Quantcast
Channel: The Yoruba Blog
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Èkó – Aginjù laarin àwọn Olú Ilú Àgbáyé”: “Lagos – A Jungle among...

Èkó ni olú ilú Nigeria fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún ki àwọn Ijọba Ológun tó kó Olú Ilú Nigeria lọ si Abuja ni bi ọdún mẹrinlélógún sẹhin.  Ki kó olú ilú kúrò ni Èkó kò din èrò ti o nwọ...

View Article


Ẹ̀kọ́-ìṣirò ni èdè Yorùbá – Simple Arithmetic in Yoruba...

Yorùbá ni bi wọn ti ma nṣe ìṣirò ki wọn tó bẹ̀rẹ̀ si ka ni èdè Gẹ̀ẹ́sì.  Akọ̀wé yi kọ ìṣirò ki ó tó bẹ̀rẹ̀ ilé-ìwé lọdọ ìyá rẹ̀ àgbà.  Nígbàtí ìyá-àgbà bá nṣe iṣẹ́ òwú “Sányán”...

View Article


Àwòrán àti pi pè orúkọ ẹ̀yà ara lati ori dé ọrùn – Pictures and...

Download: Parts of the body in Yoruba – head to neck You can also download the Parts of the body in Yoruba by right clicking this link: Parts of the body in Yoruba – head to neck (mp3) ORÍ DÉ ỌRÙN...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Òrìṣà òkè jẹ́ ki npé meji obinrin kò dé inú – Àṣà Ìkó-binrin-jọ:...

Ọkùnrin kan pẹ̀lú iyàwó púpọ̀ wọ́pọ̀ ni ilẹ̀ Yorùbá.  Àwọn obinrin ti ó bá́ fẹ́ ọkọ kan naa ni à ńpè ni “Orogún”.  Ìwà oriṣiriṣi ni ó ma ńhàn ni ilé olórogún, àrù̀n iyàwó ti...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

ÀWÒRÁN ÈLÒ ỌBẸ̀ YORÙBÁ – PHOTO GALLERY OF SOME YORUBA SOUP/STEW/SAUCE...

Originally posted 2013-05-03 23:19:39. Republished by Blog Post Promoter

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Yí Yára bi Ojú-ọjọ́ ti nyí padà nitori Èérí Àyíká – Effect of...

Ẹlẹkọ-ìjìnlẹ̀ ṣe àkiyesi pe enia ndá kún yí yára bi ojú-ọjọ́ ti nyi padà nitori èérí-àyíká.  Ojú-ọjọ́ ti nyí padà lati ìgbà ti aláyé ti dá ayé, ṣùgbọ́n àyípadà ojú-ọjọ́ ni ayé...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ẹ jáwọ́ lápọ̀n ti kò yọ̀, ẹ lọ dá omi ilá kaná” – “Restrain from...

Ọbẹ̀ àpọ̀n jẹ́ ọbẹ̀ yíyọ̀ bi ọbẹ̀ ilá, ṣùgbọ́n fún ẹni ti kò bá mọ̃ se, kò ni yọ̀.  Ọbẹ̀ ti enia lè yára sè ju ọbẹ̀ ilá ni, nitori bi a bá ni àpọ̀n kíkù nile, a din àkókò ti ó yẹ ki...

View Article

Bί a bá ránni ni iṣẹ ẹrú: One sent on a slavish errand (on man’s inhumanity...

The Mido Macia Story courtesy of NEWSY reporting from multiple sources and giving a broader view Yorὺbá nί “Bί a bá ránni nί iṣẹ ẹrú, a fi tọmọ jẹ”.  Ọlọpa tί o yẹ ki o dãbo bo ará àti ẹrú nί ìlú,...

View Article


Àwòrán ati Orúkọ àwọn Ẹiyẹ ni èdè Yorùbá – Pictures and names of...

      Originally posted 2014-10-17 13:00:55. Republished by Blog Post Promoter

View Article


“Ẹsẹ̀ yá ju mọ́tọ̀ (ọkọ̀) ara ló nfàbò sí” – ohun ìrìn-àjò ni èdè Yorùbá:...

Ni ayé àtijọ́ ẹsẹ̀ ni gbogbo èrò ma nlo lati rin lati ìlú kan si keji nigbati ọkọ̀ ìgbà̀lódé kò ti wọpọ.  Ilé Ọba àti Ìjòyè ni a ti le ri ẹṣin nitori ẹṣin kò lè rin ninu igbó kìjikìji ti o yi ilẹ̀...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Bi a bà jẹ̀kọ à dári ji Ewé”: À-lò-tún-lò – “After eating the corn...

