Iwé-àkọ-ránṣẹ́ ni èdè Yorùbá – Letter writing in Yoruba...
Ni àtijọ́, àwọn ọmọ ilé-iwé ló ńran àgbàlagbà ti kò lọ ilé-iwé lọ́wọ́ lati kọ iwé, pataki ni èdè abínibí. Ẹ ṣe àyẹ̀wò àwọn iwé-àkọ-ránṣẹ́ wọnyi ni ojú iwé yi: Ìwé ti Ìyá kọ...
View Article“Orúkọ ẹni ló njẹri ẹni lókèèrè: Yorùbá tó wà ni òkè-òkun...
Yorùbá ki dá gbé, nitori eyi, ẹbi àti ará á pa pọ̀ lati sọ ọmọ lórúkọ. Ni ọjọ́ ìsọmọ-lórúkọ, ki ṣe iyá àti bàbá ọmọ nikan ni ó nmú orúkọ silẹ̀, iyá àti bàbá àgbà àti ẹ̀gbọ́n...
View ArticleÀjàpá rẹ Erin sílẹ̀ – “Ìjàlọ ò lè jà, ó lè bọ́ ṣòkòtò ni idi...
Erin jẹ ẹranko ti Ọlọrun da lọ́lá pẹlu titobi rẹ ninu igbo. Yorùbá ni “Koríko ti Erin bá ti tẹ̀, àtẹ̀gbé ni láyé”, oko ti Erin bá wọ̀, olóko bẹ wọ igbèsè tori ibajẹ ti o ma ṣẹlẹ̀ si irú...
View ArticleOriṣiriṣi Gèlè – Various types of Head TiesOriginally Posted on July 7,...
Aṣọ Yorùbá kò pé, lai si Gèlè. Bi Yorùbá bá wọ aṣọ ìbílẹ̀ fún òde ojoojúmọ́ tàbi fún ayẹyẹ, wọn ni lati wé gèlè ki imúra lè pé. Fún ji jade ojoojúmọ́, a lè lo ipèlé aṣọ...
View Article“Ilé làńwò ki a tó sọmọ lórúkọ – Orúkọ Yorùbá” – Home is examined...
Ni àṣà Yorùbá, ni ayé àtijọ́, ọjọ́ keje ni wọn ńsọmọ obinrin ni orúkọ, ọjọ́ kẹsan ni ti ọmọ ọkùnrin, ṣùgbọ́n ni ayé òde òni, ọjọ kẹjọ ni wọn sọ gbogbo ọmọ lórú̀kọ. Yorùbá ki sọmọ...
View Article“Ará Ilú Nigeria: “Fi Ẹ̀tẹ̀ silẹ̀ pa Làpálàpá” – Nigerians are:...
Ẹ̀tẹ̀ tó mbá ilú jà ni ‘iwà-ibàjẹ́’. Ìyà ti ará ilú njẹ lọ́wọ́lọ́wọ́, ki i ṣe èrè iwà-ibàjẹ́ ọdún kan, ṣùgbọ́n ti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún. Kò si ìfẹ́ ilú, nitori eyi, àwọn oniwà ibàjẹ́...
View ArticleEwédú: Botanical Name Cochorus, Craincrain in Sierra LeoneOriginally Posted...
Ewédú jẹ ikan nínú ọbẹ̀ Yorùbá tó wọpọ ni agbègbè Ọ̀yó, Ọ̀sun, Ògùn gẹ́gẹ́bi ilá ti wọ́pọ̀ ni agbègbè Ondo àti Èkìti. Fún ẹni tó́ nkanju, ilá yára láti sè ju ewédú lọ, nítorí...
View ArticleÀròkàn ló n fa ẹkún à sun à i dákẹ́: Anguish of mind is the root...
Ohun ti Yorùbá mọ̀ si àròkàn n irònú igbà gbogbo. Kò si ẹni ti ki ronú, ṣùgbọ́n àròkàn léwu. Inú rirò yàtọ si àròkàn. Inu rirò ni àwọn Onimọ-ijinlẹ̀ lò lati ṣe ọkọ̀ òfúrufú...
View Article“Ìkà gbàgbé Àjọbi, adánilóró̀ gbàgbé ọ̀la, ẹ̀san á ké lóri...
Yorùbá ni ètò àti òfin ti àwọn Àgbà, Ọba àti Ìjòyè fi nto ilú ki aláwọ̀-funfun tó dé. Onirúurú ọ̀nà ni wọn ma fi nṣe idájọ́ ìkà laarin àwùjọ. Wọn lè fi orin tú àṣiri...
View ArticleẸ̀kọ́ àti Ọgbọ́n ni Ọ̀rọ̀ Àgbà lati Ẹnu Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọmọlolú Olunlọyọ lórí...
Bi a ba fi eti si ọ̀rọ̀ ti àgbà Yorùbá Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọmọlolú Olunlọyọ ni ori ẹ̀rọ “Amóhùnmáwòrán Òpómúléró”, ni ori ayélujára, a o ṣe àkíyèsí àwọn nkan wọnyi:...
