Ìkini Ọdún Ẹgbàálélógún – 2020 Yoruba Season Greetings
Originally posted 2020-01-02 02:46:36. Republished by Blog Post Promoter
View ArticleỌwọ́ Ọmọdé Kòtó Pẹpẹ, Tagbalagba Ò Wọ Kèrègbè: The Child’s Hand Cannot...
Only a child’s hand can reach into this type of calabash. The image is from Wikipedia. Ọ̀rọ̀ Yorùbá sọ wípé “ọwọ́ ọmọde ko to pẹpẹ, tagbalagba ko wọ̀ kèrègbè”, èyí tí a lè túmọ̀ sí wípé,...
View ArticleSíse Àpọ̀n – Preparing Wild Mango Seed Soup
Ẹ fọ ẹja, edé àti irú, ẹ dàápọ̀ pẹ̀lú ẹran bibọ, ẹja gbígbẹ, iyọ̀, irú, iyọ̀ igbàlódé àti omi sinú ikòkò kan. Ẹ gbe ka iná fún sisè. Bi ẹ ti nse lọ, ẹ da epo-pupa sinú ikòkò keji....
View ArticleÌkíni ni Èdè Yorùbá – Greetings in Yoruba Language
Yorùbá ni kíkí fún gbogbo àsìkò ọjọ́, ìṣẹ̀lẹ̀ àti èto.̀ Fún àpẹrẹ: a lérò wípé àwọn ti a kọ si abala ojú ìwé yi, àti bi a ti le pe ìkíni kankan a wúlò fún yin. ENGLISH TRANSLATION As a sign of...
View ArticleÀjàpá rẹ Erin sílẹ̀ – “Ìjàlọ ò lè jà, ó lè bọ́ ṣòkòtò ni idi...
Erin jẹ ẹranko ti Ọlọrun da lọ́lá pẹlu titobi rẹ ninu igbo. Yorùbá ni “Koríko ti Erin bá ti tẹ̀, àtẹ̀gbé ni láyé”, oko ti Erin bá wọ̀, olóko bẹ wọ igbèsè tori ibajẹ ti o ma ṣẹlẹ̀ si irú...
View Article“A ki i jẹ Igún, a ki i fi Ìyẹ́ Igún rinti: Ẹnu Ayé Lẹbọ” –“It is...
Ohun ti o jẹ èèwọ̀ tàbi òfin ni ilú kan le ma jẹ èèwọ̀/òfin ni ilú miran ṣùgbọ́n bi èniyàn bá dé ilú, ó yẹ ki ó bọ̀wọ̀ fún àṣà àti òfin ilú. Bi èniyàn bá ṣe nkan èèwọ̀, ó...
View ArticleỌba titun, Ọọni Ifẹ̀ Kọkànlélaadọta gba Adé – The new Monarch, Ooni of Ife...
Ọọni Ifẹ̀ Kọkànlélaadọta gba Adé – Ooni of Ife Oba Enitan Ogunwusi after receiving the AARE Crown from the Olojudo of Ido land on Monday PHOTOS BY Dare Fasub Ilé-Ifẹ̀ tàbi Ifẹ̀ jẹ ilú àtijọ́ ti...
View Article“Ẹ jáwọ́ lápọ̀n ti kò yọ̀, ẹ lọ dá omi ilá kaná” – “Restrain from...
Ọbẹ̀ àpọ̀n jẹ́ ọbẹ̀ yíyọ̀ bi ọbẹ̀ ilá, ṣùgbọ́n fún ẹni ti kò bá mọ̃ se, kò ni yọ̀. Ọbẹ̀ ti enia lè yára sè ju ọbẹ̀ ilá ni, nitori bi a bá ni àpọ̀n kíkù nile, a din àkókò ti ó yẹ ki...
View Article“A ki mọ́ ọkọ ọmọ, ki a tún mọ àlè rẹ” –“One does not acknowledge one’s...
Igbéyàwó ibilẹ̀ – Traditional marriage Ni ayé àtijọ́, wọn ma ńfi obinrin fún ọkọ ni, ṣùgbọ́n ni ayé òde òni, obinrin á mú̀ àfẹ́sọ́nà lati fi hàn òbi, nitori Yorùbá gba ọmọ obinrin ni...
View Article“Gèlè ò dùn bi ká mọ̀ ọ́ wé, ká mọ̀ ọ́ wé, kò tó kó yẹni”: “Head tie is not...
Aṣọ Yorùbá, ìró àti bùbá kò pé lai si gèlè. Gèlè oriṣiriṣi ló wà̀, a lè lo gèlè aṣọ ìbílẹ̀ bi: aṣọ òfi/òkè, àdìrẹ, tàbi ki á yọ gèlè lára aṣọ. Ọpọlọpọ gèle ìgbàlódé wá lati òkè òkun. Ìmúra obinrin...
View ArticleObinrin kò ṣe e jánípò si ìdí Àdìrò nikan, Obinrin ló ni gbogbo Ilé –...
