3) Ẹ̀YÀ ARA PARTS   OF THE BODY...

View Article

“Orúkọ idile Yorùbá ti ó ńparẹ́” – “Yoruba family names that are...

Orúkọ ẹni ni ìfihàn ẹni, orúkọ Yorùbá fi àṣà, iṣẹ́ àti Òriṣà idile hàn tàbi àtẹsẹ̀bi ọmọ.  Yorùbá gbàgbọ́ ninú Ọlọrun/Eledumare ki ẹ̀sin igbàgbọ́ àti imọ̀le tó dé.    Ifá jẹ́ ẹ̀sin...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ki Àgbàdo tó di Ẹ̀kọ, a lọ̀ ọ́ pa pọ̀: Ògì Ṣí ṣe” – “For Corn to become...

Ra Àgbàdo lọ́jà – Buy the Corn Àgbàdo ni wọn fi nṣe Ògì.  Ògì ni wọn fi nṣe Ẹ̀kọ́.  Ògì ṣí ṣe fẹ ìmọ́ tótó, nitori eyi, lai si omi, Ògì kò lè ṣe é ṣe.  Ọkà oriṣiriṣi ló wà ṣùgbọ́n,...

View Article

Ohun ti mo fẹ́ràn nipa Ìsimi Iparí Ọ̀sẹ̀ – What I love about the Weekend Break

Ni ọjọ́ Ẹti, ọjọ́ karun ti a ti bẹ̀rẹ̀ ilé-iwé ni ọ̀sẹ̀, inú mi ma ń dùn nitori ilé-iwé ti pari ni agogo kan ọ̀sán, ti ìsimi bẹ̀rẹ̀. Mo fẹ́ràn ìsimi ipari ọ̀sẹ̀ nitori mo ma nri àwọn òbí mi....

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ọ̀kan-lé-nigba lọkọ ọmọge, ikan ori rẹ ni ọkọ gidi: ìyànjú fún àwọn...

Ni ayé àtijọ́, òbi si òbi àti ẹbi si ẹbi ló nṣe ètò iyàwó fi fẹ́ fún ọmọ ọkùnrin ti ó bá ti bàláágà, ti wọn rò pé ó lè tọ́jú iyàwó.  Obinrin ki tètè bàláágà, nitori ki...

View Article
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live