Quantcast
Channel: The Yoruba Blog
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live

Oríkì Àjọbí, Àṣà Yorùbá ti ó nparẹ́ lọ – Family Lineage Odes, a Dying...

Oríkì* jẹ ọ̀rọ̀ ìwúrí ti Yorùbá ma nlò lati fi sọ ìtàn àṣà àti ìṣe ìdílé lati ìran dé ìran.  Ninú oríkì ni a ti lè mọ ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ ẹbí ẹni àti ohun ti a mọ ìdílé mọ́, bí i irú iṣẹ ti...

View Article


Àpẹrẹ Ìsìnkú Ìbílẹ̀ fún Arúgbó ni Ilẹ́ Yorùbá – Example of Yoruba...

Ìnáwó rẹpẹtẹ ni ìsìnkú arúgbó jẹ́ ni ilé Yorùbá.  Bi arúgbó bá kú ni ilé Yorùbá ki ṣe òkú ọ̀fọ̀ ṣùgbọ́n òkú ijọ àti ji jẹ, mi mu ni pàtàki bi irú arúgbó bá bi àwọn ọmọ ti...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ìpínlẹ̀ Èkó ṣe Àjọyọ̀ Ìdásílẹ̀ Àádọ́ta Ọdún: Creation of State –...

Afárá tuntun lati Lẹkki si Ìkòyí – New Lekki-Ikoyi Bridge Ìjọba-àpapọ̀ sọ Èkó di ìpínlẹ̀ ni àádọ́ta ọdún sẹhin.  Èkó jẹ́ olú ilú fún gbogbo orilẹ̀ èdè Nigeria tẹ́lẹ̀ ki wọn tó gbe lọ...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Adébáyọ̀ Fálétí, ògúná gbòngbò ti ó gbé èdè àti àṣà Yorùbá...

Àwọn iwé ìròyìn gbe jade wi pé Adébáyọ̀ Fálétí, ògúná gbòngbò ninú àwọn ti ó gbé èdè àti àṣà Yorùbá lárugẹ ni àgbáyé, re ibi àgbà nrè ni ọjọ́ ìsimi ọjọ́ kẹtàlélógún,...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ìròyìn kàn pé Ọ̀túnba Gani Adams ni Aàrẹ Ọ̀na Kakanfo Yorùbá...

Ọba Lamidi Adéyẹmi àti Ọ̀túnba Gani Adams – Aláafin Lamidi Adeyemi & Chief Gani Adams Lẹhin ọdún kọkàndinlógún ikú Olóògbé Olóyè M.K.O Abíọ́lá, Aàrẹ Ọ̀na Kakanfo Yorùbá kẹ̀rinlá,...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Gbẹ̀dẹ̀ bi Ogún Ìyá, Ogún Bàbá ló ni ni lára – Maternal Inheritance...

Ogún jẹ́ gbogbo ohun ìní ti bàbá tàbi ìyá bá fi silẹ́ ti wọn bá kú.  Ni ìgbà àtijọ́, kò wọ́pọ̀ ki olóògbé ṣe ìwé-ìhágún, bi wọn ṣe má a pín ohun ini wọn lẹhin ikú.  Ọ̀pọ̀lọpọ̀...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

A ki sọ pé ki wèrè ṣe òkú ìyá rẹ̀ bi ó bá ṣe ri, bi ó bá ni òhun...

Oriṣiriṣi wèrè ló wà, nitori pé ki ṣe wèrè ti ó wọ àkísà ni ìgboro tàbi já sita nikan ni wèrè.  Ẹnikẹni ti o nhu ìwà burúkú tàbi ṣe ìpinnu burúkú ni Yorùbá npè ni “wèrè”....

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ikú kò mọ àgbà, ó mú ọmọdé bi Jidé Tinubu – Death is no respecter of...

Òwe Yorùbá sọ wi pé “bi iná bá kú, á fi eérú bojú, bi ọ̀gẹ̀dẹ̀ bá kú, á fi ọmọ ẹ rọ́pò”.  Òwe yi fi hàn ipò ti Yorùbá fi ọmọ si.  Kò si ẹni ti kò ni kú, ṣùgbọ́n ọ̀fọ̀ nlá ni...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

A kú Ìdùnnú Ìdúpẹ́ – Happy Thanksgiving

Bi Ọlọrun ti ńdárí ẹ̀ṣẹ̀ ji èniyàn Bi Olóri Òṣèlú Àmẹ́rikà ti ńdáríji tòlótòló Bẹni ki èniyàn dári ji ẹni ti ó bá ṣẹ́, nitori ki a lè fi ìdùnnú dúpẹ́. Olóri Òṣèlú...

View Article


Ìtán ti a fẹ́ kà loni dá lóri Bàbá tó kó gbogbo Ẹrù fún Ẹrú – The...

