Quantcast
Channel: The Yoruba Blog
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live

A bèrè fún àròkọ ni Èdè àti Àṣa Yorùbá fún Idije Àkọ́kọ́ – The...

A rọ ẹnikẹni ti ó ni ìfẹ́ èdè àti àṣà Yorùbá (pàtàki ọmọ ilé-iwé giga ti ó nkọ ẹ̀kọ́ èdè Yorùbá) ki ó kọ àròkọ fún “theyorubablog” lóri ayélujára.  Àròkọ ti èrò bá kà jù...

View Article


Wi wé Gèlè Aṣọ Òfì/Òkè – How to tie Yoruba Traditional Woven...

Aṣọ-Òfì tàbi Aṣọ-Òkè jẹ́ aṣọ ilẹ̀ Yorùbá.  Aṣọ òde ni, nitori kò ṣe gbé wọ lójojúmọ́.  Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Aṣọ-Òfì/Òkè wúwo, ṣùgbọ́n ti ìgbàlódé ti bẹ̀rẹ̀ si fúyẹ́ nitori òwú igbalode....

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Àjàpá àti Ọmọdé Mẹta – “Ẹnu àìmẹ́nu, ètè àìmétè, ló́ nmú ọ̀ràn bá ẹ̀rẹ̀kẹ́” –...

Ni abúlé Yorùbá nigbati ko ti si ẹ̀rọ asọ̀rọ̀-mágbèsì tabi ẹ̀rọ amú-òhùn-máwòrán àti ẹ̀rọ ayélujára, àwọn ọmọdé má nkó ara jọ lati ṣe eré lẹhin iṣẹ́ oojọ Bàbá àti Ìyá wọn.  Pataki, ni igba ọ̀gbẹlẹ̀...

View Article

Àjọ jẹ kò dùn bi Ẹni kan kò ri: Ìná dànù àwọn ọmọ Olówó Nigeria ni...

Lati ọjọ́ ti aláyé ti dá ayé ni Olówó tàbi Ọlọ́rọ̀ ti wà.  Ilẹ̀ Aláwọ̀dúdú kún fún ọrọ̀ oriṣiriṣi, ṣùgbọ́n, iwà àpà, ojúkòkòrò, ki kó ti ilé dà si ita, àti ìfẹ́ àjòjì ju ara...

View Article

Ẹ̀kọ́ àti Ọgbọ́n ni Ọ̀rọ̀ Àgbà lati Ẹnu Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọmọlolú Olunlọyọ lórí...

Bi a ba fi eti si ọ̀rọ̀ ti àgbà Yorùbá Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọmọlolú Olunlọyọ  ni ori ẹ̀rọ “Amóhùnmáwòrán Òpómúléró”, ni ori ayélujára, a o ṣe àkíyèsí àwọn nkan wọnyi:...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Iṣẹ́ ajé, sọ ọmọ nù bí òkò” –“Working for survival throws away the child...

Ọjọ́ ti pẹ́ ti Yorùbá ti ńkúrò ni ilú kan si ilú keji, yálà fún ọrọ̀ ajé tàbi fún ẹ̀kọ-kikọ́.   Ni ayé àtijọ́, ọjọ́ pípẹ́ ni wọn fi ńrin irin-àjò nitori irin ti ọkọ̀ òfúrufú lè...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ayẹyẹ ṣi ṣe ni Òkèrè – Àṣà ti ó mba Owó Ilú jẹ́”: “Destination...

Yorùbá fẹ́ràn ayẹyẹ ṣi ṣe púpọ̀ pàtàki fún igbéyàwó.  Ni ayé àtijọ́, ìnáwó igbéyàwó kò tó bi ó ti dà ni ayé òde òni.  Titi di bi ogoji ọdún sẹhin, ilé Bàbá Iyàwó tàbi...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Bi a bá tori ẹni burúkú fọ́jú, a kò ni ri ojú ri ẹni rere” – “If one...

Kò si ilú, ẹ̀yà tàbi àwọ̀ ti kò ni ẹni burúkú tàbi ẹni rere.  Àti ẹni burúkú àti ẹni rere ló wà ninú ẹbi, ilú, àti gbogbo ẹ̀yà àgbáyé ninú èniyàn dúdú àti funfun, ọkùnrin,...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ọ̀pọ̀ ni eṣú fi nya igi oko: Ìbò ni ipinlẹ Ọ̀ṣun” – “There is strength in...

Ninú Ẹ̀yà mẹrin-din-logoji orilẹ̀ èdè Nigeria, ẹ̀yà mẹ́fà ni o wa ni ipinlẹ Yorùbá lápapọ̀.  Àwọn ẹ̀yà wọnyi ni: Èkó – ti olú ilú rẹ jẹ Ìkẹjà; Èkiti – ti olú ilú rẹ jẹ Adó-Èkiti;...

View Article


“A kì í tó́ó báni gbé, ká má tòó ọ̀rọ̀-ọ́ báni sọ” – Ìdàpọ̀...