Ewé iran – Organic food wrapping leaves. Courtesy: @theyorubablog Ki ariwo à-lò-tún-lò tó gbòde ni aiyé òde òni nipa àti dáàbò bo àyíká ni Yorùbá ti ńlo à-lò-tún-lò pàtàki li...

View Article

“Ẹni ti ó bá mọ inú rò, á mọ ọpẹ́ dá”: Whoever can think/reason will...

Ọmọ bibi ni ewu púpọ̀, nitori eyi ni Yorùbá fi ma nki “ìyá ọmọ kú ewu”.  Ni ọjọ́ ìsọmọ lórúkọ tàbi ìkómọ, Bàbá, Ìyá, ẹbi àti ọ̀rẹ́ òbí ọmọ tuntun á fi ìdùnnú hàn nipa ṣíṣe ọpẹ́...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Olóri Ẹbi, Baba Bùkátà” – “Headship of a Family is the Father of...

Olóri Ẹbi – Head of the Family connotes responsibiliies. Courtesy: @theyorubablog Olóri Ẹbi jẹ àkọ́bi ọkùnrin ni idilé.  Bi àkọ́bi bá kú, ọkùnrin ti ó bá tẹ̀le yio bọ si ipò.  Iṣẹ́ olóri...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“A kì í fi Oníjà sílẹ̀ ká gbájúmọ́ alápepe – Pí pa Àjòjì ni Gúsù...

Pí pa Àjòjì ni Gúsù ilẹ̀ Aláwọ̀-dúdú – South Africa’s xenophobic attacks Òwe Yorùbá kan sọ pé “Amúkun, ẹrù ẹ́ wọ́, ó ni ẹ̃ wò ìsàlẹ̀”.  Òwe yi ṣe é lò lati ṣe àyẹ̀wò ìṣẹ̀lẹ̀ pí pa...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Tori wèrè ìta la ṣe n ni wèrè inú ile”: Idibò lati yan Olóri Òṣèlú...

Ẹ̀rù ba onilé àti àlejò fún Nigeria nitori idibò à ti yan Olóri Òṣèlú à̀ti àwọn Òṣèlú yoku, ṣùgbọ́n a dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọrun pe ọjọ́ na ti wá, ó ti lọ, ilú ti yan Olóri Òṣèlú...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“A ki i jẹ Igún, a ki i fi Ìyẹ́ Igún rinti: Ẹnu Ayé Lẹbọ” –“It is...

Ohun ti o jẹ èèwọ̀ tàbi òfin ni ilú kan le ma jẹ èèwọ̀/òfin ni ilú miran ṣùgbọ́n bi èniyàn bá dé ilú, ó yẹ ki ó bọ̀wọ̀ fún àṣà àti òfin ilú.  Bi èniyàn bá ṣe nkan èèwọ̀, ó...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ọ̀run ńyabọ̀, ki ṣé ọ̀rọ̀ ẹnìkan”: “The sky is falling, is not a matter...

Ọ̀run ńyabọ̀ – the sky is falling. Courtesy: @theyroubablog Òwe Yorùbá yi ṣe gba àwọn ti o nbẹ̀rù nigba gbogbo níyànjú wípé ó yẹ ki èniyàn fara balẹ̀ lati ṣe iwadi ohun ti ó fẹ́ ṣẹlẹ̀ ki ó tó “kú sílẹ̀...

View Article


KÍKÀ NÍ YORÙBÁ: COUNTING IN YORUBA – NUMBERS 1 TO 20Originally Posted on...

KÍKÀ ỌJÀ NIPARI Ọ̀SẸ̀ – END OF WEEK STOCK TAKING: LEARNING NUMBERS 1 TO 20 Download: counting in Yoruba/a> You can also download the Yoruba alphabets by right clicking this link: counting 1 -20 in...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Àjùmòbí kò kan tãnu… Same parentage does not compel compassion…Originally...

Same parentage does not compel compassion. Òwe Yorùbá ní “Àjùmòbí kò kan tãnu, ẹni Olúwa  bá rán síni ló nṣeni lõre”.  Òwe yi wúlò lati gba àwọn ènìà tí o gbójúlé ẹbí níyànjú.  Ọ̀pọ̀lọpọ̀ rò wípé ẹ̀tọ́...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

ATỌ́NÀ LÉDÈ YORÙBÁ – Cardinal Directions in YorubaOriginally Posted on...

A compass showing the poles in Yoruba language. The image is courtesy of @theyorubablog   Originally posted 2013-04-16 19:01:07. Republished by Blog Post Promoter

View Article
Browsing all 9856 articles
Browse latest View live