View Article

A kú ọdún tuntun – Happy New Year

http://www.theyorubablog.com/wp-content/uploads/2018/01/Ẹ-káabọ̀-si-ọdún-Ẹgbàáléméjìdínlógún-2018.mp4

View Article

Ìtàn ti a o kà loni dá lórí ìdí ti ọmọ Ẹkùn fi di Ológbò – The Yoruba...

Yorùbá ma npa ìtàn lati fi ṣe à ri kọ́gbọ́n tàbi fún ìkìlọ̀.  Ẹ ṣọ́ra lati fi ìbẹ̀rù àti ojo bẹ̀rẹ̀ ọdún nitori a ma a géni kúrú. Lára ẹ̀kọ́ ti a lè ri fi kọ́ ọgbọ́n ni ìtàn ti a ka yi...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

A ò lè tori a mà jẹran dọ̀bálẹ̀ fún Mãlu – Àgbẹ́kọ̀yà kọ Àṣejù...

Ìròyìn tó gbòde, ni ọ̀rọ̀ Ìjọba-àpapọ̀ ti ó fẹ ki gbogbo ìpínlẹ̀ ni Nigeria pèsè àyè ni ọ̀fẹ́ fún àwọn darandaran lati tẹ̀dó dípò ki wọn ma kó Mãlu kiri. Ni ipinlẹ si ìpínlẹ̀,...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Gó́mìnà Ìpínlẹ̀ Èkó, Akínwùnmí Àmbọ̀dé ju ọwọ́ lu òfin fún ìpamọ́...

Ọ̀túnba Gàní Adams ṣe ìwúyè – Chief Gani Adams’ installation as the Aare Ona Kakanfo Aàrẹ Ọ̀nà Kakanfo, Ọ̀túnba Gàní Adams ti wọn ṣe ìwúyè fún ni ọjọ́ Àbámẹ́ta, oṣù kini, ọjọ́ kẹtàlá...

View Article

ÀWÒRÁN ÀTI PÍPÈ ORÚKỌ ẸRANKO, APA KEJI – Names of Wild/Domestic...

View Article


Ẹ̀kọ́ àti Ọgbọ́n ni Ọ̀rọ̀ Àgbà lati Ẹnu Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọmọlolú Olunlọyọ lórí...

Bi a ba fi eti si ọ̀rọ̀ ti àgbà Yorùbá Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọmọlolú Olunlọyọ  ni ori ẹ̀rọ “Amóhùnmáwòrán Òpómúléró”, ni ori ayélujára, a o ṣe àkíyèsí àwọn nkan wọnyi:...

View Article

Bi Irọ́ bá lọ fún Ogún Ọdún, Òtítọ á ba Lọ́jọ́ Kan – Ìbò Ọjọ́ Kejilá...

Lẹhin ọdún mẹẹdọgbọn ti Ijoba Ologun Ibrahim Babangida fagilé ìbò ti gbogbo ilú dì lai si ìjà tàbi asọ̀ tó gbé Olóògbé Olóyè Moshood Káṣìmáawòó Ọláwálé Abíọ́lá wọlé, Ìjọba...

View Article


Àròkọ ni Èdè Yorùbá – Essay in Yoruba Language

Idi ti a fi bẹ̀rẹ̀ si kọ iwé ni èdè Yorùbá lóri ayélujára ni lati jẹ́ ki ẹnikẹ́ni ti ó fẹ́ mọ̀ nipa èdè àti àṣà Yorùbá ri ìrànlọ́wọ́ lóri ayélujára. A ò bẹ̀rẹ̀ si kọ àwọn àròkọ ni...

View Article

Bi mo ṣe lo Ìsimi Àjíǹde tó kọjá – How I spent the last Easter Holiday

Ìsimi ọdún Àjíǹde tó kọjá dùn púpọ̀ nitori mo lọ lo ìsimi náà pẹ̀lú ẹ̀gbọ́n Bàbá mi àti ẹbí rẹ ni ilú Èkó. Èkó jinà si ilú mi nitori a pẹ́ púpọ̀ ninú ọkọ̀ elérò ti àwọn òbí...

View Article

Ohun ti mo fẹ́ràn nipa Ìsimi Iparí Ọ̀sẹ̀ – What I love about the Weekend Break

Ni ọjọ́ Ẹti, ọjọ́ karun ti a ti bẹ̀rẹ̀ ilé-iwé ni ọ̀sẹ̀, inú mi ma ń dùn nitori ilé-iwé ti pari ni agogo kan ọ̀sán, ti ìsimi bẹ̀rẹ̀. Mo fẹ́ràn ìsimi ipari ọ̀sẹ̀ nitori mo ma nri àwọn òbí mi....

View Article
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live