Ìtẹ́lọ́rùn ni Baba Ìwà – Contentment is the Father of CharacterOriginally...
Àìní ìtẹ́lọ́rùn ló bí gbogbo ìwà burúkú bi: irọ́ pípa, olè jíjà, àgbèrè, ojúkòkòrò àti bẹ̃bẹ lọ. Àìní ìtẹ́lọ́rùn ló wà ni ìdí àwọn Oṣèlú àti Olórí Ìjọ ti o nlo owó ìlú tàbi owó ìjọ fún ara wọn dipò ki...
View Article“Bi o kò bá lágbára ohun ti o fẹ́, ni ìfẹ́ ohun ti o ni”: “If you cannot...
Ẹ kú ipalẹ̀mọ́ ọdún o. Bi ọdún bá sún mọ́ etílé, oúnjẹ àti ohun èlò gbogbo maa nwọn nitori àwọn ọlọ́jà yio ti fi owó kún ọjà nitori èrò ti ó fẹ́ ra ọjà maa n pọ̀ si ni àsikò yi....
View Article“Ẹni bá wá iwa-kuwa, ojú rẹ á ri irikuri” – Ìtàn bi imú Erin ti di...
Ni igbà kan ri, imú Erin dàbi ti àwọn ẹranko tó kù ni, ṣùgbọ́n Erin fi aigbọ tara ẹni, di o ni imú gigùn. Gbogbo nkan tó nlọ ni ayé àwọn ẹranko yoku ni Erin fẹ tọpinpin rẹ. Yorùbá ni...
View ArticleÀwòrán àti pípè orúkọ Èlò Ọbẹ̀ Yorùbá – Pictures and pronunciation...
Àwọn èlò ọbẹ̀ Yorùbá, ẹni ti ó bá mọ ọbẹ̀ se, yio mọ èlò ọbẹ̀ ti ohun yio ra àti bi yio ti se, ṣùgbọ́n ẹni ti kò mọ ọbẹ̀ se, lè lo owó ai mọye lati se ọbẹ̀, ki ọbẹ̀ rẹ má dùn. Fún...
View Article“Iwájú lèrò mbá èrò – Kò si ohun téni kan ṣe, téni kò ṣe ri” –...
Ọ̀rọ̀ ijinlẹ àti Òwe Yorùbá wà lati fi kọ́ ọgbọ́n àti imò bi èniyàn ti lè gbé igbésí ayé rere. Ọ̀gá àgbà ninú Olórin ilẹ̀ aláwọ̀-dúdú (Olóyè, Olùdarí Ebenezer Obey) kọ ninú...
View ArticleÌpínlẹ̀ Èkó ṣe Àjọyọ̀ Ìdásílẹ̀ Àádọ́ta Ọdún: Creation of State –...
Afárá tuntun lati Lẹkki si Ìkòyí – New Lekki-Ikoyi Bridge Ìjọba-àpapọ̀ sọ Èkó di ìpínlẹ̀ ni àádọ́ta ọdún sẹhin. Èkó jẹ́ olú ilú fún gbogbo orilẹ̀ èdè Nigeria tẹ́lẹ̀ ki wọn tó gbe lọ...
View ArticleẸni gbé epo lájà, kò jalè̀ tó ẹni gba a – Olóri Òṣèlú Ilú Ọba, Na...
David Cameron’s ‘corrupt’ countries remarks to Queen branded ‘unfair’ By PRESS ASSOCIATION David Cameron called Nigeria ‘fantastically corrupt’ before the Queen Ìròyìn ti o jade ni ọjọ́ Ìṣẹ́gun,...
View Article“Orí ọti ọlọ́tí ni eṣinṣin nkúlé” – “Fly often dies on top of other people’s...
Ìsọ̀ Ẹmu – Local Palm wine bar @theyorubablog. “Ọ̀mùtí gbàgbé ìṣẹ́” fún ìgbaì diẹ ni, nítorí bí ọ̀mùtí bá jí tán, ìṣẹ́ rẹ kò tán. Gbogbo àlàyé àti ìpolongo wípé ọtí àmun jù nfa oriṣiriṣi àìsàn burúkú...
View ArticleAyẹyẹ Aadọrun ọjọ́ ibi Alhaji Lateef Káyọ̀dé Jakande, Gómìnà Alágbádá...
Èkó jẹ́ Olú-Ilú Nigeria fún ọdún mẹ́tàdinlọ́gọrin, ṣùgbọ́n idikọ fún òwò àti ọrọ̀ ajé lati ẹgbẹgbẹ̀run ọdún sẹhin titi di ọjọ́ oni. “Ta ló lè mọ ori ọlọ́là lágbo?” Gbogbo àgbáyé...
View ArticleBi Egúngún/Eégún bá ńlé ni ki a má rọ́jú, bi ó ṣe ńrẹ ará ayé,...
Yorùbá ma ńṣe ọdún Egúngún/Eégún ni ọdọ-dún lati ṣe iranti Bàbánlá/Ìyánlá wọn ti ó ti di olóògbé nitori wọn ni iṣẹ́ lati ṣe laarin alàyè lati rán ará ilú leti pé ki wọn di...