View ArticleOHUN TÍ́ A LÈRÍ NÍNÚ ÀTI ÀYÍKÁ ILÉ – BASIC YORUBA HOUSEHOLD ITEMSOriginally...
YORÙBÁ ENGLISH YORÙBÁ ENGLISH Àwo pẹrẹsẹ Plates Ṣíbí Spoon Abọ́ Dish Ọ̀bẹ Knife Ago Cup Ìgò Omi Water Bottle Aago Clock Ìkòkò Omi Water Pot Aṣọ Clothes Omi Water Oúnjẹ Food Ibi Ìdáná Kitchen...
View ArticleÌtàn Yorùbá bi Àdán ti di “Ko ṣeku, kò ṣẹyẹ” – Yoruba Folklore on how the Bat...
Àdán fò lọ bá ẹyẹ – Bat flew to join the birds @theyorubablog Ìtàn sọ wí pé eku ni àdán tẹ́lẹ̀ ki ìjà nla tó bẹ́ sílẹ̀ laarin eku àti ẹyẹ. Àdán rò wípé àwọn ẹyẹ fẹ́ bori, nitorina o fo lati lọ darapọ̀...
View ArticleYí Yára bi Ojú-ọjọ́ ti nyí padà nitori Èérí Àyíká – Effect of...
Ẹlẹkọ-ìjìnlẹ̀ ṣe àkiyesi pe enia ndá kún yí yára bi ojú-ọjọ́ ti nyi padà nitori èérí-àyíká. Ojú-ọjọ́ ti nyí padà lati ìgbà ti aláyé ti dá ayé, ṣùgbọ́n àyípadà ojú-ọjọ́ ni ayé...
View Article“Ọdún nlọ si òpin”: Ẹ ṣọ́ra fún oníjìbìtì/ẹlẹ́tàn – “End of year is fast...
Ìparí ọdún sún mọ́lé, àsikò yi ni àwọn oníjìbìtì/ẹlẹ́tàn ma nbọ́ sita lati ṣe iṣẹ́ ibi, nipa ji ja àwọn ará ilú ti kò bá funra ni olè. Àṣà Yorùbá ni ayé àtijọ́ ni lati gbé àwọn...
View Article“BÍ A TI NṢE NI ILÉ WA…”: MICHELLE OBAMA’S DRESSING AT OSCAR 2013Originally...
Image is from MSNBC (http://tv.msnbc.com/2013/02/25/a-cover-up-by-the-iranian-press-michelle-obama-has-no-right-to-bare-arms/) They covered the story on the Iranian Press Agency that found Michelle...
View ArticleÌkíni ni Èdè Yorùbá – Greetings in Yoruba LanguageOriginally Posted on July...
Yorùbá ni kíkí fún gbogbo àsìkò ọjọ́, ìṣẹ̀lẹ̀ àti èto.̀ Fún àpẹrẹ: a lérò wípé àwọn ti a kọ si abala ojú ìwé yi, àti bi a ti le pe ìkíni kankan a wúlò fún yin. ENGLISH TRANSLATION As a sign of...
View Article“A kì í fi Oníjà sílẹ̀ ká gbájúmọ́ alápepe – Pí pa Àjòjì ni Gúsù...
Pí pa Àjòjì ni Gúsù ilẹ̀ Aláwọ̀-dúdú – South Africa’s xenophobic attacks Òwe Yorùbá kan sọ pé “Amúkun, ẹrù ẹ́ wọ́, ó ni ẹ̃ wò ìsàlẹ̀”. Òwe yi ṣe é lò lati ṣe àyẹ̀wò ìṣẹ̀lẹ̀ pí pa...
View ArticleÀwòrán ati pi pe Orúkọ Ẹranko ni Èdè Yorùbá Apá Kini àti Apá Keji...
Bi ó ti ẹ̀ jẹ́ pé a ti kọ nipa orúkọ àti àwòrán ẹranko ni àwọn ìwé ti a ti kọ sẹhin, ṣùgbọ́n Yorùbá ni “Ọgbọ́n ki i tán”, nitori eyi, a ṣe àtúnṣe gẹ́gẹ́ bi “Ọ̀jọ̀gbọ́n Èdè Yorùbá” ti...
View ArticleWi wé Gèlè Ìgbàlódé – How to tie Modern Head ScarfsOriginally Posted...
Originally posted 2015-07-07 19:41:40. Republished by Blog Post Promoter
View Article“Orin ẹ̀kọ́ lati bọ̀wọ̀ fún òbí ni ilé-ìwé alakọbẹrẹ”: Primary School...
Orin yi ni Olùkọ́ ma fi ńkọ́ àwọn ọmọ ilé-ìwé alakọbẹrẹ nigbà “ilé-ìwé ọ̀fẹ́” ti àwọn Òṣèlú ilẹ̀ Yorùbá ti Olóyè Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ ṣe olórí rẹ. Ni ayé ìgbà wọnyi, ọ̀pọ̀lọpọ̀ òbí...
View Article