Ìtàn fi yé wa wi pé Yorùbá ka ọ̀rọ̀ obinrin si ni àṣà Yorùbá bi ó ti ẹ jẹ wi pé obinrin ki jẹ Ọba nitori ni àṣà ilú, ọkunrin ló njẹ olóri. Obinrin kò pọ̀ ni ipò agbára. Àwọn...
View Article“Bàbá Ìtàn Ìkọ̀lé-Èkìtì, Olóògbé Ọj̀ọ̀gbọ́n-Àgbáyé Adé Àjàyí...
http://www.theyorubablog.com/wp-content/uploads/2014/09/Baba-rele-Burial-of-an-elders-song.wav Babá re lé ò, Ilé ló lọ́ tarà-rà Bàbá re lé ò, Ilé ló lọ́ tarà-rà Ilé ò, ilé, Ilé ò,...
View Article“Ìfura loògùn àgbà, àgbà ti kò sọnú, á sọnù”: “Suspicion is the medicine of...
Ẹ̀kọ́ kíkọ́ ni ó lè fún àgbà ni ọgbọ́n àti òye lati lè sọnú. Oriṣiriṣi ọ̀nà ni a lè fi gbà kọ́ ẹ̀kọ́, ṣugbọn ni ayé òde òni, ohun gbogbo ni a lè ri kọ́ ni orí ayélujára. Bi ayélujára ti sọ ayé di...
View ArticleÀgbo – Ewé àti Egbòigi fún ìtọ́jú – Yoruba Herbal remedies/Traditional...
Ki oògùn Òyinbó tó gbòde, ewé àti egbòigi ti ó wà ni oko tàbi àyíká ilé ni Yorùbá fi nki àgbo lati dí àisàn lọ́wọ́ tàbi wo àisàn. Àwọn gbajúmọ̀ àti ọ̀dọ́ ayé òde òni ti...
View Article“Ọ̀kọ́lé, kò lè mu ràjò” – “Home-owner cannot travel with his/her house”
IIé ihò inú àpáta – Cave House Òrùlé wà lára ohun ini pàtàki ti ó yẹ ki èniyàn ni, ṣùgbọ́n èniyàn kò lè sun yàrá meji pọ̀ lẹ́ẹ̀kan. Ki ṣe bi èniyàn bá fi owó ara rẹ̀ kọ́ ilé...
View Article“Ọgbọ́n àrékérekè sọ ìràwé inú aginjù di ilé fún Àjàpá” – Pípé...
Ni ayé igbà kan, ọ̀gbẹlẹ̀ wa ni ilú àwọn ẹranko, nitori ọ̀dá òjò fún igbà pi pẹ́. Ọ̀gbẹlẹ̀ yi fa ìyàn, wọn kò ri omi mu tàbi wẹ̀. Eleyi mú ki gbogbo ẹranko (Kìnìún, Ẹkùn, Erin, Ẹfọ̀n,...
View ArticleỌdún Ẹgbã-lemẹ̃dogun wọlé, ọdún á yabo o – Year 2015 is here, may the...
Ọdún tuntun Ẹgbã-lemẹ̃dogun wọlé dé. Ilú Èkó fi tijó tayọ̀ gba ọdún tuntun wọlé, gbogbo àgbáyé naa fi tijó tayọ̀ gba ọdún wọlé. A gbàdúrà pé ki ọdún yi tura fún gbogbo wa o...
View ArticleKò si ọgbọ́n to lè dá, kò si ìwà ti o lè hù, ti o lè fi tẹ́ aiyé...
Oni – kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ – The Horseman & his son Ni aiyé àtijọ́, ẹsin àti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ló dàbi ọkọ̀ igbàlódé ti wọn ńpè ni mọ́tò. Ẹni ti ó jẹ́ ọlọ́rọ̀, ló lè ni ẹsin tàbi kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́....
View Article“Ojú ọ̀run tó ẹyẹ fò lai fi ara gbọ́n ra” – “The sky is wide enough for...
Ẹ̀sìn ti wa láyé, ki ẹ̀sìn Ìgbàgbọ́ àti Mùsùlùmi tó dé. Fún àpẹrẹ, Yorùbá gbàgbọ́ ninú “Ọlọrun” ti Yorùbá mọ̀ si “Òrìṣà-òkè” tàbi “Eledumare”. Bi Yorùbá ṣe ḿbá Ọlọrun...
View Article“Àpọ́nlé kò si fún Ọba ti kò ni Olorì” – “There is no respect for a King...
Ọ̀rọ̀ Yorùbá ni “Bi ọmọdé bá tó ni ọkọ́, à fún lọ́kọ́”. Ọkọ́ jẹ irinṣẹ́ pàtàki fún Àgbẹ̀. Iṣẹ́-àgbẹ̀ ni ó wọ́pọ̀ ni ayé àtijọ́. Nitori eyi, bi bàbá ti nkọ́ ọmọ rẹ ọkùnrin ni...
View Article