View ArticleÌtàn àròsọ bi obinrin ti sọ Àmọ̀tékùn di alábàwọ́n: The Folklore on...
Ni igba kan ri, Àmọ̀tékùn ni àwọ̀ dúdú ti ó jọ̀lọ̀, ṣùgbọ́n ni ọjọ́ kan, Àmọ̀tékùn wá oúnjẹ õjọ́ rẹ lọ. Ó dé ahéré kan, ó ṣe akiyesi pe obinrin kan ńwẹ̀, inú rẹ dùn púpọ̀ pé...
View Article“Bi a bá tori ẹni burúkú fọ́jú, a kò ni ri ojú ri ẹni rere” – “If one...
Kò si ilú, ẹ̀yà tàbi àwọ̀ ti kò ni ẹni burúkú tàbi ẹni rere. Àti ẹni burúkú àti ẹni rere ló wà ninú ẹbi, ilú, àti gbogbo ẹ̀yà àgbáyé ninú èniyàn dúdú àti funfun, ọkùnrin,...
View ArticleÀjàpá àti Ọmọdé Mẹta – “Ẹnu àìmẹ́nu, ètè àìmétè, ló́ nmú ọ̀ràn bá ẹ̀rẹ̀kẹ́” –...
Ni abúlé Yorùbá nigbati ko ti si ẹ̀rọ asọ̀rọ̀-mágbèsì tabi ẹ̀rọ amú-òhùn-máwòrán àti ẹ̀rọ ayélujára, àwọn ọmọdé má nkó ara jọ lati ṣe eré lẹhin iṣẹ́ oojọ Bàbá àti Ìyá wọn. Pataki, ni igba ọ̀gbẹlẹ̀...
View Article“Tori wèrè ìta la ṣe n ni wèrè inú ile”: Idibò lati yan Olóri Òṣèlú...
Ẹ̀rù ba onilé àti àlejò fún Nigeria nitori idibò à ti yan Olóri Òṣèlú à̀ti àwọn Òṣèlú yoku, ṣùgbọ́n a dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọrun pe ọjọ́ na ti wá, ó ti lọ, ilú ti yan Olóri Òṣèlú...
View Article‘Gómìnà Ìpínlẹ̀ Yorùbá, ẹ pèsè omi mi mun fún ará ilú ki wọ́n yé...
Ìjọba Ológun àkọ́kọ́ ni abẹ́ Olóògbé Ọ̀gágun Aguiyi Ironsi, da gbogbo ipinlẹ̀ pọ si abẹ́ Ìjọba àpapọ̀. Ki wọ́n tó dá àwọn ipinlẹ̀ pọ̀, àwọn ipinlẹ̀ ndàgbà sókè gẹ́gẹ́ bi ohun ti ó ṣe...
View ArticleBί a bá ránni ni iṣẹ ẹrú: One sent on a slavish errand (on man’s inhumanity...
The Mido Macia Story courtesy of NEWSY reporting from multiple sources and giving a broader view Yorὺbá nί “Bί a bá ránni nί iṣẹ ẹrú, a fi tọmọ jẹ”. Ọlọpa tί o yẹ ki o dãbo bo ará àti ẹrú nί ìlú,...
View Article“A ki i fi ọjọ́ kan bọ́ ọmọ tó rù”: Ìmọ̀ràn fún Òṣèlú tuntun àti...
Ọmọ ki dédé rù lai ni idi. Lára àwọn idi ti ọmọ lè fi rù ni: àìsàn, ebi, òùngbẹ, ìṣẹ́, ai ni alabojuto, òbí olójú kòkòrò, ai ni òbí àti bẹ ẹ bẹ lọ. Orilẹ̀ èdè Nigeria ti jẹ gbogbo...
View Article“ỌMỌ ÌYÁ́ MEJI KI RÉWÈLÈ”: 2 Siblings of the Same Mother Should not Die in...
Omo iya meeji okin ka abamo: Chechen legal permanent resident brothers terrorist suspects in Boston marathon bombing. Image is from the WHDH stream. “Ọmọ ìyá meji ki réwèlè, Yorùbá ma nlo ọ̀rọ̀ yi...
View Article“Ìwà bi Ọlọrun pẹ̀lú Ìtẹ́lọ́rùn, Èrè nla ni” – “Godliness with...
Ìtẹ́lọ́rùn – Contentment. Courtesy: @theyorubablog Bi kò bá si ìtẹ́lọ́rùn, kò si ohun ti èniyàn ni ti ó tó. À i ni ìtẹ́lọ́rùn ló nfa iwà burúkú bi, olè̀ jijà, àgbèrè,...
View ArticleKò si ọgbọ́n to lè dá, kò si ìwà ti o lè hù, ti o lè fi tẹ́ aiyé...
Oni – kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ – The Horseman & his son Ni aiyé àtijọ́, ẹsin àti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ló dàbi ọkọ̀ igbàlódé ti wọn ńpè ni mọ́tò. Ẹni ti ó jẹ́ ọlọ́rọ̀, ló lè ni ẹsin tàbi kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́....
View Article