Jọ mi, Jọ mi, Òkúrorò/Ìkanra ló ndà – Insisting on people doing things...
Yorùbá ni “Bi Ọmọdé ba ṣubú á wo iwájú, bi àgbà ba ṣubú á wo ẹ̀hìn”. Bi enia bá dé ipò àgbà, pàtàki gẹ́gẹ́ bi òbí, àgbà ìdílé tàbi ọ̀gá ilé iṣẹ́, ẹni ti ó bá ni ìfẹ́ kò ni...
View ArticleTọ́jú Ìwà Rẹ Ọ̀rẹ́ Mi – Ọ̀rọ̀-orin lati Ìwé Olóògbé Olóyè J.F....
Ọ̀rọ̀-orin yi jẹ ikan ninú àwọn àkọ́-sórí ni ilé-ìwé alakọbẹrẹ ni ilẹ̀ Yorùbá ni igbà ti ile-iwe àpapọ̀ yè koro. Ṣùgbọ́n ni ayé òde òni, ti gbogbo ilé-ìwé ti kọ èdè abínibí silẹ̀,...
View ArticleGómìnà Èkó tẹ́lẹ̀, Bọ́lá Tinubu – ògúná gbòngbò Ẹgbẹ́ Àjọ...
Ki ìjọba alágbádá ìgbàlódé tó dé, Yorùbá ni bi wọ́n ṣe nṣe ètò ìlú. Ètò ìlú ayé ìgbà àtijọ́ kò bẹ̀rẹ̀ tàbi pin si ọ̀dọ̀ Ọba àti Ìjòyè ìlú nìkan. Ètò ìlú bẹ̀rẹ̀ lati...
View ArticleKi gbogbo ọmọ ẹgbẹ́ yan ẹni ti yio du ipò fún ẹgbẹ́ kò yẹ kó fa ìjà...
Nínú gbogbo ẹgbẹ́ òṣèlú orílẹ̀ èdè Nigeria, àwọn alágbára díẹ̀ nínú ẹgbẹ́ ni ó ńyan ẹni ti wọ́n fẹ́ ki o fi iga gbága fún ipò pẹ̀lú àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú yoku. Ó ti di àṣà ki...
View ArticleOlùkọ̀wé Èdè àti Àṣà Yorùbá lóri ayélujára, ki gbogbo ọmọ orílẹ̀...
Àsíá orílẹ̀ èdè Nigeria – Nigerian Flag. Fún ọdún mọ́kàndín-lọgọrun lati ìgbà ti Òyìnbó Ìlú-Ọba ti fi ipá gba Èkó titi di ọjọ́ kini oṣù kẹwa, odun Ẹgbẹ̀sánlé-ọkanlelọgọta ti orílẹ̀...
View Article“Ìwà bi Ọlọrun pẹ̀lú Ìtẹ́lọ́rùn, Èrè nla ni” – “Godliness with...
Ìtẹ́lọ́rùn – Contentment. Courtesy: @theyorubablog Bi kò bá si ìtẹ́lọ́rùn, kò si ohun ti èniyàn ni ti ó tó. À i ni ìtẹ́lọ́rùn ló nfa iwà burúkú bi, olè̀ jijà, àgbèrè,...
View ArticleÒrìṣà òkè jẹ́ ki npé meji obinrin kò dé inú – Àṣà Ìkó-binrin-jọ:...
Ọkùnrin kan pẹ̀lú iyàwó púpọ̀ wọ́pọ̀ ni ilẹ̀ Yorùbá. Àwọn obinrin ti ó bá́ fẹ́ ọkọ kan naa ni à ńpè ni “Orogún”. Ìwà oriṣiriṣi ni ó ma ńhàn ni ilé olórogún, àrù̀n iyàwó ti...
View ArticleBÍBẸ ÈKÓ WÒ FÚN Ọ̀SẸ̀ KAN: A One Week Visit to a Yoruba Speaking City...
These series of posts will center around learning the Yoruba words, phrases and sentences you might come across if you visited a Yoruba speaking city or state (here Lagos). A sample conversation is...
View ArticleÌránti Aadọta Ọdún ti Ọ̀gágun Adékúnlé Fájuyi fi ara rẹ ji fún...
Yorùbá fẹ́ràn àlejò púpọ̀. Ìwà ti ọmọ ilú lè hù ti yio fa ibinú, bi àlejò bá hu irú ìwà bẹ́ ẹ̀, wọn yio ni àlejò ni, ki wọn fori ji i. Òwe Yorùbá ti ó sọ wi pé “Ojú àlejò...
View ArticleẸ Jọ̀wọ́ Darapọ̀ Mọ́ Wa lati kọ nipa Àṣà àti Ìtàn Àdáyébá ni...
Gbogbo olólùfẹ́ èdè àti àṣà Yorùbá ti ó tẹ̀lé wa ni àwọn ọdún ti ó kọjá, a ki yin fún ọdún tuntun ti ó wọlé. Èdùmàrè á jẹ́ ki ọdún na a tura o. Inú wa yio dùn ti ẹ bá lè...