Ó pé ọgọrun ọdún ni ọjọ́ kini, oṣù kini ọdún Ẹgba-̃le-mẹrinla ti Ìjọba Ìlú-Ọba ti fi aṣẹ̀ da Àríwá àti Gũsu orílẹ̀ èdè ti a mọ̀ si Nigeria pọ.  Ìjọba Ìlú-Ọba kò bere lọwọ ará ilú ki...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ránti Ọmọ Ẹni ti Iwọ Nṣe: Olè ki ṣe Orúkọ Rere lati fi Jogún” –...

Oriṣiriṣi òwe ni Yorùbá ni lati fihàn pé iwà rere ló ni ayé.  Iwà ni Yorùbá kàsí ni ayé àtijọ́ ju owó ti gbogbo ilú bẹ̀rẹ̀ si bọ ni ayé òde òni.  Fún àpẹrẹ, Yorùbá ni “Ẹni bá...

View Article

Oriṣiriṣi Gèlè – Various types of Head TiesOriginally Posted on July 7,...

Aṣọ Yorùbá kò pé, lai si Gèlè.  Bi Yorùbá bá wọ aṣọ ìbílẹ̀ fún òde ojoojúmọ́ tàbi fún ayẹyẹ, wọn ni lati wé gèlè ki imúra lè pé.  Fún ji jade ojoojúmọ́, a lè lo ipèlé aṣọ...

View Article

Obinrin kò ṣe e jánípò si ìdí Àdìrò nikan, Obinrin ló ni gbogbo Ilé –...

Ìtàn fi yé wa wi pé Yorùbá ka ọ̀rọ̀ obinrin si ni àṣà Yorùbá  bi ó ti ẹ jẹ wi pé obinrin ki jẹ Ọba nitori ni àṣà ilú, ọkunrin ló njẹ olóri.  Obinrin kò pọ̀ ni ipò agbára.  Àwọn...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ọ̀run nyabọ̀, ki ṣé ọ̀rọ̀ ẹnìkan – Ayé Móoru” –“Heaven is collapsing, is...

Ọ̀run nyabọ̀ – Nature’s fury Ìbẹ̀rù tó gbòde ayé òde òni ni pé “Ayé Móoru”, nitori iṣẹ̀lẹ̀ ti o nṣẹlẹ̀ ni àgbáyé bi òjò àrọ̀ irọ̀ dá ni ilú kan, ilẹ̀-riru ni òmìràn, ọ̀gbẹlẹ̀,...

View Article

Welcome to the Yoruba Blog…Originally Posted on January 24, 2013, last...

The home of all things Yoruba… news, commentary, proverbs, food. Keeping the Yoruba culture alive. Originally posted 2013-01-24 21:03:41. Republished by Blog Post Promoter

View Article


Ohun ti mo fẹ́ràn nipa Ìsimi Iparí Ọ̀sẹ̀ – What I love about the Weekend...

Ni ọjọ́ Ẹti, ọjọ́ karun ti a ti bẹ̀rẹ̀ ilé-iwé ni ọ̀sẹ̀, inú mi ma ń dùn nitori ilé-iwé ti pari ni agogo kan ọ̀sán, ti ìsimi bẹ̀rẹ̀. Mo fẹ́ràn ìsimi ipari ọ̀sẹ̀ nitori mo ma nri àwọn òbí mi....

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Iwé-àkọ-ránṣẹ́ ni èdè Yorùbá – Letter writing in Yoruba...

Ni àtijọ́, àwọn ọmọ ilé-iwé ló ńran àgbàlagbà ti kò lọ ilé-iwé lọ́wọ́ lati kọ iwé, pataki ni èdè abínibí.  Ẹ ṣe àyẹ̀wò àwọn iwé-àkọ-ránṣẹ́ wọnyi ni ojú iwé yi: Ìwé ti Ìyá kọ...

View Article


ÀWÒRÁN ÀTI PÍPÈ ORÚKỌ ẸRANKO, APA KEJI – Names of Wild/Domestic...

Originally posted 2018-03-22 01:59:26. Republished by Blog Post Promoter

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ṣòkòtò àgbàwọ̀, bi kò ṣoni lẹsẹ á fúnni nítan”: “A borrowed trouser/pant, if...

Ìwà àti ìṣe ọ̀dọ́ ìgbàlódé, kò fi àṣà àti èdè Yorùbá hàn rárá. Aṣọ àlòkù ti gbòde, dipò aṣọ ìbílẹ̀.  Ọpọlọpọ aṣọ àgbàwọ̀ yi kò wà fún ara àti lilò ni ilẹ̀ aláwọ̀-dúdú.  Ọ̀dọ́ miran a wọ asọ àti bàtà...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ni Iránti Bàbá Ẹgbẹ́ Òṣèré Nigeria: Olóògbé Olóyè Hubert Adédèji...

Ẹbi, ará, iránṣẹ́ Ìjọba àti àwọn ọmọ Olóògbé Olóyè Hubert Adédèji Ogunde pé jọ ni ọjọ́ kẹrinlélógún oṣù kẹrin ọdún Ẹgbãlemẹ̃dógún, ni ilú Ìjẹ̀bú Ọ̀sọ̀sà ti ipinlẹ̀ Ògùn lati...

View Article
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live