View Article“Ìpolongo tó nlọ lọ́wọ́ ni orilẹ́ èdè Nigeria ni pe“Àyípadà bẹ̀rẹ̀...
Ohun ti wọ́n bá fi ogún ọdún tàbi ju bẹ́ ẹ̀ lọ kọ́, ṣe é bàjẹ́ ni iṣéjú akàn, ṣùgbọ́n lati ṣe àtúnṣe lè gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún bakan na a. Ó ṣe pataki ki gbogbo ọmọ ilú pinu ni ikan kan...
View Article“Orí ọti ọlọ́tí ni eṣinṣin nkúlé” – “Fly often dies on top of other people’s...
Ìsọ̀ Ẹmu – Local Palm wine bar @theyorubablog. “Ọ̀mùtí gbàgbé ìṣẹ́” fún ìgbaì diẹ ni, nítorí bí ọ̀mùtí bá jí tán, ìṣẹ́ rẹ kò tán. Gbogbo àlàyé àti ìpolongo wípé ọtí àmun jù nfa oriṣiriṣi àìsàn burúkú...
View Article“Obinrin ki ṣe Ẹrú tabi Ẹrù ti wọn njẹ mọ́ Ogún – Àsikò tó lati Dáwọ́...
Yorùba Dáwọ́ Àṣà ṣì Ṣúpó Dúró – Yoruba Stop Bequeathing Widows. Courtesy: @theyorubablog Ni ayé àtijọ́, àṣà ṣì ṣúpó wọ́pọ̀ ni Ilẹ̀ Yorùbá. Obinrin ti ọkọ rẹ̀ bá kú wọn yio fi jogún...
View Article“Fi ọ̀ràn sínú pète ẹ̀rín; fi ebi sínú sunkún ayo” – “Keep your troubles...
Bi a bá wo iṣe àti àṣà Yorùbá, a o ri pe àwọn “Àlejò lati Òkè-Òkun” ti o ni “Inú Yorùbá ló dùn jù ni àgbáyé” kò jẹ̀bi. Kò si ibi ti enia lè dé ni olú-ilú àti...
View Article“A ki mọ́ ọkọ ọmọ, ki a tún mọ àlè rẹ” –“One does not acknowledge one’s...
Igbéyàwó ibilẹ̀ – Traditional marriage Ni ayé àtijọ́, wọn ma ńfi obinrin fún ọkọ ni, ṣùgbọ́n ni ayé òde òni, obinrin á mú̀ àfẹ́sọ́nà lati fi hàn òbi, nitori Yorùbá gba ọmọ obinrin ni...
View ArticleIṣẹ́ ni oògùn ìṣẹ́ – Hard-work is a cure for povertyOriginally Posted on...
Ẹ ṣe àyẹ̀wò ìwé akéwì-orin ni èdè Yorùbá ti àwọn ọmọ ilé-ìwé n kọ́ sórí ni ilé-ìwé ilẹ̀ Yorùbá ni ayé àtijọ: Iṣẹ́ ni oògùn ìṣẹ́, múra si iṣẹ́ rẹ ọ̀rẹ́ mi, iṣẹ́ ni a fi i di ẹni...
View Article“Ojú ọ̀run tó ẹyẹ fò lai fi ara gbọ́n ra” – “The sky is wide enough for...
Ẹ̀sìn ti wa láyé, ki ẹ̀sìn Ìgbàgbọ́ àti Mùsùlùmi tó dé. Fún àpẹrẹ, Yorùbá gbàgbọ́ ninú “Ọlọrun” ti Yorùbá mọ̀ si “Òrìṣà-òkè” tàbi “Eledumare”. Bi Yorùbá ṣe ḿbá Ọlọrun...
View ArticleÌpanu – “Kẹ́nu ma dilẹ̀ ni ti gúgúrú, gúgúrú ki ṣe oúnjẹ àjẹsùn”:...
Oúnjẹ òkèlè ni Yorùbá mọ̀ si oúnjẹ gidi. Ni ọ̀pọ̀ igbà oúnjẹ òkèlè ni oúnjẹ àjẹsùn, ṣùgbọ́n ìpanu ni ohun amú inú dúró ni ọ̀sán. Àwọn ìpanu bi gúgúrú àti ẹ̀pà, bọ̃li àti...
View Article“BÍ A TI NṢE NI ILÉ WA…”: MICHELLE OBAMA’S DRESSING AT OSCAR 2013Originally...
Image is from MSNBC (http://tv.msnbc.com/2013/02/25/a-cover-up-by-the-iranian-press-michelle-obama-has-no-right-to-bare-arms/) They covered the story on the Iranian Press Agency that found Michelle...
View ArticleÌHÀ TI AWỌN ÒBÍ NI ILẸ̀ KAARỌ OOJIRE KỌ SI ÈDÈ YORÙBÁ: THE ATTITUDE...
A sọ wipe ọmọ kò gbọ́ èdè, tani kó kọ̃? Àwa òbí nii ṣe púpọ ni bi àwọn ọmọ wa ṣe mú èdè abi-nibi wọn. Àwa òbí lati yi ìhà ti a kọ si èdè Yorùbá padá, ti a kò bá fẹ́ ki o pòórá....
View Article